Ìtàn iṣẹ́ akọ̀ròyìn tó jọ mọ́ dátà 

Láti ọwọ́ Brant Houston | Ogúnjọ́, Oṣù Ọ̀pẹ, ọdún 2021

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn akọ́ṣẹ́mọsẹ́ oníròyìn ní Wọ́n ṣe ìwádìí bí iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ dátà ṣe bẹ̀rẹ̀ ní ọdún 1952 nígbà tí àjọ kan tí wọ́n mọ̀ sí CBS Network tó kalẹ̀ sí ìlú Amẹ́ríkà ṣe lo àwọn àìmọye nípa ẹ̀rọ kọ̀ǹpútà ayé ìgbà náà láti fi sọ bí èsì ìbò Ààrẹ ọdún náà yóò ṣe rí. 

Díẹ̀ rèé nínú ọ̀rọ̀ náà nítorí à bá lọ, ó à bá bọ̀, wọn kò lọ dátà náà fún ìròyìn ọ̀hún títí di ọdún 1967 nígbà tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ si ní lo dátà ní pẹrẹhu.