Reporting Indigenous

Ìròyìn yìí sọ ojú abẹ níkòó, láti ọwọ́ Mark Lee Hunter àti Luuk Sengers, [Ó wà fún títà ní ilé iṣẹ́ tó ń rí sí iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn]. Àfihàn lórí ọgbọ́n àtinúdá, tí kò sì yọ bí a ṣe lè kọ ìròyìn tó lé ké n kà, tó sì yá kánmá kánmá pẹ̀lú ìparí tó jíire. Èdè tí Wọ́n fi kọ́ọ́: Gèésì. 

Ìròyìn tó mú iṣẹ́ ìwádìí lọ́wọ́ kìí ṣe ìwé atọ́ni sónà ṣùgbọ́n ibi ìpamọ́ àwọn ohun èlò lórí ẹ̀rọ ayélujára àti ohun àmúlò, èyí tó dàgbà