Ìmúwàláàyè

Fún ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbé-ìròyìn-jáde àti àwọn ilé-iṣẹ́ mìíràn tí kì í ṣe fún èrè-owó, wíwá ọgbọ́n-àtinúdá fún ètò-ìsúná fún ìmúwàláàyè, èyí tíí ṣe kọ́kọ́rọ́ fún jíjábọ̀ ju ọdún kan tàbí méjì lọ. Èyí ni àwọn Ẹ̀kọ́ Kòṣeémánìí láti ọ̀dọ àwọn akinẹgbẹ́ wa jákèjádò àgbáyé lórí oríṣìíríṣìí ọ̀nà-tówó ń-gbà-wọ́lé, ìjọ́mọ-ẹgbẹ́ dídarí ètò-ìkówójọ àti àwọn nǹkan mìíràn pẹ̀lú.

Ìmúwàláàyè: Àkójọpọ̀ Ìsọníṣókí

  • Ìmúwàláàyè: Ìfáàrà
  • Ìmúwàláàyè: Ojú-àmúwayé- Ohun Kíkà Pàtàkì
  • Ìmúwàláàyè:  Ojú-àmúwayé- Àfikún Ohun Kíkà
  • Ìmúwàláàyè: Ojú-àmúwayé- Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀-abójú-ayé-mu.

Ètò-ìkówójọ

Ètò-ìkówójọ: Ohun Kíkà Pàtàkì

Ètò-ìkówójọ: Àfikún Ohun Kíkà

Ìdásí Àwùjọ-ènìyàn àti Ọ̀nà-tówó-ń-gbà-wọlé

  • Ìdásí Àwùjọ àti Ọ̀nà-tówó-ń-gbà-wọlé: Ohun Kíkà Pàtàkì
  • Ìdásí Àwùjọ-ènìyàn àti Ọ̀nà-tówó-ń-gbà-wọlé: Àfikún Ohun Kíkà
  • Ìdásí Àwùjọ-ènìyàn àti Ọ̀nà-tówó-ń-gbà-wọlé: Ìwé-ìròyìn
  • Ìdásí Àwùjọ-ènìyàn àti Ọ̀nà-tówó-n-´gbà-wọlé: Oríṣìíríṣìí Ìṣẹ̀lẹ̀ (ètò).

Ọ̀nà-tówó-ń-gbà-wọlé Ajẹmówò

  • Ọ̀nà-tówó-ń-gbà-wọlé Ajẹmówò: Ohun Kíkà Pàtàkì
  • Ọ̀nà-tówó-ń-gbà-wọlé Ajẹmówò: Àfikun Ohun Kíkà
  • Ọ̀nà-tówó-ń-gbà-wọlé: Ìpolówó-ọjà
  • Ọ̀nà-tówó-ń-gbà-wọlé: Àwọn ọ̀nà-Ìsanwó-ohun-èèlò
  • Ọ̀nà-tówó-ń-gbà-wọlé: Àwọn Ọ̀nà-ìsanwó-ohun-èèlò-ìṣẹ̀lẹ̀ abójú-ayé-mu

Àwọn ọ̀nà-tówó-ń-gbà-wọlé-Ajẹmówò: Ìgbówò-lárugẹ, Ìtẹ̀wéjáde, Ìdòwòpọ̀, Ẹ̀tọ́-fọ́jà-títà.

  •  Ìkówójọ-Orí-ìtàkùn-ayélujára
  • Ìkówójọ-orí-ìtàkùn-ayélujára: Ohun Kíkà Pàtàkì
  • Ìkówójọ-orí-ìtàkùn-ayélujára: Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀-abójú-ayému

Àwọn Àkànṣe Àkòrí

  • Àwọn Àkànṣe Àkòrí: Ètò-Ohùn-kíká-sílẹ̀
  • Àwọn Àkànṣe Àkòrí: Owó-sísan-alábọ́dé
  • Àwọn Àkànṣe Àkòrí: Ọ̀nà-ìsanwó-látẹ̀yìnwá nínú òwò-ìpààrọ̀-owó-lọ́nà-ìgbàlódé àti òwò-ìpààrọ̀-owó-lọ́nà-ìgbàlódé
  • Àwọn Àkànṣe Àkórí: Ẹgbẹ́ Alájẹsẹ́kù oníròyìn

Ipa Alápèéjúwe

  • Ipa Alápèéjúwe Oníwàádìí: Ohun Kíkà Pàtàkì
  • Ipa Alápèéjúwe Oníwàádìí: Àfikún Ohun Kíkà

Àwọn Ìtalólobó fún àwọn Ọlọ́rẹ

  • Àwọn Ìtalólobó fún àwọn Ọlọ́rẹ

Ǹjẹ́ ó wúlò fún ọ bí?   BẸ́Ẹ̀ NI         BẸ́Ẹ̀ KỌ́

Ìmúwàláàyè: Ìfáàrà

Iṣẹ̀-ìròyìn tí kò rọ̀gbọ̀kú lórí èrè-owó nìkan ti ń dàgbàsókè díẹ̀díẹ̀ fún odidi ogún ọdún báyìí pẹ̀lú àwọn ìdí abájọ bí i: ìkógbásílé àwọn èle-owó ṣíṣe ayé-àtijọ́, ìyípadà ìmọ̀-ẹ̀rọ òòrèkóòrè àti ìfàyàrán láti fọwọ́sowọ́pọ̀ fún iṣẹ́-ìròyìn tó kógojá láìfi ti  rògbòdìyàn inú àjọ náà ṣe.

Nínú àjọ onímọ̀ yìí, “GIJN” ń ṣe àwárí àwọn ọgbọ́n-àtinúdá láti ṣe kùn-unkundun iṣẹ́-ìròyìn lọ́jọ̀ láti wà láàyè Káàkiri ayé.

Sí ìdùnnú wa ìfọwọ́sowọ́pọ̀ àwọn ọlọ́rẹ iṣẹ́-ìròyìn ń dàgbàsókè. Èyí sì ń pèsè àwọn àǹfààní tuntun ṣùgbọ́n ó nílò àwọn ọgbọ́n-àtinúdá láti mú òmíràn wọlé àti láti tọ́jú èyí tó ti wà nílẹ̀ tẹ́lẹ̀ fún àwọn ọlọ́rẹ, bíbọ́ sí abala yìí mú àkànṣe ìpèníjà wá, èyí tí a ṣe lọ́jọ̀ sínú “àwọn ìtalólobó fún àwọn Ọlọ́rẹ”.

Ní àfikún, àwọn àjọ iṣẹ́-ìròyìn ajẹmọ́-òwò tí ń gbé ohun tuntun jáde. Wọ́n ń ṣe àmúlò àwọn ìlú-mọ̀-ọ́n-ká láti fi fa ojú àwọn òǹkàwé mọ́ra láti tún fi pawó wọlé lọ́nà ti àtijọ́ àti ìgbàlódé. Àwọn ìgbésẹ̀ yìí ni ìlo ìsanwó-fún-àwòrán-yíyẹ̀wò àti ìjọ́dẹ́yìn, ìkówójọ-orí-ìtàkùn-ayélujára, ètò fáwọn-òǹkàwé, gbígbé oríṣìíríṣìí ètò kalẹ̀, lílo àwọn ìkànnì ìbánidọ́rẹ̀ẹ́, ìpolówó àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

Ìmúwàláàyè jẹ́ ìjìjagbara òòrèkòòrè ní àwùjọ tí ohun gbogbo ti ń yípadà. Àjọ onímọ̀ “GIJN” yìí sọ̀rọ̀ lórí àwọn ìdojúkọ, àǹfààní àti ìmúdọ̀tun fún èrè ńlá, fífi ojú-àmúwayé àti ìmọ̀ àwọn akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ ṣe:

Ó ní àfikún bí? Kọ̀wé síwa ní [email protected].

Àwọn ẹ̀kajẹ̀ka wa ni:

  • ÌMÚWÀLÁÀYÈ: ÌSỌNÍṢÓKÍ

Ka àṣàyàn àwọn ìwé àpilẹ̀kọ àti ìjábọ̀ tó ṣe pàtàkì, tó sì tún wúlò, èyí tó ṣe àtúpalẹ tó sì ń yànnàná iṣẹ́-ìròyìn aláìfi-tèrè-owó-ṣe

Ìwàláàyè: Ojú-àmúwayé- Ohun Kíkà Pàtàkì

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ìjábọ̀ pàtàkì ti pèsè àlàyé lẹ́kùn-ún-rẹ́rẹ́ lórí ìdásílẹ̀ àwọn ilé-ẹ̀kọ́ tí yóò ṣèránwọ́ fún iṣẹ́-ìròyìn oníwàádìí. Èyí ni àwọn kókó-ọ̀rọ̀ tó ṣe pàtàkì:

Bíbẹ̀rẹ̀ Àjọ Oníròyìn tíkò-fi-tèrè-owó-ṣe: láti ọwọ́ Àjọ fún Ìròyìn Èyí tíkò-fi-tère-owó ṣe.

Àwọn ète mẹ́fà fún Iṣẹ́-ìròyìn Tówàláàyè

Ìwé-ìléwọ́ ilé-ẹ̀kọ́ ìmúwàláàyè ilé-iṣẹ́-tí-ń-gbé-ìròyìn-jáde ti DW

Akitiyan fún Ìwàláàyè: Ìjábọ̀ túntún lórí ilé-iṣẹ́-tí-ń-gbé-ìròyìn-jáde tí a ṣẹ̀ṣẹ̀ dá sílẹ̀ ní Gúúsù Káríayé

Títẹ̀wéjáde ní owó-péréte: Gbígbé ohun tuntun yẹ àti ìdásílẹ̀ iṣẹ́-ìròyìn.

Bí àwọn Àjọ oníròyìn tíkò-fi-tèrè-owó-ṣe ṣe máa ń ṣàwárí ìmúwàláàyè: Àkànṣe Ẹ̀kọ́ 

Ṣíṣèrànwọ́-owó fún Ojúlówó Iṣẹ́-ìròyìn

Ìpèsè-ìrànwọ́ fún ìròyìn: Àwọn Àjọ àti ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbé-ìròyìn-jáde tíkò-fi-towó-ṣe

Àjọ-tó-ń-ṣe-àtìlẹ́yìn fún ìdásílẹ̀ pápá-ìwádìí iṣẹ́-ìròyìn àti ìròyìn

Gbígbé-ohun-tuntun-yọ nínú iṣẹ́-ìròyìn àti àtòjọ ohun-kíkà fún oníṣòwò

Ipa inú-rere àti òfin / ìlànà owó-orí lórí Àwọn Àjọ Oníròyìn tíkò-fi-tèrè-owó-ṣe.

Ìmúwàláàyè: Ìtọ́sọ́nà ìwàláàyè fún àwọn Ẹgbẹ́ oníwàádìí tíkò-fi-tèrè-owó-ṣe.

Iṣẹ́-ìròyìn oníwàádìí Àgbáyé: Àwọn Ète fún ìrànwọ́

Eré-ìdárayá-ìrújú Tọmọ-ẹgbẹ́

Pẹ̀lú àjọṣepọ̀ “Luminate and Democracy Fund” láti gbé Ìjọ́mọ-ẹgbẹ́ jáde nínú ìrànwọ́-owó oníròyìn láti ṣiṣẹ́ ní oṣù karùn-ún, ọdún 2020. $700,00 jẹ́ iye-owó fún ètò-ìrànwọ́ fún abala ìjọ́mọ-ẹgbẹ́ tó ń rí sí ìgbóhun-tuntun-jáde. Fún àfikún àlàyé láti Kópa wà níbí. Kò sí gbèdéke àkókò.

(Pàyán-àn)

Ìròyìn Rere jẹ́ iṣẹ́-ìwádìí Àjọ Atẹ̀wéjáde Amẹ́ríkà àti Yàrá-ìròyìn “Knight Lenfest” tí ìgbóhùn-tuntun-jáde, èyí tí Àjọ John S. Àti James L. Knight ṣèrànwọ́ fún láti ṣàlàyé àwọn ọ̀rọ̀ tó jẹmọ́ ìmùwàláàyè.

Àwọn Oníròyìn Yúròòpù Gbogbogbò: Ẹ̀kọ́ tuntun lórí ìfilélẹ̀ ète òwò fún ìgbékalẹ̀ iṣẹ́-ìròyìn.

ÈTÒ-ÌKÓWÓJỌ

Èyí jẹ́ àkọlé pàtàkì fún èyí tíkò-fi-tèrè-owó-ṣe. Ohun-àmúlò wa jẹ́ ojúlówó àfojúsùn ìsọnidọlọ́rẹ  àtọkànwá àti àwọn ìwé-àpílẹ̀kọ mìíràn nípa ìkówójọ.

ÌDÁSÍ ÀWÙJỌ-ÈNÌYÀN ÀTI Ọ̀NÀ-TÓWÓ-Ń-GBÀ-WỌLÉ

Sísomọ́ àwọn òǹkàwé ní ọ̀nà tuntun pẹ̀lú ọgbọ́n-àtinúdá, pẹ̀lú ìrànwọ́ ìkànnì ìbánidọ́rẹ̀ẹ́ fún ìmúgbòòrò àwùjọ-ènìyàn àti ọ̀nà-tówó-ń-gbà-wọlé. Ka ìmọ̀ràn abójú-ayé-mu láti ọwọ́ àwọn olóòtú pẹ̀lú ìfẹ́ ìdásí àwùjọ-ènìyàn.

ÈRÈ AJẸMÓWÒ

Kò sí lílọ́ lọ́rùn, jíjèrè jẹ́ ohun pàtàkì, ó sì máa ń wáyé ní ọ̀nà àtijọ́ àti ìgbàlódé. Àwọn akọ́ṣẹ́mọṣé a máa ṣàmúlò àǹfààní ìpolówó-ọjà, ìsanwó-fúnṣẹ́, ìsanwówọlé àti ìjọ́mọ-ẹgbẹ́, ìdòwòpọ̀, àjọṣepọ̀ ìtèwétà, àwọn ẹ̀tọ́ àti ọ̀nà ìtajà àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

ÀWỌN Ọ̀NÀ MÌÍRÀN TÉRÈ Ń GBÀWỌLÉ

Àwọn ọgbọ́n-àtinúdá mìíràn wà láti ṣèrànwọ́ fún iṣẹ́-ìròyìn oníwàádìí. Àwọn wọ̀nyí ni: Ìkọ́ni, Ìkẹ́kọ̀ọ́, ìwé-ìròyìn, Ìgbéròyìnjáde-orí-ìtàkùn-àgbáyé, àwọn ètò, ìsanwó-kekéèké, ìdòwòpọ̀ àti àjọṣepọ̀ ìtẹ̀wétà, ọ̀nà-ìsanwó-àtẹ̀yìnwá-nínú òwò-ìpààrọ̀-owó lọ́nà-ìgbàlódé àti òwò-ìpààrọ̀-owó-lọ́nà-ìgbàlódé, títa dátà, àwòrányíyà ìgbàlódé, gbígbé eré jáde àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

ÌKÓWÓJỌ-ORÍ-ÌTÀKÙN-AYÉLUJÁRA

Ó wà jẹ́ ọ̀nà kan pàtàkì fún ìrànwọ́ iṣẹ́-ìròyìn oníwàádìí, ìkówójọ-orí-ìtàkùn-ayélujára pè fún èrò tó dára àti ìmúṣe tó gúnrégé. Kó bí a tií ṣe é pẹ̀lú àwọn ẹ̀kọ́ láti ọ̀dọ̀ àwọn tó ti gbìyànjú rẹ̀ rí.

IPA ONÍWÀÁDÌÍ

Síṣòdìwọ̀n ipa iṣẹ́-ìròyìn oníwàádìí ti di ohun àmúyẹ tó gbòòrò láti pè fún ìrànwọ́ àwọn ọlọrẹ, òǹkàwé àti onímọ̀dámọ̀dá mìíràn. Kì í ṣe ohun tí a tún le fi ọwọ́ yẹpẹrẹ mú má ṣùgbọ́n ó dùn sọ ju ṣíṣe lọ. Wò ó bí a ti í ṣe é.

Ìkówójọ

Ǹjẹ́ ò ń ṣiṣẹ́ ní ilé-iṣẹ́ àjọ tó-ń-gbé-ìròyìn-jáde tíkò-fi-tèrè-owó-ṣe bí? Iṣẹ́-ìròyìn tíkò-fi-towó-ṣe ti ń gbòòrò jákèjádò. Ó sì jẹ́ ohun pàtàkì láti ní ọgbọ́n-inú tó múnádóko fún ìkówójọ. Èyí ní àwọn ìmọ̀ran iyebíye láti inú iṣẹ́-ìwádìí àwọn ọlọ́rẹ àti ìkówójọ àbàláyé sí ìkówójọ-orí-ìtàkùn-àgbáyé fún ìdáwọ́lé iṣẹ́-ìwádìí.

ÈTÒ-ÌKÓWÓJỌ

  • Ètò-Ìkówójọ: Ohun-kíkà Pàtàkì
  • Ètò-Ìkówójọ: Àfikún Ohun Kíkà

ÈTÒ-ÌKÓWÓJỌ-ORÍ-ÌTÀKÙN-ÀGBÁYÉ

Ètò-ìkówójọ-Orí-Ìtàkùn-Àgbáyé: Ohun-kíkà Pàtàkì

Ètò-Ìkówójọ-Orí-Ìtàkùn-Àgbáyé: Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Abójú-ayé-mu.

ÌFÚNNILÓWÓ-ṢÒWÒ àti ÌRÌN-ÀJÒ-Ọ̀FẸ́

  • Ìfúnnilówó-ṣòwò tó jẹmọ́ “COVID-19”
  • Ìrìn-àjò-ọ̀fẹ́ gbogbogbò
  • Àwọn Ìrìn-àjò-ọ̀fẹ́ jákè-jádò àgbáyé
  • Àwọn Ìrìn-àjò-ọ̀fẹ́ àkànṣe
  • Ìfúnnilówó-sòwò Oníjàábọ̀
  • Ìfúnnilówó-ṣòwò Alákàálẹ̀-ohun-pàtàkì
  • Àwọn Ìfúnnilówó-ṣòwò Mìíràn

Ìdásí Àwùjọ àti Ọ̀nà-tówó-ń-gbà-wọlé: Ohun Kíkà Pàtàkì.

Àwọn Yàrá-Ìròyìn Káàkiri ti ń mọ rírì ìdásí àwùjọ àti bí ìmọ́gaara àti ọ̀nà-ìdásí ṣe lè mú ìfọ̀kànbalẹ̀ lọ́wọ́ àti ọ̀nà-tówó-ń-gbà-wọlé ni ọ̀pọ̀lọpọ̀. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwòṣe fún ìpawówọlé ló ti wà, iṣẹ́-ìròyìn oníwàádìí tíkò-fi-tèrè-owó-ṣe náà sì ń wá èyí tó jẹ́ ojúlówó níbẹ̀.

  • Ìrinṣẹ́ Ọ̀nà tówó-ń-gbà-wọlé fún òǹkàwé.
  • Àwọn ọ̀nà mẹ́rìnlá láti lo ìdòwòpọ̀ láti ṣẹ̀dá iṣẹ́-ìròyìn tó peregedé àti ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ọ̀nà-tówó-ń-gbà-wọlé.
  • Ó ju ẹyin-ojú lọ: Bí iṣẹ́-ìròyìn ṣe lè rérè jẹ nínú ìdásí àwùjọ.
  • Àwọn ẹ̀kọ́ lórí wíwa ojútùú sí eré-ìdárayá-ìrújú ìjọ̀mọ-ẹgbẹ́ fún ilé-iṣẹ́-agbéròyìn-jáde.
  • Ìtọ́sọ́nà fún ọ̀nà-tówó-ń-gbà-wọlé àwùjọ àti ìdásí
  • Àtúnṣe sí Àlàyé-nípa-Ẹni: Ìdí tó fi yẹ kó o bèèrè lọ́wọ́ àwọn ọmọm-ẹgbẹ́ rẹ ohun tí wọ́n mọ̀.

Àwọn Ipa sí Ìsanwó: Ìdí tí àwọn asanwó òde-òní fi yàn láti sanwó fún ìròyìn (2017).

Ìdásí tàbí Àwárí: Ọ̀nà Tó Dàra jù lọ láti Ṣàwárí Àwùjọ wa.

Àwọn Ọ̀nà Mìíràn térè ń gbà wọlé: Ohun-kíkà Pàtàkì

Oríṣìíṣìí ọ̀nà-ìkówójọ àti Ìyànnàná lórí àwọn ọ̀nà-tówó-ń-gbà-wọlé mìíràn ṣe pàtàkì fún ìmúwàláàyè àjọ iṣẹ́-ìròyìn tíkò-fi-tèrè-owó-ṣe.

Àwọn oríṣìíríṣìí ọ̀nà nìyí tí àwọn ọ̀pọ̀lọpọ̀ àjọ ti gbà láti ṣàwárí ìrànwọ́-owó fún iṣẹ́ wọn.

Iṣẹ́-Ìròyin Ajẹmọ́-Ètò-Ìsúná Tó Peregedé

ÌMÚWÀLÁÀYÈ: Ojú-Àmúwayé – Àfikún Ohun-Kíkà

Ìdí tí àwọn ilé-iṣẹ́ ìròyìn kékéèké fi ń rí owó-sísan fún àwọn ohun-èèlò ìgbàlódé gẹ́gẹ́ bí ohun-tó le koko.

Ìrànwọ́-owó fún iṣẹ́-ìròyìn láti ọ̀dọ̀ Ìjọba: Ibi ńlá ni tàbí ibi yẹpẹrẹ?

Àwọn oníròyìn máa ń rí i dájú pé kò sí ìnákúùná owó, akínkanjú-iṣẹ́ fún pípa bílíọ̀nù kan dọ́là wọlé jákèjádò ní ọdún kan.

Àwọn ilé-iṣẹ́ Ìròyìn kò fi tẹ̀mítẹ̀mí gbáralé àjọ-aṣèrànwọ́ – ṣùgbọ́n ìrànwọ́ iṣẹ́-ìròyìn gbòòrò.

Ìjábọ̀ Ìròyìn lọ́nà Ìgbàlódé ti Ọdún 2019

Àwọn orísun àkójọpọ̀-fáyẹ̀wò ọ̀fẹ́ mẹ́wàá lórí ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbr´-ìròyìn-jáde àti àwùjọ oníròyìn (Olùgbọ́)

Àwọn ìdojúkọ méje láti borí nígbà tí a bá ṣẹ̀ṣẹ̀ dá ilé-iṣẹ́ sílẹ̀.

Àjọ Ìmúwàláàyè PBS

Ǹjẹ́ Iṣẹ́-ìròyìn tó péye lè pẹ́ títí bí? Èyí ni àwọn àjọ ogún tó-ń-gbé-ìròyìn-jáde tí wọ́n ń yanjú ìṣòro yìí.

Àjọṣepọ̀, ìjọ́mọ-ẹgbẹ́ àti àìṣègbè láwùjọ: Bí àwọn atẹ̀wétà ní àwọn àgbègbè ìjẹgàba-lórí-ìròyìn ṣe ń gbòòrò.

Àwọn Ìgbésẹ̀ mẹ́rin láti ṣàwárí àwọn ọ̀nà-tówó-ń-gbà-wọlé tuntun fún iṣẹ́-ìròyìn.

Àwọn àṣà-ìgbàlódé àgbáyé lórí ìkànnì-ìbánidọ́rẹ̀ẹ́ àti bí wọ́n ṣe ń nípa lórí àwọn atẹ̀wétà.

Iṣẹ́-ìròyìn Onírànwọ́ tí ń gbèrú nílẹ̀-adúláwọ̀: Ìdí tó fi nóílò àyẹ̀wò fínnífìnní.

Àwọn ìbéèrè tó bá òfin mu mẹ́fà tó yẹ kí ẹni tó fẹ́ dá ilé-iṣẹ́ sílẹ̀ rò.

Àwọn ọjọ́-iwájú márùn-ún fún iṣẹ́-ìròyìn.

Àwọn ọ̀nà-àátọ̀ láti àwọn ilé-iṣẹ́ ìròyìn tó-ń-fèrè-owó-ṣe di àwọn tíkò-fèrè-owó-ṣe.

Sísanwó fún àwọn ìlú mọ̀n-ọ́n-ká fún ìròyìn orí-ìtàkùn-àgbáyé ní Amẹ́ríkà àti Yúróòpù: Ìtalólobo ọdún 2019.

Dídojúkọ àwọn ìdojúkọ nínú ilé-iṣẹ́-ìgbéròyìn-jáde tíko-rọ̀gbọ̀kú-lé-ìjọba: Ipò fún Igbákejì adarí lágbàáyé.

Àádọ́ta àbá láti máa rówó láti ọ̀dọ̀ ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbé-ìròyìn-jáde: atọ́ka tó lọ sàn-án (abala kẹrin)

Àjọṣepọ̀-ìgbédìde gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà ìdàgbàsókè fún ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbé-ìròyìn-jáde.

Ǹjẹ́ àfojúsùn-ọ̀rọ̀-owó ni yóò mú ẹ̀mí iṣẹ́-ìròyìn tó jágaara gùn.

Àwọn ẹgbẹ́ Olùmúlò fẹ́ díjelé ìkànní-ìbánidọ́rẹ̀ẹ́-ojú-ìwé-àgbáyé láti gba iṣẹ́-ìròyìn sílẹ̀ lọ́wọ́ píparun.

Bí a ṣeé lóye oríṣìíríṣìí àwọn òǹkàwé àti bí a tií mú ẹ̀ka kọ̀ọ̀kan sanwó-àjọsọ API

Ìkànnì-ìbánidọ́rẹ̀ẹ́-ojú-ìwé-àgbáyé fún èrè-tíkò-lowó-lọ- Àwọn Ìtalólobó àti Ìṣe tó dára jù lọ. Àpótí Ọlọ́rẹ

“Ìkànnì-ayélujára Òfẹ́” àti Ìdíyelé Fún Ilé-iṣẹ́-tó-ńgbé-ìròyìn-jáde aláfojúsùn-púpọ̀: Àwọn Ewu tó wà nínú Àìkọbi-sí-ìròyìn. CIMA

Àwọn Ìtalólobó mọ́kànlá fún ìdásílẹ̀ àwọn ilé-iṣẹ́-ìròyìn: Àyọlò Anya Schifrin láti inú àbọ Àjọ Walkley 

Àgbéjáde ìwé-atọ́ka INN ti ọdún 2018: Ìpele Ìròyìn INN tíkò-fi-tèrè-owó-ṣe

Èyí ni ìpele ìròyìn tíkò-fi-tèrè-owó-ṣe ti Nieman ní ọdún 2018

Àwọn ọ̀nà wo ni à ń gbà rí owó nínú iṣẹ́-ìgbéròyìn-jáde? “Jamiab” A ti wá pẹ̀lú méjìdínlógún irú èyí.

Adarí-ọkùnrin nílé-iṣẹ́-tó-ń-tẹ̀wé-tà: Bí ìròyìn Orí-ìtàkùn-àgbáyé Àmóhun tuntun jáde Gúgù ṣe ń tún iṣẹ́-ìròyìn rọ: Àwọn Alábòójútó iṣẹ́-ìròyìn nílẹ̀ Yúròòpù àwọn tí wọ́n kángun sí ìrànwọ́ Gúgù jẹ́ àjọ àátẹ̀lé lórí ọ̀rọ̀-òwò ní ìwọ̀-oòrùn Yúróòpù. Bákan náà, àjọ ìròyìn tíkò-fi-tèrè-owó-ṣe àti ilé-iṣẹ́ ìgbéròyìn-jáde tí gbogbogbòò kì í sáàbà gba ìrànwọ́. Ìbéèrè kan ṣoṣo ni pé: Kín ni Ìkànnì-àgbáyé-Gúgù ń gbìyànjú láti rí jẹ lérè nípa nínáwó ìrànwọ́?

Àjọ̀dún Ọdún Kọkànlá Iṣẹ́-ìmọ̀-ẹ̀rọ Ìgbàlódé fún àwọn Oníròyìn ONA (Fídíò wákàtí kan láti ọwọ́ Amy Webb). 

Ìjábọ̀ CIMA: Àtìlẹ́yìn fún ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbé-ìròyìn-jáde tí kò Rọ̀gbọ̀kù lé ìjọba: Âtúpalẹ̀ tó kún fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ Ìrànwọ́

Àgbéyẹ̀wò Ìkìlọ̀ fún ewu lórí wàhálà ọrọ̀-ajé àti ètò-ìṣèlú jákè-jádò àwọn yàrá-ìròyìn nílẹ̀ Yúròòpù.

Pẹpẹ fún adarí-ọkùnrin: Bí ìkànnì-ìbánidọ́rẹ̀ẹ́-ojú-ìwé-àgbáyé àti ìkànnì ayélujára Gúgù ṣe di méjì pàtàkì nínú àwọn olùṣèrànwọ́-owó fún iṣẹ́-ìròyìn lágbàáyé.

Àyípadà ètò-ìṣúná tó ti dé bá iṣẹ́-ìròyìn.

Òpin iṣẹ́-ìròyìn Oníwàádìí rèé bí? Kò tíì yá.

Ìrànwọ́ fún Iṣẹ́-ìròyìn tíkò-rọọgbọ̀kú lé ìjọba jẹ́ ọ̀nà-àbáyọ kúrò lọ́wọ́ ìṣòro Ìròyìn èké (pẹ̀lú àbọ̀ lórí iṣẹ́-ìròyìn oníwàádìí tí à ń ṣèrànwọ́-owó fún).

Ìpèníjà nínú iṣẹ́-ìròyìn ti di ìpèníjà ìjọba-alágbádá

Àwọn ìṣòro oríṣìíríṣìí ìkànnì-ìbánidọ́rẹ̀ẹ́-ojú-ìwé-àgbáyé kò ṣeé fi wé èyí tó ri bọ̀ wá dé bá àwọn agbéròyìnjáde orí-ìkànnì-ayélujára.

Àjàkálẹ̀-àrùn COVID-19 tún gbé ìṣòro tó ń dojúkọ ìmúwàláàyè ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbé-ìròyìn-jáde ní Gúúsù Ilẹ̀-Adúláwọ̀.

Oṣù méjì; Ìdá ọgbọ̀n nínú àròpín ọlọ́gọ́rùn-ún (30%) èlé ìdíyelé àti ẹgbẹ̀rún méjìdínlógún àwọn olùkà tó ń sanwó: Ohun tí “eldiario.es” ṣe lẹ́yìn tí COVID-19 jà nìyí.

Ǹjẹ́ àwọn òfin iṣẹ́-ìròyìn tíkò-fi-tèrè-owó-ṣe tó ti wà nínú ìwé báyìí ran àwọn àjọ-oníròyìn lọ́wọ́ ní Kánádà bí?

Aṣáájú kan nínú ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbé-ìròyìn-jáde tún gbìyànjú pẹ̀lú àjọṣepọ̀ iṣẹ́-ìròyìn tuntun.

Ṣíṣiṣẹ́ lórí ìmọ́n-ọ́n-ṣe ọdún mẹ́wàá, ilé-iṣẹ́-ìròyìn “Tribune” tó wà nílùú “Texas” fẹ́ẹ́ kọ́ ọ ni ẹ̀kọ́ ọgbọ́n tá à ń gbà pawó wọlé.

A ti ṣàgbéró àjọṣepọ̀ orílẹ̀-èdè láti fi okun kún okun iṣẹ́-ìròyìn tíkò-fi-tèrè-owó ṣe ní orílẹ̀-èdè Jámínì.

Àwọn Àròkọ tó jọra wọn 

Ìkọ́ni àti Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ 

Ìròyìn lórí Àmọ̀ràn ní ṣókí àti àwọn ohun èlò 

Àwọn ohun èlò COVID-19 

Àwọn ọmọ Ẹgbẹ́ GIJN 

Ìkànsíraeni àti ìbáṣepọ́

Fífi ènìyàn ṣòwò, iṣẹ́ kà ń pá àti fífi ènìyàn ṣòwò ẹrú 

Àmìn Ẹ̀yẹ

Ìkówójọ 

Nípa ìkànnì ìranlọ́wọ́ GIJN 

Ìpín, Ìgbé lárugẹ àìfíkítà

NÍPA ÌKÀNNÌ ÌRANILỌ́WỌ́ GIJN 

NÍPA GIJN 

GBÍGBÁRÚKÙÙ TÍ GIJN