Ìgbìmọ̀ tó ń rí sí ètò ẹ̀kọ́ iṣẹ́ ìròyìn lágbàáyé: 

Àpèjúwe àti àwọn ètò ẹ̀kọ́ lórí iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn [Ní sísẹ n tẹ̀lé álífábẹ́ẹ̀tì orúkọ àwọn Fáṣítì gbogbo àti àwọn Ọ̀jọ̀gbọ́n]. 

Aligọ́rídìmù fún àwọn Oníròyìn 

Àkànṣe iṣẹ́ sílábọ́ọ̀sì tí aligọ́rídìmù, èyí tí onímọ̀ nípa ìròyìn tó jọ mọ́ ìṣirò Jonathan Stray, ti ilé ẹ̀kọ́ iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ wá ní ìlú ńlá Columbia kọ́. Ó tún wà ní ìkànnì Github níbi tí ẹ yóò ti ní àǹfààní sí ìfàwàránhàn, àwọn ohun èlò ìkàwé, àti àwọn iṣẹ́ ìdárayá. 

Ní lọ́kàn wí pé kíláàsì yìí wá fún àwọn ìpẹ́ẹ́ẹ̀rẹ́ ní ipele ètò ẹ̀kọ́ Python.