gijn-logo

Investigative Reporting- À toolkit for Reporters

Iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn: Ohun èlò fún àwọn oníròyìn: ìwé atọ́ni sónà olójú ewé ọgọ́rùn-ún ó lé méje èyí tí ilé iṣẹ́ Amẹ́ríkà tó ń rí sí oko òwò aládàńi gbé jáde lọ́dún 2009 pẹ̀lú aàtìleyìn USAID àti Al-Masry Al-Youm tí wọ́n ń rí sí iṣẹ́ akọ̀ròyìn. Èdè tí Wọ́n fi kọ́ọ́: Gèésì. 

Iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn lásìkò ìjọba àwa àwa ara wá: À wò kọ́se, ìpèníjà àti kíkó ẹ̀kọ́:  Ìwé ìjábọ̀ láti ọwọ́ Drew Sullivan tí àjọ tó ń rí sí ìròyìn lórí ìwà ọ̀daràn àti ṣíṣe owó ìlú kúmo kùmo, pẹ̀lú ìlànà lórí ètò àti mú kí iṣẹ́ àwọn olóoòótú ìròyìn ká ojú òṣùwọ̀n pẹ̀lú ààbò tó péye fún wọn. Àjo tó ń rí sí ìgbé lárugẹ ilé iṣẹ́ ìròyìn ló ṣe a gbá tẹrù rẹ̀. Èdè tí Wọ́n fi kọ́ọ́ : Gèésì. 

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *