Iṣẹ́ ọwọ́ fún ṣíṣe iṣẹ́-ìròyìn aṣèwádìí le súni nípa onírúurú ìfikọ́ra. Ohun èlò yìí sọ só àìmọye ìpèníjà tí àwọn aládàáṣe kojú àti àwọn àjọ ilé-iṣẹ́ òròyìn tí ṣe àtẹ̀jáde àti ìfọ́nká ìwádìí. Ẹ tún wo àwọn ohun èlò tó níṣe lórí ìlọ́wọ́sí àwọn olùwòran àti ìṣàfihàn ipa, èyí ẹ le rí nínú GIJN Sustainability Resource Center.
Àwọn Ohun Èlò fún Àjọ
- Ìbádòwòpọ̀-ọ̀rẹ́ àti Ìfọwọ́sowọ́pọ̀
- Àtẹ̀jáde Ìtàn-kan náà sí ọ̀pọ̀ Ìwé-ìròyìn
- Mímútóbi ẹ̀rọ ìtàkùn ayélujára ní yàrá-ìròyìn rẹ
Ìfọ́nká àti Ìdáṣe
- Ríró-ohùn àwọn Ìtàn Aṣèwádìí
- Ríró-ohùn lásìkò Ìtànkálẹ̀ ààrùn
- Níbi tò yẹ ká ti rò-ohùn
- Níbi tí a ti le gbà Owó-ìrànwọ́
- Àdéhùn
- Ìsedúró tó léwu
- Isedúró Ìnáwó Ilé-iṣẹ́ tó ń gbé ìròyìn jáde
- Ààbò àti Àìléwu
- Ìkànnì Àtẹ̀jáde-ara-ẹni.
Ǹjẹ́ ẹ ri wí pé ó wúlò? Bẹ́ẹ̀ni Bẹ́ẹ̀kọ́