Ìròyìn tó jọ mọ́ Dátà: Àkójọpọ̀ GIJN

Àwòrán

Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú

Tí o bá ní àkójọpọ̀ dátà tó níí ṣe pẹ̀

lú agbègbè, àwọn ohun èlò wọ̀nyí àti àwọn àtẹ àmọ̀ràn lè ṣe

ìrànwọ́ fún àtúpalẹ̀ dátà rẹ nípa lílo àwòrán máàpù.

Ohun èlò máàpù tó wọ́pọ̀

jùlọ tí wọ́n ń lò nínú nínú yàrá ìkóròyìn ni ArcGIS láti inú Esri (tó ní

àwọn àṣàyàn ọ̀fẹ́ fún àwọn akọ̀ròyìn) àti ohun èlò QGIS tí kò ní kọ́

lú ń kọ́ọ́ nínú nípa lílo rẹ̀.

Àwọn míràn wúlò fún wíwo àwòrán, ṣùgbọ́n a ti fi ọ̀nà míràn kun láti máà wo máàpù.

Wíwo àwòrán tó jọ mọ́ dátà lórí máàpù, ní òdodo, jẹ́ àgbékalẹ̀ GIJC19 láti ọwọ́ Inga Schlegel

àti Johannes Kröger ti ilé ẹ̀kọ́ Fáṣítì Hafencity tó wà nílùú Hamburg.

Datajournalism.com ń ṣe àgbékalẹ̀ ìdánilẹ́kọ̀ọ́ lórí máàpù ní orí àtẹ QGIS àti CartoDB láti ọwọ́

akọ̀ròyìn tí iṣẹ́ rẹ̀

jọ mọ́, Maarten Lambrechts.

JEO jẹ́ ìkànnì iṣẹ́ ìròyìn tí Gustavo Faleiros dá sílẹ̀

láti fi ṣe í fi lọ́ọ́

lẹ̀

ibi ìpamọ́ dátà sí. Ó ń ṣe

ẹ̀kúnwọ́ fún àwọn ilé iṣẹ́ ìròyìn, àwọn tó ń kó ìròyìn jọọ lórí ẹ̀rọ ayélujára àti àwọn ẹgbẹ́ ẹlẹ́yinjú

aláàánú láti gbé ìròyìn wọn jáde lórí ayélujára. Àlàyé ní kíkún fún Àmọ̀ràn àti Àtìlẹ́yìn wà

níhìn-ín.

Àwọn ohun èlò ìrànwọ́ mìíràn wà fún lílò Máàpù fún Ìròyìn: Atọ́nà fún fún Ìròyìn pẹ̀lú

Àtìlẹ́yìn Kọ̀ǹpútà (2017) èyí ni ìwé atọ́ni sónà tó ń ṣe atọ́ka fún lílo ìkànnì QGIS láti ṣe àtúpalẹ̀

dátà pẹ̀

lú máàpù, tí kò sì yọ Ìgbáradì fún dátà lórí ẹ̀rọ ayélujára sílẹ̀. Àwọn tó kọ ìwé ọ̀hún ni

àwọn akọ̀ròyìn ilẹ̀ Amẹ́ríkà, Jennifer LaFleur, David Herzog àti Charles Minshew, tí wọ́n ń ṣe

ìdánilẹ́kọ̀ọ́

lórí GIS fún àwọn oníròyìn àti àwọn olóoòótú ìròyìn lórí iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn. Ẹ̀yà

ìwé yìí tí wọ́n kọ́kọ́ ṣe dá lórí ArcGIS láti ìkànnì Esri. (Ó wà fún títà ní IRE).

Mark Monmonnier ní onírúurú ìwé tó dá lórí máàpù tí kò sì yọ Bí o ṣe lè pa irọ́ pẹ̀lú Máàpù, ó

wà nínú àtúnṣe kẹta (2018). (Ó wà fún títà).

Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú