YÀRÁ ÌRÒYÌN ÀWỌN AKẸ́KỌ̀Ọ́ 

Wọ́n ti Gbóríyìn fún Ẹ̀ka Iṣẹ́ Ìwádìí lórí Ìròyìn tuntun, ti ilé ẹ̀kọ́ Fáṣítì Toronto lásìkò Àjàkálẹ̀ Àrùn 

Láti ọwọ́ Jelter Meers |  Ọjọ́ Kẹẹ̀dógún, Oṣù Belú, Ọdún 2020 

Láti ìgbà tí wọ́n ti ṣe í fi lọ́ọ́lẹ̀ ẹ̀ka iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn ti ilé ẹ̀kọ́ Fáṣítì Toronto lọ́jọ́ kejìlélogúń, Oṣù Ọ̀wàwà, ní wọ́n tí ń gba kóríyá láti ọ̀dọ̀ àwọn olùkọ́ àti àwọn oníròyìn bákannáà lórí wípé akọ̀ròyìn àti olùkọ́ ni Robert Cribb ni yóò léwájú fún àkànṣe iṣẹ́ ọ̀hún.