Irinṣẹ́ Fún Àgbéyẹ̀wò Ààbò Àwọn Oníṣẹ́-Ìròyìn.

Jọ̀ ó tẹ “tókàn” láti bẹ̀rẹ̀. Irinṣẹ́ Fún Àgbéyẹ̀wò Ààbò Àwọn Oníṣẹ́-Ìròyìn (JSAT) dàgbàsókè fún ìlò àwọn Alábàáṣepọ̀ GIJN àti àwọn Oníròyìn káàkiri àgbáyé. Lórí ìparí, irinṣẹ́ fún àgbéyẹ̀wò máa ṣe ìfihàn oríṣìí àwọn ìṣedúró. Tẹ̀ ẹ́ tàbí fi ìròyìn náà pamọ́ fún ìlò àwọn àjọ. JSAT wà ní beta lọ́wọ́lọ́wọ́ èyí yóò sì dàgbàsókè síwájú si. A kí ìwọlé rẹ káàbọ̀.