Is̩é̩ tí ó gbo̩ngbó̩ nípa sís̩e is̩é̩ ìròyìn o̩ló̩fintótó lè sú ènìyàn látàrí orís̩irís̩i àgbéyè̩wò ajé̩mó̩-ìs̩èlú. Ohun èlò yìí mójú tó díè̩ nínú àwo̩n àdojúko̩ tí àwo̩n adás̩é̩s̩e àti àwo̩n ilé-is̩é̩ ìròyìn máa ń rí látàrí sís̩e àgbéjáde àti àtúnpín ìwádìí. E̩ tún wo̩ àwo̩̩n ohun-èlò tí ó jo̩ mó̩ lórí ìbánis̩e àti sís̩àfihàn ipa, léyìí tí e̩ lè rí ní Sustainability Resource Center ti GIJN.
Àwo̩n ohun èlò fún àjo̩
Ìpinka àti àdás̩e
- Sís̩e àgbékalè̩ àwo̩n ìtàn o̩ló̩fintótó
- Sís̩e àgbékalè èrò ní àkókò àjàkálè̩ àrùn
- Ibi tí a ti lè s̩e àgbékalè̩ èrò
- Ibi tí a ti lè rí ìrànwó̩ owó
- Àdéhùn
- As̩èdúró fún ewu
- As̩èdúró fún gbèsè aje̩mó̩-ìròyìn
- Ààbò àti Ìs̩ó̩
- Awo̩n ìtàkùn fún àdáko̩