ỌPẸ́ PÀTÀKÌ LỌ́WỌ́ ÀWỌN TÓ Ń ṢE ONIÍGBỌ̀WỌ́ 

ROBERT R. 

MCCORMICK FOUNDATION 

Ẹ fẹ́ràn wá lórí Facebook 

Ẹ tẹ̀lé wá lórí twitter 

Ṣe alábàápín ní ìkànnì RSS

ÀJỌ IJEC ṢE ÀGBÀ TẸRÙ IṢẸ́ TÍ Ẹ̀KA YÌÍ Ń ṢE LÓRÍ ÌRÒYÌN TÍ KÒ NÍ ÈRÈ LÓRÍ.

NÍPA ÌGBÌMỌ̀ ÈTÒ Ẹ̀KỌ́ TÓ Ń RÍ SÍ IṢẸ́ ÌWÁDÌÍ LÓRÍ ÌRÒYÌN 

Ìgbìmọ̀ ètò ẹ̀kọ́ tó ń rí sí iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn, èyí tí ìyẹn ajọ IJEC ṣe àgbékalẹ̀ ìpàdé àwọn onímọ̀ ní ilé ẹ̀kọ́ Fáṣítì tí wọ́n ń kọ́ nípa iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ dátà jákèjádò àgbáyé gbogbo. 

IJEC ṣe àfihàn àwọn iṣẹ́ ìwádìí àti ohùn èlò tí àwọn ẹ̀ka ẹ̀kọ́ àti àwọn akẹ́kọ̀ọ́ gbé kalẹ̀. Ìgbìmọ̀ yìí tún gbà wọ́n níyànjú fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ láàárín àwọn olùkọ́, àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àti àwọn oníròyìn lórí yàrá ìròyìn tí kò ní èrè jíjẹ nínú.