Turbulent with a chance of data: Journalism’s drone-powered futures: A guide to storytelling with UAVs, láti o̩wó̩ Monica Sengul-Jones nínú datajournalism.com
Tips on Drone Journalism, láti o̩wó̩ Raffy Tima tí ó jé̩ àgbà olóòtú ìròyìn àti oníròyìn pè̩lú GMA Network Manila, Philipines tí wó̩n s̩e àgbékalè̩ nígbà GIJC17.
Six Tips for Succeeding at Drone Journalism, ató̩nà láti o̩wó̩ Jonny Miller. Olùbádàpò̩ Code for Africa News tí ó yan àwòrán àti ìròyì dúróònù láàyò.
4 Tips for Better Drone Journalism Stories , láti o̩wó̩ Irene Wangui fún International Journalism Network
Drone Journalism Manual láti Drone Journalism Lab ní ilé-è̩kó̩ gíga University of Nebaraska-Lincoln College of Journalism and Mass Communication
Experts offer insights into drone innovation Àròko̩ láti o̩wó̩ Sherry Ricchiardi fún International Journalism Network s̩e àkósínú ò̩pò̩ agbègbè tí ó sì fi ò̩pò̩lo̩pò̩ àpe̩re̩ sílè̩, bí tí alábala mé̩rin tí ó dá lé orí slum tí ó tóbi jù ní àgbáyé tí wó̩n pè ní “ Unequal Scenes. ”
Observations on how we teach drone journalism, láti o̩wó̩ Judd Slivka, olùdarí àkó̩kó̩ fún is̩é̩-ìròyìn láti òkè fún Missouri School of Journalism.
The Engine Room , àjo̩ aláìgbáralé ìjo̩ba tí ó wà ní ilè̩ Amé̩ríkà s̩e ìfilò̩ ohun èlò tí wó̩n pè ní ‘Do it Yourself Arial Photography.
How drones are changing journalism – media technologist Ben Kreimer on storytelling from the air, ìfò̩rò̩wérò̩ pè̩lú ò̩kàn nínú àwo̩n olùbánisò̩rò̩ ní Digital Innovators’ Summit 2016 ni Berlin.
What You Need to Know About Drones in J-Schools, gé̩gé̩ bí èrò Kathleen Bartzen Culver, alága James E. Burgess nínú Journalism Ethics ní School of Journalism & Mass Communication ní University of Wisconsin-Madison.
Drones in Media Bring New Perspectives, Ethical Issues, láti o̩wó̩ Sarah Hartley , alátúns̩e àti olùbádásílè̩ ní Contributoria.com.
World of Drones, ohun èlò láti o̩wó̩ e̩gbé̩, New America, ní ìwé è̩kó̩ ìbè̩rè̩ àti àlàyé lórí àwo̩n òfin dúróònù ní ilè̩ òkèèrè.
Investigating with Drones, Stone Tablets, and LinkedIn láti o̩wó̩ Sheila Coronel, Olórí agbo-ìmò̩ nípa ò̩rò̩ è̩kó̩ ní Columbia Journalism School.
Democratizing the Sky: Drones in Visual Journalism, ìtàkurò̩so̩ pè̩lú òsìs̩é̩ ayàwòrán New York Tiimes Josh Haner, e̩ni tí ó tètè bè̩rè̩ sí lo àwòrán yíyà dúróònù. Níbí sì ni Haner tì sò̩rò̩ àwo̩n dúróònù tí ó ń lò àti ààbò: Taking Visual Journalism Into the Sky With Drones.
Five lessons learned about the drone part of drone journalism è̩kó̩ nípa fífò láti Missouri Drone Journalism program, lara èyí tí a ti rí “wind is variable.”
Bard College ni US ní ìtàkùn ayélujára fún ibùdó ìké̩kò̩ó̩ tí ó ń mójú tó ò̩rò̩ e̩jó̩ tí ó je̩ mó̩ dúróònù, pè̩lú àwo̩n ohun mìíràn.