ÌRÒYÌN 

Ilé Ẹ̀kọ́ Fáṣítì Illinois níbi tí wọ́n ti ń fi Ẹ̀dùn Ọkàn hàn Nípa Àjàkálẹ̀ Àrùn COVID-19 àti bí wọ́n ṣe ń ń polongo bí àwọn ènìyàn ṣe ń lòdì sí òfin lórí ẹ̀rọ ayélujára Ìbánidọ́rẹ̀ẹ́

Láti ọwọ́ Ga in Good, juila Morrison àti Dylan Tiger/ Fún Àjọ CU Citizen Access | Ọjọ́ Kẹfà, Oṣù ṣẹ́ẹ́rẹ́ Ọdún 2021. 

Àgbéyẹ̀wò ìwé ìfẹ̀húnú han, tí iye wọn lé ní irínwó lórí àwọn tó ń ṣe àríyá, tí wọ́n sì ń lòdì sí òfin ìlera, and fífi ọwọ́ pa idà òfin lójú lásìkò kí onílé ó gbé lé ní àwọn ìyẹ̀wù wọn gbogbo àti kíkó ará jọọ ni èyí tó kọjá bó ṣe fojú hàn tẹ̀lé rí. 

Nígbà tí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tẹ̀lé àwọn ìlànà wọ̀nyí nípa lílo ìbòmú wọn, nípa yíyà fún àwùjọ elérò rẹpẹtẹ, sìbẹ̀ ogunlógọ̀ akẹ́kọ̀ọ́ ni wọ́n ṣì lọ sí ibi àríyá, tí wọ́n sì tún kóra jọ sí àwọn ilé Gíríìkì àti àwọn ìyẹ̀wù wọn gbogbo. 

Cite this article

APA: adminTheCJID. (2023). ÌRÒYÌN . CJID. Retrieved from https://thecjid.org/iroyin/

Author