Ìs̩àtúnko̩ àti ìs̩àkóso

Crafting Investigative Reportage Into Dramatic Narratives,  láti o̩wó̩ Vinod K Jose, Olùs̩àtúnko̩ àgbà fún The Caravan, Ìwé ìròyìn àkó̩kó̩ fún is̩é̩ ìròyìn aláròyé àti o̩ló̩fintótó ní ilè̩ India. Àgbékalè̩ GIJC19  so̩ nípa ‘ìdeation’, ò̩nà àbáwo̩lé nípa ìs̩àtúnko̩ àti ìhùwàsí tí ó tò̩nà fún ìròyìn. Síwájú rí, PowerPoint tí ó pè̩lú àpe̩e̩re̩ .

Using Story-Based Inquiry to Focus, Manage and Build ni àkòrí ní GIJC17 fún Mark Lee Hunter, tí ó s̩e àgbékalè̩, Story-Based Inquiry, tí a mò̩ mó̩ síso̩ ìtàn o̩ló̩fintótó káàkiri.

Editing the Investigative Story  láti o̩wó̩ Mark Schoofs. . Ni GIJC17, olùs̩àtúnko̩ Buzzfeed News’ Investigative & Projects mójú tó “ìbè̩rè̩ tí ó s̩e kókó”. 

Precautions Editors Must Take è̩kó̩ mé̩jo̩ tí a s̩e àgbékalè̩ rè̩ ní GIJC19 láti o̩wó̩ Musikilu Mojeed, Olùs̩àtúnko̩ àgbà, Premium Times, Nigeria.

Editing the investigative journalism story, àgékúrú àwo̩n kókó tí a s̩e ní ìpérò GIJC17.

Pre-Publication Quality Control, àgbékalè̩ láti GIJC17 láti o̩wó̩ Nils Hanson, Olùs̩àtúnko̩ àgbà, Mission Investigate (Uppdrag granskning), Swedish Television (SVT)

Take our playbook: NPR’s guide to building immersive storytelling projects,  s̩e àpéjúwe ìlànà ìdàgbàsókè tí wo̩n ń pè ní Hypothesis-Driven Design 

Managing the Investigative Project, ìtó̩nisó̩nà láti o̩wó̩ Walter Robinson, olùs̩àtúnko̩ ní The Boston Globe, tí ó sò̩rò̩ níbi ìdánilé̩kò̩ó̩ Uncovering Asia 2016 ní Nepal. “A máa ń s̩e àkóso ìdàrúdàpò̩”.

A Who’s Who of Editors Point to Their Greatest Influence: Paul Steigeràròko̩ Poynter Institute nípa Paul E. Steiger, olùs̩àkóso ìs̩àtúnko̩ nígbà kan rí fún The Wall Street Journal.

5 Tips for Managing Investigative Journalism Projects,  ìmò̩ràn láti e̩nu àwo̩n àgbà ò̩jè̩ onís̩é̩-ìròyìn o̩ló̩fintótó mé̩ta tí journalism.co.uk s̩e àgékúrú rè̩

Tips for Editing Investigative Stories,  àko̩sílè̩ láti o̩wó̩ Jessica Weiss fún IJNet

Our IKEA-Inspired Kit for Newsroom Processes, láti o̩wó̩ Robin Kwong, Olórí è̩ka ò̩ní ìfijís̩é̩ ní Financial Times

10 Resolutions for Newsroom Managers, láti o̩wó̩ Jill Geisler, tí ó di ipò alága Bill Plante ní Leadership and Media Integrity ní Loyola University ní Chicago mú. Tí a s̩e àtè̩jáde rè̩ nínú Columbia Journalism Review

Research Plan for Investigative Projects nínú àlàkalè̩ ètò ìs̩e tí Margot Williams, tí ó ti fìgbà kan rí jé̩ olùs̩àtúnko̩ as̩èwádìí ní The Intercept, tí ó sì sò̩rò̩ ní GIJC19, s̩e è̩dá