Ìkówójọ-Orí-Ìtàkùn-Ayélujára

Ohun Kíkà Pàtàkì

Iṣẹ́-ìwádìí “GIJN” ṣàgbékalẹ̀ àwọn ìtalólobó lórí ọ̀nà tí a lè gbà gbé ìpolongo ìkówójọ orí-ìtàkùn-ayélujára, àwọn orúkọ orílẹ̀-èdè àti ẹkùnjẹkùn tó jẹ mọ́ ìkànnì ìkówójọ orí-ìtàkùn-ayélujára, àbá lóri àwọn ohun-èèlò pàtàkì láti lò. Àti ọ̀rọ̀ nípa àwọn tó ti ṣe é.

Ní ìpàdé-àpérò ọdún 2019 ní Hamburg “Tame Bodeky” ti “Atlatszo” ní “Hungary” ṣàlàyé lórí ìmọ̀ràn méje (wo ìwé-ìtalólobó rẹ̀)

  1. Ṣàgbékalẹ̀ onírúurú ìkànnì àti ojú-òpó láti máa gba ìrànwọ́.
  2. Ní àfojúsùn ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ìrànwọ́ kékéèké.
  3. Ní àwọn orílẹ̀-èdè tí kò tíì gbòmìnira, àwọn ènìyàn fẹ́ràn láti máa ṣèrànwọ́ láìdá orúkọ wọn.
  4. Ọjà títà máa ń ṣókùnfà ìkówójọ-orí-ìtàkùn-ayélujára.
  5. Polówó ìkówójọ-orí-ìtàkùn-ayélujára rẹ dáradára.
  6. Ṣàgbékalẹ̀ ohun-tuntun panilẹ́rìn-ínn, kí o sì kọjú sọ́nà nínú àwọn ìpolongo ìkówójọ-orí-ìtàkùn-ayélujára rẹ.
  7. ṣàgbéyẹ̀wò ohun tó ṣiṣẹ́ àti èyí tí kò ṣiṣẹ́.

Fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ àlàyé, kàn sí ojú-ìwé orísun-ìmọ̀ GIJN

Ìkówójọ Orí-ìtàkùn-Ayélujára fún àwọn onìròyìn

  • Àwọn ìtalólobó fún ìkówójọ-orí-ìtàkùn-ayélujára.
  • Àwọn ìkànnì-ayélujára-ìkówójọ-orí-ìtàkùn-ayélujára lágbàáyé.
  • Àwọn ìkànnì-ayélujára-ìkówójọ-orí-ìtàkùn-ayélujára ẹlẹ́kunjẹ̀kùn
  • Ẹ̀kọ́ àti àwọn ìtọ́sọ́nà fún ìkówójọ-orí-ìtàkùn-ayélujára.
  • Àwọn ohun-èèlò ọ̀fẹ́ fún ìpolongo ìkówójọ-orí-ìtàkùn-ayélujára.

Ohun tó yẹ kó o mọ̀ kí o tó bẹ̀rẹ̀ ìpolongo ìkówójọ-orí-ìtàkùn-ayélujára Àjọ Iṣẹ́-ìròyìn Yúróòpù.

A ni àwọn ìpolongo ìkówójọ-orí-ìtàkùn-ayélujára mẹ́rin tó ṣe àṣeyọrí: Èyí ni àwọn ìtalólobó mẹ́wàá fún yàrá-ìròyìn rẹ.

Ìkówójọ-orí-ìtàkùn-Ayélujára: Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀-Abójú-ayé-mu.

Bí àwọn Ajábọ̀-ìròyìn ṣe pa mílíọ̀nù méjì àti ààbọ̀ dọ́là wọlé ní ọjọ́ mọ́kàndínlọ́gbọ̀n pẹ̀lú ìkówójọ-orí-ìtàkùn-ayélujára. 

Iṣẹ́-ìròyìn Àjọṣe

Ìkànnì iṣẹ́-ìròyìn ìkówójọ-orí-ìtàkùn-ayélujára tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ “hottest media industry tech” tí “Nz Marketing Magazine” dá sílẹ̀ ní “New Zealand Herald”

Ìkànnì máa ń ṣàmúlò àwárí-ìrànwọ́-ayélujára láti ṣèrànwọ́ owó fún iṣẹ́-ìròyìn níbi tí òmìnira ìròyìn ti ní àkùdé.

Àgbéyẹ̀wò iṣẹ́-ìròyìn kòlóḿbíà.

Lẹ́yìn àṣeyọrí ìkówójọ-orí-ìtàkùn-ayélujára àká “Swiss Magazine Republic”kọ́ọ̀sì kan lòri “àtúngbá pé iṣẹ́ ṣíṣe kan ni iṣẹ́-ìròyìn” Nieman Lab.

Ní Ítálì, “II Giornale” ń ṣe ìkówójọ-orí-ìtàkùn-ayélujára láti ṣèrànwọ́-owó fún ìjábọ̀ rẹ̀ kúrò lọ́wọ́ ìkùnsínú agbègbè.

Ilé-iṣẹ́ ìwé-ìròyìn “Guardian” ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà pa ju ẹgbẹ̀rún lọ́nà àádọ́ta dọ́là lọ nínú ìpolongo ìkówójọ-orí-ìtàkùn-ayélujára rẹ̀ lóri titalẹ̀ tí kìí ṣe taládàáni.

Ìpolongo ìkówójọ-orí-ìtàkùn-ayélujára “OCCRP

  • Àwọn Àkànṣe Àkòrí: Èto-ohùn-kíkọsílẹ̀. 

Àwọn Ọ̀nà mìíràn térè ń gbà wọlé: Ètò-ohùn-kíkà-sílẹ̀

Àwọn ọ̀nà mẹ́jọ tí àwọn atẹ̀wé-ìròyìn-jáde ń gbà rí owó láti ara ètò-ohùn-kíkásílẹ̀

Atọ́nà Òǹtẹ̀wé-ìròyìn-jáde sí ètò ohùn-kíkàsílẹ̀ ṣèjábọ̀ gbígbàwọlé.

Rédíò àti Ọ̀nà-ìfúnnilówóṣòwò Àkásílẹ̀-ohun ṣíṣàwárí àwọn Ènìyàn àwùjọ tuntun láti inú àwọn ìkànnì Àtijọ́.

Ọjọ́-iwájú ètò-ohun-kíkásílẹ̀ ni ìsanwó-àjọsọ. Àwọn ẹ̀kọ́ láti inú ìtàn àjọ-agbéròyìn-jáde.

Bí ilé-iṣẹ́-ìròyìn “Guardian” ṣe ń mú kí ọ̀nà-ohùn-kíkásílẹ̀ pawó wọlé.

Pẹ̀lú ìfẹ́ràn ńlá (ìràwọ̀) àti owó-àjọsọ sísan. Àwọn Àfojúsùn Aléwájú fún “Netflix” lórí ọ̀nà-ohùn-kíkásílẹ̀

Ọ̀rọ̀-okòwò fún àgbàsílẹ̀.

Ìfowógbawọlé mílíọ̀nù mẹ́wàá fún akọ́ni ọ̀nà-ohùn-kíkásílẹ̀ oníwàádìí.

Àwọn ọ̀nà méje  pẹ̀lú ìdí tí o fi gbọ́dọ̀ kọbi ara sí ọ̀nà-ohùn-kíkásílẹ̀.

Pípawó wọlé láti ara ọ̀nà-ohùn-kíkásílẹ̀

  • Àwọn Àkanṣe Àkòrí: Owó-sísan Alábọ́lé. 

Àwọn ọ̀nà mìíràn térè ń gbà wọlé: owó-sísan-Alábọ́dé.

Ìdí tì owó-sísan alábọ́dé kò fi tíì kú …báyìí.

Bí o ṣe le jẹ́ kí àwọn olùkà ìgbàlódé rẹ fẹ́ láti sanwó – láti owó-sísan alábọ́dé sí owó-àjọsọ ìkànnì ìbánidọ́rẹ̀ẹ́ “Global Editors Network”

Ní Winnipeg, owó-sísan-alábọ́dé kò fi bẹ́ẹ̀ pa owó ńlá, ṣùgbọ́n wọ́n dúró gẹ́gẹ́ bíi ọgbọ́n-inú tó ṣe pàtàkì.

Gẹ́gẹ́ bí ìyípadà nínú àwọn ìgbà, àwọn atẹ̀wéjáde náà ti tún ń yí padà sí owó-sísan-alábọ́dé.

  • Àwọn Àkànṣe Àkòrí: Ọ̀nà-ìsanwó-látẹ̀jáde nínú ọ̀nà-ìpààrọ̀-owó-lọ́nà-ìgbàlóde àti ìpààrọ̀-owó-lọ́nà-ìgbàlódé.

Ọ̀nà mìíràn térè ń gbà wọlé: Ọ̀nà-ìsanwó latẹ̀yìnwá-nínú-ọ̀nà-ìpààrọ̀-owó-lọ́nà-ìgbàlódé àti ìpààrọ̀-owó-lọ́nà-ìgbàlódé.

Àjọ agbéròyìn-jáde àti ọ̀nà-ìsanwó látẹ̀jáde nínú ọ̀nà ìpààrọ̀-owó-lọ́nà-ìgbàlódé-ẹ̀pọ́n ni tàbí ìrètí?

Ǹjẹ́ ọ̀nà-ìsanwó-látẹ̀yìnwá-nínú-ọ̀nà-ìpààrọ̀-owó-lọ́nà-ìgbàlódé gba iṣẹ́-ìròyìn sílẹ̀ bí?

Àwùjọ fẹ́ ta ọ̀nà-ìpààrọ̀-owó-lọ́nà-ìgbàlóde tí iye rẹ̀ jẹ́ òbítíbitì mílíọ̀nù dọ́là láti ṣàtìlẹyìn fún ìkànnì àgbáyé àwọn yàrá-ìròyìn.

Ọ̀nà-ìsanwó-látẹ̀yìnwá nínú ọ̀nà-ìpààrọ̀ owó-lọ́nà-ìgbàlódé – ó ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ ni ṣùgbọ́n kò tíì pẹ́ fún àwọn òǹtẹ̀wé-ìròyìn-jáde náà kó ipa nínú rẹ̀.

Ó dìgbà, “Denver Post”, báwo ni, ọ̀nọ̀-ìsanwó-látẹ̀yìnwá-nínú-ọ̀nà-ìpààrọ̀-owó-lọ́nà-ìgbàlódé.

Ọ̀nà-ìsanwó-látẹ̀yìnwá-nínú-ọ̀nà-ìpààrọ̀-owó-lọ́nà-ìgbàlódé: kín ni ipa rẹ̀ lòrí àjọ onìròyìn?

Àjọ “Blockchain Media Firm Civil” ṣàgbéjáde yàrá-ìròyìn láti kọ́ ọjà-ìta-gbangba fún àwọn oníròyìn.

Ọ̀nà-ìpààrọ̀-owó-lọ́nà-ìgbàlódé fún iṣẹ́-ìròyìn oníwàádìí ṣàgbéjáde “ICO”

Ọ̀nà-ìsanwó-látẹ̀yìnwá-nínú-ọ̀nà-ìpààrọ̀-owó-lọ́nà ìgbàlódé fún iṣẹ́-ìròyìn: Bí àbá ìrànwọ́-owó-ńlá ṣe ń bẹ̀rẹ̀ kékeré.