Journalist Survival Guide

Ni èyí tí àjọ Samir Kassir tó kalẹ̀ sí ìlú Beruit ṣe àgbékalẹ̀ rẹ̀, atọ́nà lórí àwọn abẹ̀mí ni wọ́n gbé kalẹ̀ láti ṣe ìrànwọ́ fún àwọn akọ̀ròyìn àti àwọn ajàjàgbara to ń ṣiṣẹ́ lójú ogun àti ibi tí làásìgbò tí ń wáyé ṣùgbọ́n tí kò sì yọ àwọn ìgbésẹ̀ tó yẹ láti tẹ̀lé lórí ètò ààbò lọ́nà ìgbàlódé. Èdè tí Wọ́n fi kọ́ọ́: Gẹ̀ẹ́sì àti Lárúbáwá. 

Ohun èlò tó rọ̀ òfin kí ìròyìn tú jáde: Atọ́nà fún àwọn oníròyìn lórí bí wọ́n ṣe lè ní àǹfààní sí ìròyìn láti ọ̀dọ̀ ìjọba: Ìwé olójú ewé márùn-ún dín lọ́gọ́rin bojú wo ìlànà tí àwọn akọ̀ròyìn tó ń gba ọ̀nà tó tọ́ láti fi kó ìròyìn jọ. Ìwé yìí wá láti ọwọ́ àjọ tí wọ́n ń pè ní Access Info Europe àti Network for Reporting on Eastern Europe n-ost. Ó wà ní èdè Gẹ̀ẹ́sì, Italian, Russian, Italian, Macedonian, Bosnian, Croatian, Hungarian àti Serbian.

Kíkó ìròyìn jọ lórí ìwà tí kò bójú mu: Àpótí irin iṣẹ́ fún àwọn oníròyìn làásìgbò àti ìwà tí kò bójú mu: Èyí ni ìwé olójú ewé mọ́kànlélógúta tó bojú wo