Yoruba articles from Global Investigative Journalism Network

 

Field Guide to Security

tí wọ́n sì tún gbé ètò ìdáni lẹ́ẹ̀kọ́ kan kalẹ̀ lórí ohun èlò alágbè ká. Pẹ̀lú ìlànà lórí bí wọ́n ṣe fàràn tó jíire kalẹ̀, and ṣíṣe àtúntọ̀ rẹ̀ lórí …

Field Guide to Security Read More »

Iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ dátà

GIJN ti ṣe àkójọpọ̀ àti ètò àwọn ohun èròjà nípa lílo dátà fún ìròyìn tó jọ mọ́ iṣẹ́ ìwádìí.   À bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ojúlówó àwọn èròjà ìdánilẹ́kọ̀ọ́ kí a tóó kán …

Iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ dátà Read More »

Legal Defense and Emergency Aid

Aabo Ofin ati Iranlọwọ pajawiri Tani ó ń gbèjà ẹ̀tọ́ àwọn oníṣẹ́ ìròyìn? Tani ó le pèsè àtìlẹ́yìn tí pàjáwìrì bá ṣẹlẹ̀? Èyí ní àwọn ìtọ́sọ́nà sí àwọn ẹgbẹ́ tí …

Legal Defense and Emergency Aid Read More »

Àwọn Ìtalólobó àti Àwọn Ète: Ìdáṣe Lásìkò Àjàkálẹ̀-ààrùn COVID-19

Ìdáṣe gẹ́gẹ́ bí oníròyìn oníwàádìí jẹ́ ìpèníjà ní àkókò tó dára jù, ó sì tún ṣàfihàn àwọn ìṣòro nígbà àjàkálẹ̀-ààrùn kòrónà. Láti ṣísàkóso ewu ajẹmára sí pípàdánù iṣẹ́ láti ara …

Àwọn Ìtalólobó àti Àwọn Ète: Ìdáṣe Lásìkò Àjàkálẹ̀-ààrùn COVID-19 Read More »

Global Investigative Journalism Network

Membership in GIJN Ọmọ ẹgbẹ ninu Global Investigative Journalism Network wa ni sisi si awọn ti kii ṣe ere, awọn NGO, ati awọn ajọ eto ẹkọ, tabi deede wọn, ti …

Global Investigative Journalism Network Read More »

Ọmọ ẹgbẹ́ GIJN

GIJN jẹ ẹgbẹ ti awọn ẹgbẹ ti ko ni ere ti o ṣe atilẹyin iṣẹ akọọlẹ iwadii ni ayika agbaye. Lati ìgbà tí o ti bẹrẹ ni odun 2003, GIJN …

Ọmọ ẹgbẹ́ GIJN Read More »

GIJN Members

100Reporters, USA Dedicated si sisọ awọn apẹrẹ tuntun ni iṣẹ iroyin lódidi,  100 Reporters darapọ mọ awọn iyebiye ti awọn onirohin alamọdaju ti o dara julọ ti aye pẹlu awọn …

GIJN Members Read More »

Teaching and Training

Okan gboogi lara ojuse GIJN ni lati se akojopo atona fun iwadii to m’una d’oko lori Iroyin. Oniruuru awon ede ni e yoo ri, pelu eto eko ati ilaniloye l’oniranran. …

Teaching and Training Read More »

Ìdáṣe: Àwọn Ibi láti Ró-ohùn Àwọn Òye Ìtàn

Kò sí àwọn ìkànnì kan tí wọ́n ṣe fún àwọn oníròyìn ní pàtó láti ta àwọn òye ìtàn oníwàádìí, ṣùgbọ́n àwọn ìkànnì orí-ìtàkùn ayélujára díẹ̀ le fihàn pé wọ́n wúlò. …

Ìdáṣe: Àwọn Ibi láti Ró-ohùn Àwọn Òye Ìtàn Read More »

AsÌpín, Ìgbéga àti Àìfíkítà

Iṣẹ́ takuntakun tó wà nìdii iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ ìwádìí lè kọ́ ìpèníjà látàrí onírúurú akùdé. Ohun èlò yìí ṣe àgbékalẹ̀ onírúurú ìpèníjà tí àwọn àìfíkítà àti àwọn ilé …

AsÌpín, Ìgbéga àti Àìfíkítà Read More »

Ìjẹ́-aládàáni:  Ìkànnì tó rí owó àpawọlé fún àwọn Oǹkọ̀wé

Ìdàgbàsókè àwọn ìkànnì wà tí ó ran àwọn òǹkọ̀wé lọ́wọ́ láti pa owó nígbà tí wọ́n bá ń ṣe àtẹ̀jáde-ara-ẹni. Bóya eléyìí tọ́ fún ọ yóò nílò ìwádìí.  Ní abala …

Ìjẹ́-aládàáni:  Ìkànnì tó rí owó àpawọlé fún àwọn Oǹkọ̀wé Read More »

Ìbádòwòpọ̀-ọ̀rẹ́ àti Ìfọwọ́sowọ́pọ̀

Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ lórí iṣẹ́-àkànṣe aṣèwádìí jẹ́ gbajúgbajà síi lójojúmọ́. Ṣíṣeṣẹ́ pọ̀ pẹ̀lú alábàáṣiṣẹ́ le ṣe àfikún àti ìrànlọ́wọ́ jíjábọ̀ ohun èlò àti ìgbéga ọ̀nà oǹkàwé. Le gba àwọn Ìmọ̀ọ́ṣe tó yàtọ̀, …

Ìbádòwòpọ̀-ọ̀rẹ́ àti Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Read More »

Ìfọ́nká, Ìgbéga, àti Ìdáṣe

Iṣẹ́ ọwọ́ fún ṣíṣe iṣẹ́-ìròyìn aṣèwádìí le súni nípa onírúurú ìfikọ́ra. Ohun èlò yìí sọ só àìmọye ìpèníjà tí àwọn aládàáṣe kojú àti àwọn àjọ ilé-iṣẹ́ òròyìn tí ṣe àtẹ̀jáde …

Ìfọ́nká, Ìgbéga, àti Ìdáṣe Read More »

Iṣẹ́-Ìròyìn Oníwàádìí Aládàáni: Bí Wọ́n Ṣe Máa Ń Ró-Ohùn

Títa àwọn àbá Iṣẹ́-ìròyìn Oníwàádìí Aládàáni dàbí títa àwọn ìtàn mìíràn gidi gan, ṣùgbọ́n ó tún le jù ú lọ. Kò kàn sí ìgbéjáde ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbé-ìròyìn-jáde tó tó tó ń wù …

Iṣẹ́-Ìròyìn Oníwàádìí Aládàáni: Bí Wọ́n Ṣe Máa Ń Ró-Ohùn Read More »

AsÌpín, Ìgbéga àti Àìfíkítà

Iṣẹ́ takuntakun tó wà nìdii iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ ìwádìí lè kọ́ ìpèníjà látàrí onírúurú akùdé. Ohun èlò yìí ṣe àgbékalẹ̀ onírúurú ìpèníjà tí àwọn àìfíkítà àti àwọn ilé …

AsÌpín, Ìgbéga àti Àìfíkítà Read More »

Ìlọ́wọ́sí Olùwòran

Mímúlò ìtàkùn ayélujára tó níwọ̀n lò ní Yàrá-ìròyìn rẹ: Ewé-ìtalólobó lórí Ìfọ́ńká àti  lílọ́wọ́sí àwọn olùwòran Láti ọwọ́ Rossalyn Warren | March 18, 2021 Bí o bá ń ka èyí, …

Ìlọ́wọ́sí Olùwòran Read More »

Ìtàn iṣẹ́ akọ̀ròyìn tó jọ mọ́ dátà 

Láti ọwọ́ Brant Houston | Ogúnjọ́, Oṣù Ọ̀pẹ, ọdún 2021 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn akọ́ṣẹ́mọsẹ́ oníròyìn ní Wọ́n ṣe ìwádìí bí iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ dátà ṣe bẹ̀rẹ̀ ní ọdún 1952 …

Ìtàn iṣẹ́ akọ̀ròyìn tó jọ mọ́ dátà  Read More »

Bíbẹ̀rẹ̀ – Àwọn Àmọ̀ràn ní ìpele ìpele

Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú Tí o bá ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣé alábàápàdé ìròyìn tó jọ mọ́ dátà, àwọn ohun èlò wọ̀nyí wá lọ́fẹẹ̀ẹ́ fún lílo, tí yóò sì jẹ́ …

Bíbẹ̀rẹ̀ – Àwọn Àmọ̀ràn ní ìpele ìpele Read More »

Bí a ṣe lè dá Ikọ̀ tó ṣẹ̀dá iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ dátà

Láti ọwọ́ Fabiola Torres López | Ọjọ́ Kọkànlá, Oṣù Agẹmọ 11, Ọdún 2017 Ní ọdún márùn-ún sẹ́yìn, àwọn akọ̀ròyìn tó ń bojú wo ibi ì kò èròjà sí tàbí wá …

Bí a ṣe lè dá Ikọ̀ tó ṣẹ̀dá iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ dátà Read More »

Dátà fún iṣẹ́ ìròyìn: Àkójọpọ̀ GIJN

Ìwòye Dátà Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú Nígbà tí o bá ti ṣe àtúpalẹ̀ rẹ, o lè fẹ́ ya àwọn àwòrán, ìwé àwòrán àpẹẹrẹ ilẹ̀, tàbí máàpù láti …

Dátà fún iṣẹ́ ìròyìn: Àkójọpọ̀ GIJN Read More »

Lílo Ìkànnì R

Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú Ìkànnì R jẹ́ gbajúgbajà ohun èlò èdè tí wọ́n máa ń lò lọ́pọ̀ ìgbà fún àfọ̀mó dátà, ìṣirò àti wíwọ̀ye dátà. Ilẹkun Ìkànnì …

Lílo Ìkànnì R Read More »

Ìròyìn tó jọ mọ́ Dátà: Àkójọpọ̀ GIJN

Àwòrán Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú Tí o bá ní àkójọpọ̀ dátà tó níí ṣe pẹ̀ lú agbègbè, àwọn ohun èlò wọ̀nyí àti àwọn àtẹ àmọ̀ràn lè ṣe …

Ìròyìn tó jọ mọ́ Dátà: Àkójọpọ̀ GIJN Read More »

Dátà fún iṣẹ́ ìròyìn: Àkójọpọ̀ GIJN

Ìwòye Dátà Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú Türkçe Nígbà tí o bá ti ṣe àtúpalẹ̀ rẹ, o lè fẹ́ ya àwọn àwòrán, ìwé àwòrán àpẹẹrẹ ilẹ̀, tàbí máàpù …

Dátà fún iṣẹ́ ìròyìn: Àkójọpọ̀ GIJN Read More »

Àtúpalẹ̀ Dátà – Python

Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú Python jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ohun èlò èdè tó gbajúgbajà jùlọ fún àwọn oníròyìn tí iṣẹ́ wọn jọ mọ́ dátà, ó tún wúlò …

Àtúpalẹ̀ Dátà – Python Read More »

Àtúpalẹ̀ Dátà – SQL

Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú SQL jẹ́ ohun èlò tí wọ́n máa ń lò nígbà gbogbo nígbà tí wọ́n bá fẹ́ ṣiṣẹ́ pẹ̀ lú ibi tí aà ń …

Àtúpalẹ̀ Dátà – SQL Read More »

Àtúpalẹ̀ Dátà – Ìwé Atọ́nà

Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú Àwọn ìwé atọ́nà wọ̀nyí jẹ́ ohun èlò àkọ́kọ́ fún àwọn akọ̀ròyìn láti lò. Wọ́n kéré lọwọ, lọ́nà tó ní àgbékalẹ̀ bíi .csv files. …

Àtúpalẹ̀ Dátà – Ìwé Atọ́nà Read More »

Ohun èlò fún àfọ̀mọ́ àti àmúyẹ Dátà

Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú Ǹ JẸ́ o ní dátà tí kò ká ojú òṣùwọ̀n? Àwọn ohun èlò wọ̀nyí yóò wúlò fún ẹ láti ṣe àmúlò dátà rẹ …

Ohun èlò fún àfọ̀mọ́ àti àmúyẹ Dátà Read More »

Iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ dátà: Àkójọpọ̀ GIJN

Àkójọpọ̀ Dátà: Àmọ̀ràn ní Ṣókí Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú Tí o bá ní dátà tì ẹ, ó lè wọ àwọn ìwé Àmọ̀ràn ní ṣókí lọ́fẹẹ̀ẹ́ àti àwọn …

Iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ dátà: Àkójọpọ̀ GIJN Read More »

Iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ dátà: Àkójọpọ̀ GIJN

Fífá Dátà Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú Fífá dátà jẹ́ lílo ohun èlò tó jẹ́ kó rọrùn láti lo dátà lórí ẹ̀rọ ayélujára. Àwọn ohun tó wà ní …

Iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ dátà: Àkójọpọ̀ GIJN Read More »

Iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ Dátà Data Journali:Àkójọpọ̀ GIJN

Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ lórí iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ Dátà Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú Türkçe Ǹ jẹ́ ó fẹ́ kọ́ nípa ọgbọ́n àtinúdá lórí ìwé ìtẹ̀wé? Àwọn ètò ẹ̀kọ́ …

Iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ Dátà Data Journali:Àkójọpọ̀ GIJN Read More »

Iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ dátà: Àkójọpọ̀ GIJN

Bíbẹ̀rẹ̀ – Àwọn Àmọ̀ràn ní ìpele ìpele Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú Tí o bá ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣé alábàápàdé ìròyìn tó jọ mọ́ dátà, àwọn ohun èlò wọ̀nyí wá …

Iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ dátà: Àkójọpọ̀ GIJN Read More »

Iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ dátà

GIJN ti ṣe àkójọpọ̀ àti ètò àwọn ohun èròjà nípa lílo dátà fún ìròyìn tó jọ mọ́ iṣẹ́ ìwádìí.   À bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ojúlówó àwọn èròjà ìdánilẹ́kọ̀ọ́ kí a tóó kán …

Iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ dátà Read More »

Verification Handbook

Ìwé Ìléwọ́ Ìṣàmúdájú jẹ́ ìwé àmúlò fún àwọn oníròyìn àti àwọn tó ń ṣe ìrànwọ́ lásìkò pájáwì láti ilé iṣẹ́ Ìròyìn ilẹ̀ Yúróòpù, ìyẹn European Journalism Centre. Wọ́n ṣe àgbékalẹ̀ …

Verification Handbook Read More »

Iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ Dátà: Àkójọpọ̀ GIJN

Ìpàdé Àpérò lórí Iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ Dátà Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú Àwọn ìpàdé àpérò wọ̀nyí pèsè àǹfààní lóní yanturu láti mọ àwọn ènìyàn sii, láti …

Iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ Dátà: Àkójọpọ̀ GIJN Read More »

Ìgbìmọ̀ tó ń rí sí ètò ẹ̀kọ́ iṣẹ́ ìròyìn lágbàáyé: 

Àpèjúwe àti àwọn ètò ẹ̀kọ́ lórí iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn [Ní sísẹ n tẹ̀lé álífábẹ́ẹ̀tì orúkọ àwọn Fáṣítì gbogbo àti àwọn Ọ̀jọ̀gbọ́n].  Aligọ́rídìmù fún àwọn Oníròyìn  Àkànṣe iṣẹ́ sílábọ́ọ̀sì tí …

Ìgbìmọ̀ tó ń rí sí ètò ẹ̀kọ́ iṣẹ́ ìròyìn lágbàáyé:  Read More »

Teaching and Training

Ìkọ́ni àti ìdanilẹ́kọ̀ọ́ Ọ̀kan gbòógì lára ojúṣe GIJN ni láti se àkójọ pọ̀ atọ́nà fún ìwádìí tó múná dóko lórí ìròyìn yín.  Onírúurú àwọn èdè ni ẹ yí ò rí …

Teaching and Training Read More »

ÌRÒYÌN 

Ilé Ẹ̀kọ́ Fáṣítì Illinois níbi tí wọ́n ti ń fi Ẹ̀dùn Ọkàn hàn Nípa Àjàkálẹ̀ Àrùn COVID-19 àti bí wọ́n ṣe ń ń polongo bí àwọn ènìyàn ṣe ń lòdì …

ÌRÒYÌN  Read More »

ILÉ IṢẸ́ FRANK

Ilé Ẹ̀kọ́ Fáṣítì Illinois ń ṣe Ìgbanisíṣẹ́ sí Ipò Ọ̀gá Àgbà èyí tí yóò jẹ́ Alárinà Láàárín àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ fún Ìmọ̀ Ìròyìn àti Àwọn Akọ́ṣẹ́mọsẹ́  Láti ọwọ́ Jelter Meers | …

ILÉ IṢẸ́ FRANK Read More »

YÀRÁ ÌRÒYÌN ÀWỌN AKẸ́KỌ̀Ọ́ 

Wọ́n ti Gbóríyìn fún Ẹ̀ka Iṣẹ́ Ìwádìí lórí Ìròyìn tuntun, ti ilé ẹ̀kọ́ Fáṣítì Toronto lásìkò Àjàkálẹ̀ Àrùn  Láti ọwọ́ Jelter Meers |  Ọjọ́ Kẹẹ̀dógún, Oṣù Belú, Ọdún 2020  Láti …

YÀRÁ ÌRÒYÌN ÀWỌN AKẸ́KỌ̀Ọ́  Read More »

Iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ dátà: Àkójọpọ̀ láti ọwọ́ GIJN 

Bíbẹ̀rẹ̀ lórí ìwé  Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú  Русский | Türkçe Iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ dátà máa ń ní àkọ̀rí. Ojú ewé GIJN máa ń ní àwọn …

Iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ dátà: Àkójọpọ̀ láti ọwọ́ GIJN  Read More »

The Global Investigative Journalism

Ìpàdé Àpérò Àgbáyé lórí iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn yóò wà lórí ẹ̀rọ ayélujára ní oṣù kọkànlá, ọdún 2021; Òmíràn yóò wáyé ní ìlú Sydney lọ́dún 2022. Láti Ìkànnì GIJN | …

The Global Investigative Journalism Read More »

The Field Guide to Security Training

Ìtọ́ni sọ́nà lórí ìdánilẹ́kọ̀ọ́ lórí ètò ààbò jẹ́ kọ̀ríkúlọ́ọ́ọ̀mù tí Open News fi lọ́ọ́lẹ̀, àwọn ìgbìmò tó ń ṣe ìrànwọ́ fún àwọn olùgbé jáde, àwọn ọlọ́gbọ́n orí, ó àwọn onímọ̀ …

The Field Guide to Security Training Read More »

ỌPẸ́ PÀTÀKÌ LỌ́WỌ́ ÀWỌN TÓ Ń ṢE ONIÍGBỌ̀WỌ́ 

ROBERT R.  MCCORMICK FOUNDATION  Ẹ fẹ́ràn wá lórí Facebook  Ẹ tẹ̀lé wá lórí twitter  Ṣe alábàápín ní ìkànnì RSS ÀJỌ IJEC ṢE ÀGBÀ TẸRÙ IṢẸ́ TÍ Ẹ̀KA YÌÍ Ń ṢE …

ỌPẸ́ PÀTÀKÌ LỌ́WỌ́ ÀWỌN TÓ Ń ṢE ONIÍGBỌ̀WỌ́  Read More »

Ìwé atọ́nà fún ààbò SEEMO

Ìwé atọ́nà fún ààbò SEEMO: Ìwé atọ́ni sónà fún àwọn oníròyìn tí Wọ́n ń ṣe àkànṣe iṣẹ́ tàbí lórí ìṣẹ̀lẹ̀ pájáwì: Ìwé ìléwọ́ yìí jáde láti ilé iṣẹ́ Ìròyìn Gúúsù …

Ìwé atọ́nà fún ààbò SEEMO Read More »

ÌRÒYÌN TUNTUN 

Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ tó jẹ́ ti ilẹ̀ Òkèèrè, tí wọ́n ń dé padà láti Àwọn Orílẹ̀ Èdè tí Àjàkálẹ̀ Àrùn kò fi bẹ́ẹ̀ bá fínra gbé Òṣùwọ̀n COVID-19 ju ti Amẹ́ríkà …

ÌRÒYÌN TUNTUN  Read More »

Reporting Indigenous

Ìròyìn yìí sọ ojú abẹ níkòó, láti ọwọ́ Mark Lee Hunter àti Luuk Sengers, [Ó wà fún títà ní ilé iṣẹ́ tó ń rí sí iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn]. Àfihàn …

Reporting Indigenous Read More »

Ìdáṣe: Ìfúnnilówó Iṣẹ́-àkànṣe Oníwàádìí Tìrẹ

Ìfúnnilówó Owó-ìrànwọ́ fún àwọn iṣẹ́-àkànṣe ìjábọ̀ wà láti onírúurú orísun. Àwọn Olùfúnnilówó kan gba gbogbo irúfẹ́ àbá wọlé, nígbà tí àwọn mìíràn wá láti ṣe ìrànwọ́ fún àwọn àkórí kan …

Ìdáṣe: Ìfúnnilówó Iṣẹ́-àkànṣe Oníwàádìí Tìrẹ Read More »

ÀRÙN KÒRÓRÀ

Àwọn tó Lùgbàdì Àrùn Kòrónà tí kò Fara Hàn  By Ilé iṣẹ́ tó ń rí sí iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn ti Howard | Ọgbọ́n Ọjọ́, Oṣù Ọ̀pẹ, Ọdún 2020 Àwọn …

ÀRÙN KÒRÓRÀ Read More »

Ìtọ́ni sọ́nà fún Ìwádìí Ìjìnlẹ̀ Lórí Ìròyìn

Ǹ jẹ́ ẹ́ ń wá àmọ̀ràn ní ṣókí, àwọn ohun èlò tàbí ìtọ́ni sónà? Yẹ ìsàlẹ̀ wò fún àwọn ìtọ́sọ́nà tó ní í se pẹ̀lú ìwádìí ìjìnlẹ̀ lórí Ìròyìn pẹ̀lú …

Ìtọ́ni sọ́nà fún Ìwádìí Ìjìnlẹ̀ Lórí Ìròyìn Read More »

Manual for Arab journalists

Ìwé ìléwọ́ fún àwọn oníròyìn ilẹ̀ Lárúbáwá nípa òmìnira à ti kó ìròyìn jọ pẹ̀lú iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn: e yóò rí ìwé olójú ewé mọ́kànlélógún ọ̀hún gbà lọ́fẹẹ̀ẹ́ lórí …

Manual for Arab journalists Read More »

ÀWỌN ÀRÒKỌ

DÍDẸ́RỌ́ ÀJÀKÁLẸ̀ ÀRÙN FI ÀÀYÈ SÍLẸ̀ LÁTI WÁ ÌYÀNJÚ SÍ ÀÌṢE DÉÉDÉÉ LÓRÍ LÍLO DÁTÀ Ọjọ́ Kọkàndínlógún, Oṣù Èbíbí, Ọdún 2021  Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ṣe àǹfààní ń lá gbáà fún …

ÀWỌN ÀRÒKỌ Read More »

Ìgbé dìde Ọ̀run Àpáàdì: Atọ́nà fún àwọn ará ìlú lórí iṣẹ́ ìwádìí tó jíire

(PDF): Ilé iṣẹ́ tó ń rí sí sí iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn, àkọ́kọ́ irú rẹ̀ ní àgbáyé tí won kò fi dá oko òwò, èyí tó ń rí sí “iṣẹ́ …

Ìgbé dìde Ọ̀run Àpáàdì: Atọ́nà fún àwọn ará ìlú lórí iṣẹ́ ìwádìí tó jíire Read More »

Investigative Reporting- À toolkit for Reporters

Iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn: Ohun èlò fún àwọn oníròyìn: ìwé atọ́ni sónà olójú ewé ọgọ́rùn-ún ó lé méje èyí tí ilé iṣẹ́ Amẹ́ríkà tó ń rí sí oko òwò aládàńi …

Investigative Reporting- À toolkit for Reporters Read More »

Iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn 

Ohun èlò fún àwọn oníròyìn: ìwé atọ́ni sónà olójú ewé ọgọ́rùn-ún ó lé méje èyí tí ilé iṣẹ́ Amẹ́ríkà tó ń rí sí oko òwò aládàńi gbé jáde lọ́dún 2009 …

Iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn  Read More »

Òmìnira oníròyìn

GIJN dẹ́ku ìjálé láti ọ̀dọ̀ Aṣojú Russian lórí ilé olóòtú IStories Roman Anin.   Láti ọ̀dọ̀ òṣìṣẹ́ GIJN | ọjọ́ kẹsàn-án oṣù kẹrin, ọdún 2021 Òṣìṣẹ́ IStories, dídá sí àwọn oníròyìn …

Òmìnira oníròyìn Read More »

Empowering Independent Media

Ríró àwọn ilé iṣẹ́ ìròyìn aládàńi ní agbára: Ìlàkàkà ilẹ̀ Amẹ́ríkà láti fún àwọn ilé iṣẹ́ ìròyìn ní ààyè láti ṣíṣe láì ní ìdíwọ́ àti ẹ̀rọ ayélujára jákèjádò orílẹ̀ èdè …

Empowering Independent Media Read More »

A Taste for Trouble

“Fífi ọwọ́ fà wàhálà láti”  ọwọ́ Aniruddha. Ní ogún ọdún sẹ́yìn, Bahal dá ẹ̀fúùfù àgbáyé èyí tó ń ṣe ìwádìí lórí à ì ṣe déédéé tó ń wáyé láàárín àwọn …

A Taste for Trouble Read More »

Ipa Alápèjúwe

Ipa Alápèjúwe oníwàádìí: ohun-kíkà pàtàkì. Iṣẹ́-ìròyìn oníwàádìí ń tan ìmọ́lẹ̀ nínú àwọn kọ̀rọ̀ tó ṣókùnkùn èyí tó jẹ mọ́ ènìyàn, àjọ ìhùwàsí ìjọba àti ìgbésẹ̀, àtúnṣe kíákíá, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ …

Ipa Alápèjúwe Read More »

Ìmúwàláàyè

Fún ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbé-ìròyìn-jáde àti àwọn ilé-iṣẹ́ mìíràn tí kì í ṣe fún èrè-owó, wíwá ọgbọ́n-àtinúdá fún ètò-ìsúná fún ìmúwàláàyè, èyí tíí ṣe kọ́kọ́rọ́ fún jíjábọ̀ ju ọdún kan tàbí méjì lọ. …

Ìmúwàláàyè Read More »

GIJN Nílẹ̀ Adúláwọ̀: Àǹfààní sí Àkọsílẹ̀ Gbogbogbò

Láàrín àwọn ogunlọ́gọ̀ orílẹ̀-èdè tó bọ́ sí gúúsù aṣálẹ̀ nílẹ̀-adúláwọ̀, àǹfààní sí àkọsílẹ̀ gbogbogbò kìí ṣe ohun tó rọrùn rárá títí dòní, bí-ó-tilẹ̀ jẹ́ pé kò sí àwọn òfin tó …

GIJN Nílẹ̀ Adúláwọ̀: Àǹfààní sí Àkọsílẹ̀ Gbogbogbò Read More »

Ìkówójọ-Orí-Ìtàkùn-Ayélujára

Ohun Kíkà Pàtàkì Iṣẹ́-ìwádìí “GIJN” ṣàgbékalẹ̀ àwọn ìtalólobó lórí ọ̀nà tí a lè gbà gbé ìpolongo ìkówójọ orí-ìtàkùn-ayélujára, àwọn orúkọ orílẹ̀-èdè àti ẹkùnjẹkùn tó jẹ mọ́ ìkànnì ìkówójọ orí-ìtàkùn-ayélujára, àbá …

Ìkówójọ-Orí-Ìtàkùn-Ayélujára Read More »

Ìdásí Àwùjọ àti Ọ̀nà-Tówó-ń-gbà-wọlé.

Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀-Abójú-ayé-mu Ohun-èèlò ọmọ-ẹgbẹ́ 101: Ṣégeṣège Ìtúpalẹ̀ rẹ, kí o sì gùnlé ìrólágbára-ètò àkójọpọ̀-fáyẹ̀wò fún ìjọ́mọ-ẹgbẹ́ Agbára ìgbóhuntuntunjáde nínú iṣẹ́-ìròyìn ọlọ́gbọnrangandan lórí ìtàkùn-àgbáyé: Àwọn àpẹẹrẹ márùn-ún tó peregedé. Iṣẹ́-ìwádìí àwùjọ …

Ìdásí Àwùjọ àti Ọ̀nà-Tówó-ń-gbà-wọlé. Read More »

Ìdáṣe:Àdéhùn àti Ìdúnàádúràá

Àwọn Èrò Oní-àdéhùn Ìdúnàádúràá Àdéhùn fún Átíkù Oníwàádìí gbọ́dọ̀ bo onírúurú ìṣòro tí kò fi bẹ́ẹ̀ yẹ fún, sọ pé àbùdá nípa ọmọ ọlọ́ńgbò tó rẹwà. Àwọn kókó kan tó …

Ìdáṣe:Àdéhùn àti Ìdúnàádúràá Read More »

Better News

Ìròyìn tó dára jù lọ Èyí jẹ́ Ẹ̀rọ ayélujára tó ní onírúurú ohun èlò èyí tí ilé iṣẹ́ ìtẹ̀wé ilẹ̀ Amẹ́ríkà ṣe àgbékalẹ̀ rẹ̀.  Ìgbìmọ̀ amúṣẹ́yá AEJMC láti dí àlàfo …

Better News Read More »

Àwọn Aṣáájú ṣàgbéjáde sítáì

Àwọn Aṣáájú ṣàgbéjáde sítáì “Pimp My Ride” àjọ alátùn-ún-ṣe fún ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbé-ìròyìn-jáde. Àwọn Agbóhuntuntunjáde Tíkò-lẹ́gbẹ́ A dàbí àwọn ènìyàn-àwùjọ. “AJ+” ń ṣe àtúnṣe sí yàrá-ìròyìn rẹ̀ láti bá àìní àwọn ọ̀dọ́ …

Àwọn Aṣáájú ṣàgbéjáde sítáì Read More »

Àlàyé lórí Ìpolówó-ọjà Ìmọ̀-ẹ̀rọ “Tow Center”

Àwọn oníròyìn náà ń kíyèsí ìpolówó ìmọ̀-ẹ̀rọ. Àwọn náà sinmi lé e. “CJR” Kín ni ohun tuntun nínú títẹ àádọ́ta àbájáde fún owó iṣẹ́-ìròyìn: àlàyé tó lọ sàn-án (apá kejì). …

Àlàyé lórí Ìpolówó-ọjà Ìmọ̀-ẹ̀rọ “Tow Center” Read More »

Ìṣedáṣe: Ààbò àti Àìléwu

Àwọn oníròyìn Àdáṣe máa ń sábà wà láàyè ara wọn nígbà tí ó bá di ọ̀rọ̀ ààbò, lójú aye àti ìmọ̀ ẹ̀rọ ayélujára, ṣùgbọ́n ọ̀pọ̀ ohun-èèlò aṣèrànwọ́ ló wà. Ìrànlọ́wọ́ …

Ìṣedáṣe: Ààbò àti Àìléwu Read More »

Reporting in Indigenous Communities

Ìròyìn ní èdè agbègbè jẹ́ èyí tí akọ̀ròyìn pẹ̀lú ilé iṣẹ́ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ ìlú Canada, Duncan McCue gbé jáde lọ́dún 2011. Ó ń àwọn èròjà láti kọ ìròyìn lédè abínibí jákèjádò …

Reporting in Indigenous Communities Read More »

ÀÌDÁṢE: Fi Ìsedúró Wéwu

Níní ìṣedúró nígbà tí o wà lórí àwọn iṣẹ́ àyànṣe eléwu le jẹ́ ìkówólé tó mú ọpọlọ dáni àti èyí tí kò wọ́n tó bí o ṣe bẹ̀rù. Rí àwọn …

ÀÌDÁṢE: Fi Ìsedúró Wéwu Read More »

Ìṣèdáṣe: Àwọ̀n Ìkànnì tí ó máa ń mówó wọlé fún àwọn òǹkọ̀wé 

Onírúurú ìkànnì tí ìdàgbàsókè ti débá ló wà tí ó ń ran àwọn òǹkọ̀wé lọ́wọ́la ti owó nípaṣè ìgbéjáde-ara-ẹni. Yàlá àwọn wọ̀nyí tọ̀nà fún ọ èyí yóò gbà ìwádìí. Ní …

Ìṣèdáṣe: Àwọ̀n Ìkànnì tí ó máa ń mówó wọlé fún àwọn òǹkọ̀wé  Read More »

Àwo̩n Ohun-Èlò àti Ìlànà

Àwo̩n O̩gbó̩n láti s̩e àgbàpamó̩ àwo̩n Àté̩jís̩é̩ orí Telegram lórí Ogun Russia àti Ukraine Láti o̩wó̩ Bellingcat Tech Team | March 15, 2022 Pè̩lú ìtàkùn Facebook àti Twitter tí ó ti jé̩ dídínà-mó̩, …

Àwo̩n Ohun-Èlò àti Ìlànà Read More »

Àwo̩n Ilé-Is̩é̩ Oníròyìn Ò̩te̩lè̩múyé̩  

Èyí ni àwo̩n ilé-is̩é̩ aláìgbojúlé-èrè tí a bá tan káàkiri àgbáyé tí wo̩n ń s̩e is̩é̩ láti ran ìròyìn ò̩te̩lè̩múyé̩ ló̩wó̩, láti agbègbè sí agbègbè. Ó jé̩ àkójo̩pò̩ tí ó …

Àwo̩n Ilé-Is̩é̩ Oníròyìn Ò̩te̩lè̩múyé̩   Read More »

Àwo̩n Àko̩sílè̩ Is̩é̩-Ìròyìn Ò̩te̩lè̩múyé̩

Ǹjé̩ e̩ ń wà ète, ohun-èlò, àti ìdánilé̩kò̩ó̩? Ató̩nà ìsàlè̩ yìí dá lé is̩é̩-ìròyìn ò̩te̩lè̩múyé̩ tí ó sì s̩e àgbékalè̩ àwo̩n àpe̩e̩re̩ àti àfihàn káàkiri àgbáyé. Ò̩pò̩ wà ní ò̩fé̩, …

Àwo̩n Àko̩sílè̩ Is̩é̩-Ìròyìn Ò̩te̩lè̩múyé̩ Read More »

Àpótí-ìwé GIJN: Àìmo̩ye ìwé fún Muckrakers ní 2021

Láti o̩wó̩ Laura Dixon | April 5, 2021 Ní GIJN, a s̩e oríire láti s̩e alábàápàdé àwo̩n orís̩irís̩i ìwé àti ìròyìn lórí ipò is̩é̩-ìgbóhùnsáfé̩fé̩ aje̩mó̩ròyìn àti ìròyìn ò̩te̩lè̩múyé̩ tí ó mó̩yán lórí. Èyí …

Àpótí-ìwé GIJN: Àìmo̩ye ìwé fún Muckrakers ní 2021 Read More »

Ìwò lórí àwo̩ Ìlànà Ìs̩èwádìí

Ìmò̩ràn lóri kókó ìs̩èwádìí máa ń wáyé ní orís̩irís̩I ò̩nà – kìí s̩e fún onís̩é̩-ìròyìn o̩ló̩fintótó nìkan, s̩ùgbó̩n fún o̩ló̩pàá, agbanisís̩é̩, agbe̩jó̩rò, onís̩é̩ ìlú, àti àwo̩n yòókù. Nǹkan tó fojú …

Ìwò lórí àwo̩ Ìlànà Ìs̩èwádìí Read More »

Àwo̩n Ò̩nà Mé̩rin tí a fi lè tètè s̩e ìfìdíòdodo-múlè̩ àwòrán lórí è̩ro̩ ìbánisò̩rò̩

Láti o̩wó̩ Raymond Joseph | O̩jó̩ Ke̩rìnlélógún, Os̩ù Ògún, 2021 This photograph of a weasel clinging to the back of a flying woodpecker went viral on social media. While it had all the …

Àwo̩n Ò̩nà Mé̩rin tí a fi lè tètè s̩e ìfìdíòdodo-múlè̩ àwòrán lórí è̩ro̩ ìbánisò̩rò̩ Read More »

Àwo̩n Ò̩nà Mé̩rin tí a fi lè tètè s̩e ìfìdíòdodo-múlè̩ àwòrán lórí è̩ro̩ ìbánisò̩rò̩

Láti o̩wó̩ Raymond Joseph | O̩jó̩ Ke̩rìnlélógún, Os̩ù Ògún, 2021 GIJN ti s̩e àfikún ató̩nà oní-sísè̩-n-tè̩lé wa lórí níní àrídájú lórí àwo̩n àwòrán láti mò̩ bóyá àwòràn tí e̩ ń rí lórí ayélujára jé̩ …

Àwo̩n Ò̩nà Mé̩rin tí a fi lè tètè s̩e ìfìdíòdodo-múlè̩ àwòrán lórí è̩ro̩ ìbánisò̩rò̩ Read More »

Ìpínká, Ìgbéláruge̩ , àti ìdás̩é̩-s̩e

Is̩é̩ tí ó gbo̩ngbó̩ nípa sís̩e is̩é̩ ìròyìn o̩ló̩fintótó lè sú ènìyàn látàrí orís̩irís̩i àgbéyè̩wò ajé̩mó̩-ìs̩èlú. Ohun èlò yìí mójú tó díè̩ nínú àwo̩n àdojúko̩ tí àwo̩n adás̩é̩s̩e àti àwo̩n …

Ìpínká, Ìgbéláruge̩ , àti ìdás̩é̩-s̩e Read More »

Ohun èlò: Ató̩nà láti rí orísun tí ó dáńtó̩Guides to Finding Expert Sources

Láti o̩wó̩ Kira Zalan | May 23, 2016 Ǹjé̩ e̩ ń wá àwo̩n orísun? Rírí onímò̩ ní apá ibì kan jé̩ ibi tí ó dára láti bè̩rè̩ fún ò̩pò̩ ìtàn. GIJN s̩e àyè̩wò …

Ohun èlò: Ató̩nà láti rí orísun tí ó dáńtó̩Guides to Finding Expert Sources Read More »

Fífí-ìdí-òdodo-múlè̩ & Àrídájú

Guide to Fact-Checking Investigative Stories  ti GIJN láti o̩wó̩ Nils Hanson (2021) Four Quick Ways to Verify Images on a Smartphone ti GIJN láti o̩wó̩ Raymond Joseph. (2021) Making Stories Ironclad …

Fífí-ìdí-òdodo-múlè̩ & Àrídájú Read More »

Àwo̩n Ohun-Èlò Gbòógì fún Ìbò US: Ató̩nà Orí-Ìrìn fún Àwo̩n Ónís̩é̩-Ìròyìn ní Iwájú

Kò buŕkú jù láti so̩ pé orílè̩-èdè Amé̩ríkà kò tí rí irú ìbò bí èyí rí. Ní o̩jó̩ ke̩ta, os̩ù Bélú, àwo̩n o̩mo̩ orílè̩-èdè Amé̩ríkà yóò dìbò yan ààre̩, àwo̩n …

Àwo̩n Ohun-Èlò Gbòógì fún Ìbò US: Ató̩nà Orí-Ìrìn fún Àwo̩n Ónís̩é̩-Ìròyìn ní Iwájú Read More »

Ìs̩àtúnko̩ àti ìs̩àkóso

Crafting Investigative Reportage Into Dramatic Narratives,  láti o̩wó̩ Vinod K Jose, Olùs̩àtúnko̩ àgbà fún The Caravan, Ìwé ìròyìn àkó̩kó̩ fún is̩é̩ ìròyìn aláròyé àti o̩ló̩fintótó ní ilè̩ India. Àgbékalè̩ GIJC19  …

Ìs̩àtúnko̩ àti ìs̩àkóso Read More »

Is̩é̩-ìròyìn tí ó je̩ mó̩ ìlò dúróònù

Turbulent with a chance of data: Journalism’s drone-powered futures: A guide to storytelling with UAVs, láti o̩wó̩ Monica Sengul-Jones nínú datajournalism.com Tips on Drone Journalism, láti o̩wó̩ Raffy Tima tí …

Is̩é̩-ìròyìn tí ó je̩ mó̩ ìlò dúróònù Read More »

Iṣẹ́-ìròyìn Àdáṣe: Ìṣedúró Ìgbáralé ènìyàn àti ìjọba fún ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròròyìn-jáde

Iṣẹ́-ìròyìn Àdáṣe: Ìṣedúró Ìgbáralé ènìyàn àti ìjọba fún ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròròyìn-jáde Àwọn oníròyìn Oníwàádìí Àdáṣe gbọdọ̀ ro mímú iṣedúró síta dáadáa láti dá ààbò bo ara wọn kúrò ni ewu fífi ẹ̀sùn …

Iṣẹ́-ìròyìn Àdáṣe: Ìṣedúró Ìgbáralé ènìyàn àti ìjọba fún ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròròyìn-jáde Read More »

Ìtalólobó àgbà-ọ̀jẹ̀ fún wíwú gbòǹgbò ìròyìn-èké

Ìtalólobó àgbà-ọ̀jẹ̀ fún wíwú gbòǹgbò ìròyìn-èké Láti ọwọ́ Maurice Oniang’o | ọjọ́ kẹtà-lé-lógún oṣù kọkànlá, ọdún 2021 Fún àwọn oníròyìn aṣèwádìí tí wọ́n ń wú ìpòlongo tí ìròyìn tí kò …

Ìtalólobó àgbà-ọ̀jẹ̀ fún wíwú gbòǹgbò ìròyìn-èké Read More »

Kín ni Iṣẹ́-ìròyìn Aṣèwádìí?

Kín ni Iṣẹ́-ìròyìn Aṣèwádìí?   Fún wíwo ohun tí ó ǹ lọ lọ́wọ́, wo Ọjọ́-iwájú Iṣẹ́-ìròyìn Aṣèwádìí pẹ̀lú. Nígbà tí oríkì ìjábọ̀ ìròyìn aṣèwádìí máa ń yàtọ̀, láàárín àwọn ẹgbẹ́ alámọ̀dájú …

Kín ni Iṣẹ́-ìròyìn Aṣèwádìí? Read More »

IṢẸ́-ÌRÒYÌN DÉÉTÀ

Àwọn Ìtalólobó fún Kíkọ́ ìròyìn-jọ-kọ̀ḿpútà  fún Ìwádìí Láti ọwọ́ Miriam Forero Ariza | ọjọ́ kẹtàlá oṣù keje, ọdún 2021 Ní tòròtòrò ọdún yìí, gẹ́gẹ́ bí orílẹ̀-èdè ti Colombia tí ìwọ́de …

IṢẸ́-ÌRÒYÌN DÉÉTÀ Read More »

Àwọn Èlò Okòwò fún Yàrá-ìròyìn: Ìtọ́nisọ́nà GIJN

 Ìtọ́nisọ́nà yìí ni wọn ṣe ìdúpẹ́ láti ran àwọn Google News Initiative lọ́wọ́. Talya Cooper ni ó ṣe ìwádìí àti ló kọ ọ́, olùwádìí tí ó tẹ̀dó sí New York …

Àwọn Èlò Okòwò fún Yàrá-ìròyìn: Ìtọ́nisọ́nà GIJN Read More »

Afghanistan: Bí wọ́n ṣe lè ran àwọn oníròyìn lọ́wọ́ àti àwọn yòókù tó wà nínú Ewu.

Láti ọwọ́ Smaranda Tolosano | Ọjọ́ kejì-dín-lógún oṣù kẹjọ, ọdún 2021 Ìmúdójú-ìwọ̀n tó kẹ̀yìn: Ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù kẹjọ Ní akitiyan láti ran àwọn oníròyìn àti àwọn yòókù tó ń gbìyànjú …

Afghanistan: Bí wọ́n ṣe lè ran àwọn oníròyìn lọ́wọ́ àti àwọn yòókù tó wà nínú Ewu. Read More »

Àwọn Ìtalólobó Ìjábọ̀ Ìròyìn àti Àwọn Èlò

Ń wá àwọn ohun èlò láti 2021 Global Investigative Journalism Conference? O ti wá sí ibi tó tọ́. Tẹ ibí yìí. O ó rí tó ojú-ewé igba, àwọn ìgbékalẹ̀, àwọn …

Àwọn Ìtalólobó Ìjábọ̀ Ìròyìn àti Àwọn Èlò Read More »

Journalist Survival Guide

Ni èyí tí àjọ Samir Kassir tó kalẹ̀ sí ìlú Beruit ṣe àgbékalẹ̀ rẹ̀, atọ́nà lórí àwọn abẹ̀mí ni wọ́n gbé kalẹ̀ láti ṣe ìrànwọ́ fún àwọn akọ̀ròyìn àti àwọn …

Journalist Survival Guide Read More »

IṢẸ́ ÌWÁDÌÍ 

Ìwé Àkọsílẹ̀ Iṣẹ́ Ìwádìí ń pèpè fún iṣẹ́ ìwádìí tó dá lé àkójọpọ̀ dátà fún COVID-19  Ìwé Àkọsílẹ̀ lórí iṣẹ́ ìwádìí fún àkójọpọ̀ dátà lórí COVID-19 kan  tí kéde àwọn …

IṢẸ́ ÌWÁDÌÍ  Read More »

Ìdàpọ̀ Alápapọ̀

Owó-ìrànwọ́ àti Ìdàpọ̀-ọ̀rẹ́ fún àwọn oníròyìn Owó-ìrànwọ́ tó níṣe pẹ̀lú COVID-19 Ò ń wá ààyè láti ṣe àtúnṣe sí ìmọ̀ọ́ṣe rẹ àti láti fẹ ayé rẹ lójú? Iṣẹ́ ojoojúmọ́ ti …

Ìdàpọ̀ Alápapọ̀ Read More »

Àwọn Orísun ti ilé-iṣẹ́ Ìròyìn lórí Ìfowósílẹ̀ lórí Àjàkálẹ̀ Ààrùn Tókárí-ayé COVID- 19

Ohun tí àwọn Oníròyìn nílò fún ìkóròyìn jọ tó dára lásìkò Àjàkálẹ̀ Ààrùn Tókárí-ayé COVID- 19 ti ṣe ìwúrí fún idàgbàsókè àkójọ olùgbówósílẹ̀ láti ṣe ìfúnni sí àwọn Oníròyìn. Ń …

Àwọn Orísun ti ilé-iṣẹ́ Ìròyìn lórí Ìfowósílẹ̀ lórí Àjàkálẹ̀ Ààrùn Tókárí-ayé COVID- 19 Read More »

ÀÀBÒ ÀTI ÀÌLÉWU

Ohun Tó Yẹ Ní Ṣíṣe Lásìkò Tí Àwọn Aláṣẹ/ Agbófinró Já Wọ Inú Ilé Rẹ. Láti ọwọ́ Julia Krasnikova | Ọjọ́ kejì-lé-lógún oṣù kẹrin, ọdún 2021 Roman Anin (lọ́wọ́ ọ̀tún), …

ÀÀBÒ ÀTI ÀÌLÉWU Read More »

Àwọn Ìfúnni àti Ìdàpọ̀ ọ̀rẹ́

Ǹjẹ́ o ń wá àyè láti ṣe ìgbéga sí ìmọ̀ọ́ṣe rẹ àti kí o fẹ àgbáyé lójú? Ó fẹ́ fọ́ iṣẹ́ ojoójúmọ́ nínú yàrá-ìròyìn kí o sì ṣe ìdàgbàsókè iṣẹ́ …

Àwọn Ìfúnni àti Ìdàpọ̀ ọ̀rẹ́ Read More »

Ohun tó Yẹ kó o ṣe Lásìkò tí Wọ́n Tẹ̀lé Ọ tàbí Orísun Rẹ

Láti ọ̀dọ Rowan Philip | ọjọ́ kẹtà-dín-lógún oṣù karùn-ún, Ọdún 2021 Harvey Weinstein lẹ́yìn ìgbà tí ó fara hàn ní Ilé-Ẹjọ́ ní New York. Wọ́n padà sọ ọ́ sí ẹ̀wọ̀n, …

Ohun tó Yẹ kó o ṣe Lásìkò tí Wọ́n Tẹ̀lé Ọ tàbí Orísun Rẹ Read More »

ÀÀBÒ. DÍDÁÀÀBÒ BO ARA ẸNI LÓRÍ Ẹ̀RỌ AYÉLUJÁRA FÚN ÀWỌN ONÍRÒYÌN: ÌFÁÀRÀ

Láti ọwọ́ Martin Shelton | ọjọ́ kejìlá oṣù kẹjọ, ọdún 2016 Ṣọ́ ògiri rẹ. (Peter Levy) Dídáààbò bo ara ẹni láìsọ ọkàn rẹ nù Àtẹ àwọn ohun èlò òǹkọ̀wé wà …

ÀÀBÒ. DÍDÁÀÀBÒ BO ARA ẸNI LÓRÍ Ẹ̀RỌ AYÉLUJÁRA FÚN ÀWỌN ONÍRÒYÌN: ÌFÁÀRÀ Read More »

Àìléwu àti Ààbò

Àwọn òǹkà yẹn jẹ́ ohun ìkorò fún àwọn akẹgbẹ́ wa káàkiri àgbáyé. Gẹ́gẹ́ bí aṣojú àwọn oníṣẹ́-ìròyìn ìfẹ̀hónú hàn ṣe sọ, láti 1992, àwọn oníròyìn tí ó ju egbèje (1,400) …

Àìléwu àti Ààbò Read More »

Kíkó Ìròyìn Lópòópónà Jọ Lórí Àwọn Tó Ń Fẹ̀họ́nú Hàn.

Abraji’s Security Manual fún kíkó ìròyìn lópòópónà jọ lórí ìfẹ̀hónú hànKíkó Ìròyìn Lópòópónà Jọ Lórí Àwọn Tó Ń Fẹ̀họ́nú Hàn. Kíkó ìròyìn jọ lórí ìfẹ̀hónú hàn lóri pópó níṣe pẹ̀lú …

Kíkó Ìròyìn Lópòópónà Jọ Lórí Àwọn Tó Ń Fẹ̀họ́nú Hàn. Read More »

ÀÀBÒ Ẹ̀RỌ AYÉLUJÁRA

Wọ́n gba àwọn Oníròyìn ní ìyànjú gidigidi láti dá ààbò bo àwọn ìbánisọ̀rọ̀ wọn àti àwọn ìròyìn wọn láti dènà ìruga sókè ìhalẹ̀mọ́ni. Síbẹ̀, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹ̀kọ́ ṣe àfihàn pé …

ÀÀBÒ Ẹ̀RỌ AYÉLUJÁRA Read More »

Irinṣẹ́ Fún Àgbéyẹ̀wò Ààbò Àwọn Oníṣẹ́-Ìròyìn.

Jọ̀ ó tẹ “tókàn” láti bẹ̀rẹ̀. Irinṣẹ́ Fún Àgbéyẹ̀wò Ààbò Àwọn Oníṣẹ́-Ìròyìn (JSAT) dàgbàsókè fún ìlò àwọn Alábàáṣepọ̀ GIJN àti àwọn Oníròyìn káàkiri àgbáyé. Lórí ìparí, irinṣẹ́ fún àgbéyẹ̀wò máa …

Irinṣẹ́ Fún Àgbéyẹ̀wò Ààbò Àwọn Oníṣẹ́-Ìròyìn. Read More »

Àìléwu àti Ààbò

Àkójọpọ̀ ìṣìrò korò: àwọn oníṣẹ́-ìròyìn tí ó ju egbèje lọ ní ó di pípa ní 1992, pẹ̀lú àwọn tí wọ́n dojú ìjà kọ tí wọ́n sì ṣe inúnibí sí ju …

Àìléwu àti Ààbò Read More »

Ohun tó Yẹ kó o ṣe Lásìkò tí Wọ́n Tẹ̀lé Ọ tàbí Orísun Rẹ

Láti ọ̀dọ Rowan Philip | ọjọ́ kẹtà-dín-lógún oṣù karùn-ún, Ọdún 2021 Harvey Weinstein lẹ́yìn ìgbà tí ó fara hàn ní Ilé-Ẹjọ́ ní New York. Wọ́n padà sọ ọ́ sí ẹ̀wọ̀n, …

Ohun tó Yẹ kó o ṣe Lásìkò tí Wọ́n Tẹ̀lé Ọ tàbí Orísun Rẹ Read More »