The Field Guide to Security Training

Ìtọ́ni sọ́nà lórí ìdánilẹ́kọ̀ọ́ lórí ètò ààbò jẹ́ kọ̀ríkúlọ́ọ́ọ̀mù tí Open News fi lọ́ọ́lẹ̀, àwọn ìgbìmò tó ń ṣe ìrànwọ́ fún àwọn olùgbé jáde, àwọn ọlọ́gbọ́n orí, ó àwọn onímọ̀ nípa dátà pẹ̀lú ìfọwọ́sowọ́pọ̀ lórí àkànṣe iṣẹ́ lórí Ìròyìn àti ìkànnì Buzz Feed Open Lab tó jẹ́ ìkànnì iṣẹ́ ọnà àti ìmọ̀ ẹ̀rọ, and ẹ̀ka ti Buzz Feed News. 

Àwọn ìtọ́ni sọ́nà mìíràn tó wúlò

Ìwé ìléwọ́ Mojo: Àlàyé lórí Iṣẹ́, láti ọwọ́ Ive Burum. Èyí ni ìwé atọ́ni sónà olójú ewé ọ̀ọ́dúnrún ó lé àádọ́ta tí òǹkọ̀we GIJN, tó tún ń kọ̀wé fún Mojo, I ó Burum,