Aabo Ofin ati Iranlọwọ pajawiri
Tani ó ń gbèjà ẹ̀tọ́ àwọn oníṣẹ́ ìròyìn? Tani ó le pèsè àtìlẹ́yìn tí pàjáwìrì bá ṣẹlẹ̀? Èyí ní àwọn ìtọ́sọ́nà sí àwọn ẹgbẹ́ tí wọ́n ní ìdásílẹ̀ tí ó ń ṣe àmọ̀dájú ní gbígba ìrànlọ́wọ́ òfin fún àwọn oníṣẹ́ ìròyìn àti àwọn àjọ tí ó ń pèsè àtìlẹ́yìn pàjáwìrì sí àwọn oníṣẹ́ ìròyìn nínú ewu.
Ìtọ́sọ́nà Akoroyin láti yàgò fún Awọn ẹjọ àti Àwọn ẹwù Òfin mìíràn
Òfin olúgbèjà tipsheet
Ìrànlọ́wọ́ pajawiri fún Àwọn oníròyìn
Nje eleyi le ràn é lọwọ? Beeni Beeko
O ṣi ni ìbéèrè?
Kàn sí tábìlì iranlọwọ wà.
Pada sí
Related Article
About The GIJN Help Desk
Reporting Tips and Tools
Data Journalism
Contacts and Networking
Teaching and Training
Awards
COVID-19 Resources
Distribution, Promotion, and Freelancing
Human Trafficking, Forced Labor, and Slavery
LGBTQ Issues