Ipa Alápèjúwe oníwàádìí: ohun-kíkà pàtàkì.
Iṣẹ́-ìròyìn oníwàádìí ń tan ìmọ́lẹ̀ nínú àwọn kọ̀rọ̀ tó ṣókùnkùn èyí tó jẹ mọ́ ènìyàn, àjọ ìhùwàsí ìjọba àti ìgbésẹ̀, àtúnṣe kíákíá, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ fún ìmúdàgbà àwùjọ. Síbẹ̀síbẹ̀, ó ṣòro láti ṣàfihàn ipa yìí – ó jẹ́ ohun pàtàkì gẹ́gẹ́ bí ọlọ́rẹ tó fẹ́ mọ ipa iṣẹ́ tí wọ́n ṣèrànwọ́ fún. Àwọn ọ̀nà nìyí láti ṣàfihàn ìgbéléwọ̀n ohun tó o tó, èyí tí yóò jẹ́ nípa sísọ ọ́ jáde.
Àwọn ìtalólobó méjìlá láti ṣàwárí ọ̀pọ̀ ènìyàn mìíràn àti ipa lórí ìròyìn oníwàádìí tó wúni lórí.
Iṣẹ́-ìwádíí Ipa Oníwàádìí GIJN
Ipa Oníwàádìí: Ìjábọ̀ lórí ìgbéléwọ̀n tó dára jù lọ lórí ìjábọ̀ ipa oníwàádìí.
Àká-Àkójọpọ̀-fáyẹ̀wò iṣẹ́-ìwádìí àwọn olùdásílẹ̀ ipa ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròyìn-jáde.
Àwọn irinṣẹ́ ipa ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròyìn-jáde.
Àwọn ìṣe tó dára jù lọ nínú ìgbéléwọ̀n ipa ìjábọ̀ iṣẹ́-ìwádìí.
Ǹjẹ́ a lè ṣègbéléwọ̀n ipa ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbé-ìròyìn-jáde bí? ṣàgbéyẹ̀wò pápá ìwádìí náà.
Ipa ìgbéléwọ̀n: ìkànnì lórí àwọn irinṣẹ́ àti orísun-ìmọ̀.
Bí a ṣe lè ṣàmúlò ọnà-ìgbéléwọ̀n tó tọ̀nà.
Ipa Ńlá: Ìtọ́sọ́nà-péréte sí èrè-owó ti àwọn iṣẹ́-ìwádìí pàtàkì.
Ìtọ́sọ́nà fún Ipa pápá-ìwádìí láti ọwọ́ “Dor Society”, àjọ tí-kò-fi-tèrè-owó-ṣe pẹ̀lú àfojúsùn eré-ṣíṣe, àkòrí mìíràn lórí ìpínfunni fún ipa àti ìgbéléwọ̀n, nípa jíjẹ́ kó wúlò dáradára.
Ipa Alápèéjúwe oníwàádìí: Àfikún ohun-kíkà.
Ilé-ẹ̀kọ́ Oníròyìn Amẹ́ríkà tíí ṣe tọ̀nà-ìgbéléwọ̀n fún ìròyìn.
Àgbéyẹ̀wò ipa Àgbáyé “Panama Papets” Lẹ́yìn ọdún mẹ́ta.
Bí a ti ń ṣàgbéró ọ̀nà-ìgbéléwọ̀n fún yàrá-ìròyìn tó bójúmu.
Ipa Ńlá: Ìtọ́sọ́nà-kékeré fún èrè-owó lórí àwọn iṣẹ́-ìwádìí pàtàkì.
Bí ipa àti ìfojúbùkà ṣe ràn Caralina lọ́wọ́ lórí ìròyìn gbogbogbò rẹ̀.
Kín ni ohun tó ń jẹ́ ọ̀nà-ìgbéléwọ̀n Gidi?
Ìyípadà Ìgbéléwọ̀n ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròyìn-jáde: Bí àríyànjiyàn lórí ìròyìn ṣe nílò ẹ̀rí tó dájú – àti bí a ṣe le rí ọ̀kan.
Ọ̀nà-ìgbéléwọ̀n wà káàkiri lórí ìkànnì-ayélujára. Bí wọ́n ṣe máa ń ṣe ìrànwọ́ nìyí..
Bóyá a tilẹ̀ ti ń wá ọ̀nà láti yanjú ìṣòro iṣẹ́-ìròyìn lọ́nà tí kò tọ́.
Ilé-iṣẹ́ ìdásí àwùjọ ń jìjàkadì lórí àṣeyọrí ìgbéléwọ̀n.
Bá àgbájọ ìkànnì ìròyìn tó dára jù lọ pàdé.
Onímọ̀-ọrọ̀-ajé ṣàgbéjáde ọ̀nà tí à ń gbà gbé iṣẹ́-ìròyìn oníwàádìí pamọ́.
Bí a ṣe ń ṣẹ̀dá àjọ fún ìjábọ̀ láti ṣe àfihàn ipa lórí yàrá-ìròyìn tí-kò-fi-tèrè-owó-ṣe rẹ.
Iṣẹ́-ìròyìn oníwàádìí ń ṣiṣẹ́: ọgbọ́n-inú ipa.
Àgbéyẹ̀wò ipa iṣẹ́-ìròyìn Alálàyé
Ipa ìdàgbàsókè iṣẹ́-ìròyìn oníwàádìí tí-kò-fi-tèrè-owó-ṣe abẹ́lé tọdún 2017.A