Ìdásí Àwùjọ àti Ọ̀nà-Tówó-ń-gbà-wọlé.

Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀-Abójú-ayé-mu

Ohun-èèlò ọmọ-ẹgbẹ́ 101: Ṣégeṣège

Ìtúpalẹ̀ rẹ, kí o sì gùnlé ìrólágbára-ètò àkójọpọ̀-fáyẹ̀wò fún ìjọ́mọ-ẹgbẹ́

Agbára ìgbóhuntuntunjáde nínú iṣẹ́-ìròyìn ọlọ́gbọnrangandan lórí ìtàkùn-àgbáyé: Àwọn àpẹẹrẹ márùn-ún tó peregedé.

Iṣẹ́-ìwádìí àwùjọ ní pèpéle tó ga jù lọ. Bí a ṣe ń lò ó – àti ohun tí a kò lérò kó ṣe fún wa.

Àròjinlẹ̀ tó gúnrégé: Bí àwọn atẹ̀wétà ṣe máa ń ṣàmúlò èrògbà ọmọ-ẹgbẹ́ láti ṣàfihàn ìpéye àti láti ṣàwárí ìròyìn.

Àwọn àlàálẹ̀ láti sọ àfojúsùn wa dòótọ́: Àgbeyẹ̀wò ipa ojú-àmúwayé ìlú.

Ǹjẹ́ ìròyìn alátẹ̀jíṣẹ́ le ṣiṣẹ́ bí? Bébà Tuntun ti Ìǹdìánà rò bẹ́ẹ̀.

“Bí a bá rọ́mọ-ẹgbẹ́ ẹgbẹ̀rún méje, ayé wa ti dára”  Bí ilé-iṣẹ́-ìròyìn “Daily Maverik” ṣe ṣàgbékalẹ̀ ètò ìjọ́mọ-ẹgbẹ́ rẹ̀

Àwọn ẹ̀kọ́ àti ìkíyèsára láti inú ìrírí àádáje ọdún ti ìjọ́mọ-ẹgbẹ́ nípele orílẹ̀-èdè  Eré-ìdárayá- ìrújú ìjọ́mọ-ẹgbẹ́

Darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́: Bí àjọ̀dún àwọn tó ní ìgbóná-ọkàn àti àwọn aláfọwọ́sowọpọ̀ ṣe ń ran ìgbéró iṣẹ́-ìròyìn lọ́wọ́ Ǹjẹ́ àwọn aláfọwọ́sowọ́pọ̀ ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbé-ìròyìn-jáde ní àwòṣe òwò lọ́jọ́ iwájú bí?

Àdàlú: àkójọpọ̀ àfojúsùn ìkànnì ìròyìn ní Éṣíà, faramọ́ ìdàgbàsókè díẹ̀díẹ̀ àti mímọ àwùjọ rẹ̀

Àwọn oníròyìn agbóhuntuntunjáde “ibero-America” nínú àgbéjáde àkóónú nípa lílo ìmọ̀-ẹ̀rọ tuntun àti ojúnà láti ṣàgbékalẹ̀ àwùjọ.

Ìyapa: “De Correspondent” ń bọ̀ ní Amẹ́ríkà pẹ̀lú  ète ìgbóhuntuntun jáde lórí ìsanwó fún àkóónú

Ohun mẹ́rin tí “HBR” ti kọ́ nípa àgbéyẹ̀wò ìdásí àwùjọ

Bí ìkànnì ìròyìn Abẹ́lẹ́ “Berkeleyside”  ṣe kó Mílíọ̀nù Dọ́là kan jọ Látàrí Ọ̀rẹ Àwùjọ Tààrà.

Àjọṣepọ̀ pẹ̀lú ọmọ-ẹgbẹ́ rẹ̀, Àjọ fẹ́ ṣe àfihàn pé ìrànwọ́-olùkà ṣe pàtàkì fún iṣẹ́-ìròyìn ní “Switzerland”

Nípa àtẹ̀jíṣẹ́-gbogbogbò-abẹ́lẹ́, “Outlier Media” so ìròyìn tíkò-lérè-púpọ̀ lórí pẹ̀lú àkójọpọ̀ fáyẹ̀wò tó wúlò tó sì jẹ́ tara-ẹni

Bí “vox” se ṣàmúlò àwọn ẹgbẹ́ ìkànnì-ìbánidọ́rẹ̀ẹ́-ojú-iwé-àgbáyé láti ṣàgbédìde Àwùjọ tirẹ̀.

“Politifact” kó ẹgbẹ̀rún márùn-lé-lọ́gún-rùn-ún Dọ́là jọ ní ogúnjọ́ péré látàrí àgbéjáde tuntun ètò ìjọ́mọ-ẹgbẹ́ rẹ̀.

Àkójọpọ̀ yóò pèsè pèpéle láti ṣàgbéyẹ̀wò àwọn ìbéèrè tó níi ṣe pẹ̀lú ìdásí àwùjọ

Bí “De Correspondent” ṣe tọ́ àwọn òǹkọ̀wé rẹ̀ sọ́nà láti ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú àwọn olùkà àti láti máa ṣíṣẹ́ bí adarí ìjíròrò”

Ìdásí iṣẹ́-ìròyìn tíkò-fi-tèrè-owó-ṣe: Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀-abójú-ayé-mu (ní USA)

Ohun tí àwọn ọmọ-ẹgbẹ́ sọ nípa ìdí tí wọ́n fi ṣàtìlẹyìn fún “De Correspondent”

Ní wákàtí díẹ̀, “Marshall Project” pa owó òbítíbitì ẹgbẹ̀rún wọlé nípa àgbékalẹ̀ ètò ìjọ́mọ-ẹgbẹ́ rẹ̀ tuntun

Ilé-iṣẹ́-ìròyìn “The Atlantic” ṣàgbéjáde ètò ìjọ́mọ-ẹgbẹ́ tó la owó lọ fún àwọn tọ́kàn wọn rọ̀mọ́ọ gidigidi èyí tí ṣe “Masthead”

Bí ilé-iṣẹ́-ìròyìn “Mother Jones” ṣe làlùyọ nínú iṣẹ́-ìròyìn ní ayé àtijọ́: ó bèèrè owó lọ́wọ́ àwọn olùkà

Ìdásílẹ̀ elẹ́kajẹ̀ka: Ìkànnì yìí ń fun olùkà ní àǹfààní láti sanwó fún àkóónú orí ìtàkùn-àgbáyé nípa dídáhùn ìbéèrè

Bí àwọn ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ilé-iṣẹ́-ìròyìn abẹ́lé yìí ṣe dá ẹwù sínú àwọn ọmọ-ẹgbẹ́ rẹ: fífún wọn ní àǹfààní ìdásí nínú àgbéjáde ìròyìn

Ilé-iṣẹ́-ìròyìn “Guardian” ṣàgbéyẹ̀wò ìjọ́mọ-ẹgbẹ́ pẹ̀lú irúfẹ́ yàrá-ìròyìn tó wà lágbàáyé

Ọ̀nà sí mílíọ̀nù kan: ilé-iṣẹ́-ìròyìn “Guardian” ti kọjá láti rí àwọn ọmọ-ẹgbẹ́ tó ń sanwó, láti ẹgbẹ̀rún mẹ́ẹ̀dógún sí ìgbà ẹgbẹ̀rún

Ilé-iṣẹ́-ìròyìn “De Correspondent” ní báyìí ti ni ẹgbẹ̀rún lọ́nà àádọ́ta ọmọ-ẹgbẹ́ tó ń sanwó: ìdojúkọ wa tó peléke jù lọ ní ọdún 2017.

Àwọn àwòṣe iṣẹ́-ìròyìn oníwàádìí tó jẹ mọ́ àwùjọ tí àwọn ará Kánádà ti wá di olórílẹ̀-èdè.

  • Ìdásí Àwùjọ àti Ọ̀nà-tówó-ń-gbà-wọlé: ìwé-ìròyìn

Èyí ni láti mú àwọn olùkà dúró lẹ́yìn àjàkálẹ̀ àrùn “COVID” àwọn atẹ̀wétà rí ìrètí nínú ìwé-ìròyìn àti ìgbóhùn-sáfẹ́fẹ́-orí-ìtàkùn-àgbáyé

Bí “Indiegraaf” ṣe ṣèrànwọ́ láti ṣàgbéjáde ilé-iṣẹ́-ìròyìn mẹ́fà lábẹ́lẹ̀ nígbà COVID-19. Ìwé-ìròyìn ṣe pàtàkì fún ìjólóòtọ́ olùkà. Èyí ni bí a ti jèrè àǹfààní wọn.

Kì í ṣe atọ́ka ìwé-ìròyìn oṣoòṣù

Ọgbọ́n-inú ìfisípò ìwé-ìròyìn ní ṣókí

Bí ìgbóhuntuntunjáde oníwèé-ìròyìn ṣe ń tukọ̀ ìpawowọlé atẹ̀wétà kín ni ohun tuntun nínú ìtẹ̀wétà.

Atọ́ka ọ̀kànlélúgba fún mímú ìwé-ìròyìn rẹ lọsí ìpele tó kàn – ìgbérú iye, owó pípa, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Atọ́ka ìwé-ìròyìn

Bí a ti ń sàlékún ìjágaara ìwé-ìròyìn ìròyìn-tó dára (Better news)

Bí àwọn tó ń tẹ ìwé-ìròyìn jáde ṣe ń ṣe àgbàwọlé padà àwọn asanwó-àjọsọ ti sáà wọn ti tan “Digiday”

Gbigbé ìròyìn orí-ìtàkùn-àgbáyé hàn gbangba dé méjìdínlọ́gọ́rin nínú àròpín-ọlọ́gọ́rùn-ún “Digital Content Next”

Ìdásí ọgbọ́n-inú-ìwé-ìròyìn láti mú ìdàgbàsókè bá àwùjọ àti olùkà “Medium”

Bí o ṣe le bẹ̀rẹ̀ ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbé-ìròyìn-jáde oníwèéròyìn tirẹ̀

Àwọn ẹ̀kọ́ mẹ́fà nípa ìtàkùn-àgbáyé àti àwùjọ lórí ìdágbàsókè fún ìròyìn tíkò-fi-tèrè-owó-ṣe

Àwọn àfojúsùn tó sọrọ́ sọdòótọ́ ìtàkùn-àgbáyé: ohun tí àtúpalẹ̀ ẹgbẹ̀rún-kan-lé-lọ́ọ̀ọ́dúnrún ìwé-ìròyìn ajẹmọ́ṣẹ̀lẹ̀ kọ́ wa.

Ilé-iṣẹ́-ìròyìn “The Wall Streer Journal” ṣe ń sọ ìwé-ìròyìn rẹ̀ dọ̀tun-tó sì ń gbìyànjú láti ṣàfihàn ọ̀pọ̀ àdídùn.

Ìwé-ìròyìn “Best Media”

Ìdí tí ilé-iṣẹ́-ìwé-ìròyìn “The New York Time” ṣe fẹ́ràn ìwé-ìròyìn pélébépélébé.

Èyí ni ohun tí o gbọ́dọ̀ mọ̀ láti ṣàgbéró àṣeyọrí ìwé-ìròyìn tí wọ́n ń sanwó fún ìròyìn afolékè, ìwé-ìròyìn ààràárọ̀ àti ìwé-ìròyìn àwùjọ.

Àwọn ìpìlẹ̀ ìwé-ìròyìn: kọ àtẹ̀jíṣẹ́ orí-ìtàkùn-àgbáyé

Lílo irinṣẹ́ àkójọpọ̀-fáyẹ̀wò sáyẹ́ǹsì fún àtúpalẹ̀ àwùjọ orí ìtàkùn-àgbáyé

Ǹjẹ́ Àwọn olóṣèlú ilẹ̀ Bùràsíìlì ni? Pẹ̀lú àtìlẹ́yìn ìròyìn tí-a-sanwó-fún “poder 360” walẹ̀ nínú àgb´ekalẹ̀ agbára orílẹ̀-èdè náà.

Àwọn ẹ̀kọ́ tí a rí kọ́ láti inú ìdàgbàsókè “Vox Media’s Newsletter”

Àgbéró ìwé-ìròyìn gidi

Bí a tíi kọ ìwé-ìròyìn sórí ìtàkùn-àgbáyé tí àwọn ènìyàn àwùjọ yóò fi rí i ká

Àwọn ọ̀nà mẹ́rin tí ìwé-ìròyìn yóò fi di ìlú-mọ̀ọ́n-ká láàrin ìdá àádọ́ta sí ọgọ́ta nínú aròpín ọlọ́gọ́rùn-ún

Èyí ni àbá méjìlélógójì fún ìwé-ìròyìn ọjọ́-iwájú ní yàrá-ìròyìn rẹ.

Ohun kan tí gbogbo àwọn ilé-iṣẹ́-ìròyìn ìgbàlódé alábẹ́lé nílò ni ìwé-ìròyìn ìgbàlódé

Lílo irinṣẹ́ àkójọpọ̀ fáyẹ̀wò sáyẹ̀nsì fún àtúpalẹ̀ àwùjọ orí ìtàkùn àgbáyé: ìtọ́ka iṣẹ́-ìwádìí 

Ó fẹ́ bẹ̀rẹ̀ sí ní tẹ ìròyìn jáde bí? Kọ́kọ́ ka èyí ná. Atọ́ka NPR lórí ìyàwòrán, ọdún 2016

Ìdásí Àwùjọ àti ọ̀nà-tówó-ń-gbà-wọlé: Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀

Ọ̀nà Ìgbàlejò àti agbátẹrù ìdásí ìṣẹ̀lẹ̀ tó nítumọ̀ Todd Milbourn àti Lisa Heyanioto

Àwọn ìtalólobó àwọn ètò-oníran èyí tó ṣàtìlẹyìn fún iṣẹ́-ìròyìn

Bí a ṣe le ṣàgbejáde òwò aláyẹyẹ tó gúnrégé

Bí a ti ń ṣàmúlò iṣẹ́-ìròyìn àwùjọ àti àwọn ètò ìtàn-sísọ láti fa ojú àwọn ọlọ́rẹ mọ́ra fún iṣẹ́ tíkò-fi-tèrè-owó-ṣe

Ilé-iṣẹ́-ìròyìn “The New York Time” ń ṣe àgbékalẹ̀ ìpè-ẹ̀rọ-ìbániṣọ̀rọ̀ fún ìpàdé-àpérò pẹ̀lú àwọn asanwó-àjọsọ, èyí tó fẹ́ dàbí ètò-orí-rédíò.

Bí ilé-iṣẹ́ ìwé-ìròyìn kan ṣe ṣàgbéjáde ètò-ráḿpẹ́ orí-ìtàkùn ayélujára láti ṣe alékún ọjà títà rẹ̀.

Gbígbé iṣẹ́-ìròyìn hàn gbangba: Bí ètò ìròyìn ṣe ń ṣòkùnfà ìdásí àti àlékún ọ̀nà-tówó-ń-gbà-wọlé.

Bí yàrá-ìròyìn tíkò-fi-tèrè-owó-ṣe ní “New York” ṣe pa ẹgbẹ̀rún méje-lé-lọ́gọ́rùn-ún Dọ́là wọlé pẹ̀lú ìlù lílù àti àwòrán oríṣìíríṣìí eré-ọmọdé.

Ọ̀nà-tówó-ń-gbà-wọlé-Ajẹmówò: Ohun Kíkà Pàtàkì

Èrè tó ń wọlé látara òwò máa ń gba oríṣìíríṣìí ọ̀nà, ó sì le jẹ́ àlékún ìrànwọ́ fún àwọn àjọ iṣẹ́-ìròyìn tíkò-fi-tèrè-owó-ṣe tàbí ìrànwọ́ pátápátá. Èyí tó le jẹ́: Ìpolówó-ọjà àti ìsanwó-àjọsọ, pẹ̀lú àwọn mìírà-n náà:

Ìròyìn ìgbóhuntuntunjáde ìkànnì-àgbáyé (Google) àti INN gbé Atọ́ka fún ìròyìn tíkò-fi-tèrè-owó-ṣe jade lórí owó-tó-wọlé: Ìwé-iléwọ́ ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ tó ṣàfihàn bí a ṣe le ní owó-tó-ń-wọlé ni `lékún pẹ̀lú ète ìpolówó-ọjà fún àwọn yàrá-ìròyìn àtilẹ́yìn àkóónú pẹ̀lú àwọn owó tí a pa wọlé mìíràn.

Bí a ṣe le ṣàgbéyẹ̀wò Ọ̀nà-tówó-ń-gbà-wọlé-ajẹmówò gẹ́gẹ́ bí ọgbọ́n-inú fún ìmúdúró àwọn àjọ ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbé-ìròyìn-jáde oníwàádìí láti ọwọ́ Ross Settles olùrànlọ́wọ́ ọ̀jọ̀gbọ́n pẹ̀lú àfojúsùn lórí iṣẹ́-ìròyìn ìgbàlódé àti ète-òwò ní Àjọ Èkó iṣẹ́-ìròyìn àti ìtẹ̀wéròyìn-jáde ti “Hong Kong University”

Ète-òwo iṣẹ́-ìròyìn Ọ̀fẹ́ lórí ìkọ́ni àti ìkẹ́kọ̀ọ́

Ohun-èèlò-irinṣẹ́: (wo àlàyé láti ọwọ́ Jeremy Caplan, Adarí Ètò-ẹ̀kọ́. Àjọ “Tow-Knight” fún Ète-òwò iṣẹ́-ìròyìn, “City University of New York)

Àwọn Ọ̀nà tuntun fún àwọn atẹ̀wétà láti ṣàwárí ọ̀nà-tówó-ń-gbà-wọlé ìgbàlódé.

Ọjọ́-ìdájọ́ fún iṣẹ́-ìròyìn: Ǹjẹ́ àwọn ìdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́- ìròyìn ìgbàlódé yóò múra de ìdojúkọ bí?

Ohun-èèlò fún Ìpowówọlé olùkà: orísun-ìmọ̀ pẹ̀lú ìwé àpilẹ̀kọ lórí oríṣìíríṣìí àkọlé èyí tí ilé-ẹ̀kọ́ ìròyìn Amẹ́ríkà gbé kalẹ̀.

Ọ̀nà-tówó-ń-gbà-wọlé-Ajẹmówò

Bí iṣẹ́-ìròyìn ṣe le di títúsílẹ̀ kúrò lọ́wọ́ àwọn aàwòṣe aṣèrànwọ́ ajẹmówò

Ìjà lemọ́lemọ́ láàrin ilé-iṣẹ́ ohun-amáyédẹrùn “Apple” àti ìkànnì-ayélujára “Google” le nípa lórí àwọn atẹ̀wétà ìròyìn náà pẹ̀lú.

Atọ́ka tó wúlò fún àwọn àjọ ìròyìn tó níí ṣe pẹ̀lú àwọn àǹfààní ìpawówọlé ní ẹgbẹ́ kéréje pẹ̀lú ìkópa iṣẹ́-ìròyìn.

Bi “The Washington Post’s User Lab” ṣe jẹ́ kí ìbéèrè olùpolówó-ọjà àti asanwó-àjọsọ gúnrégé Digidan

Ohun tó túmọ̀ sí láti sọ ajọ ìròyìn di ọ̀nà ìpawówọlé fún olùkà. Ilé-ẹ̀kọ́ ìròyìn Amẹ́ríkà: Atọ́ka kékeré fún ọgbọ́ndàá fún ìyanjú ìṣòrò tó máa ń yọjú nígbà tí a bá ń ṣàgbéró ètò ìsanwó-àjọsọ.

Àtẹ-iṣẹ́ àti ẹ̀kọ́ fún ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbé-ìròyìn-jáde lórí owó-ìbẹ̀rẹ̀-okòwò Àgbéyẹ̀wò iṣẹ́-ìròyìn kòlòḿbíà.

Ilé-iṣẹ́ ohun-amáyédẹrùn “Apple” ń bá àwọn ilé-iṣẹ́ ìwé-ìròyìn ńlá-ńlá sọ̀rọ̀ lórí dídarapọ̀ mọ́ àwọn tó ń kópa nínú ọ̀rọ ìsanwó-àjọsọ rẹ̀ “Recode”

Àwọn ọ̀nà tuntun fún àwọn atẹ̀wétà láti jẹ̀gbádùn ípawówọlé ìgbàlódé.

Ọ̀nà tí a fi ń ṣe àgbéjáde ẹ̀kọ́ orí ìkànnì-ayélujára tó lérè nígbà tí ò ń ṣe ìgbédìde Àwùjọ rẹ.

Àwọn ọ̀rọ̀ tí kò yẹ kóníròyìn sọ ní gbangba ṣùgbọ́n tí wọn yóò sọ láìtijú.

Ìdìde ìmọ̀-ẹ̀rọ ti lànà fún iṣẹ́-ìròyìn tó lérè nípa sísṣ ọ́ di Tara-ẹni.

Kò sowó tí à ń fi ṣòfò: Àlékún owó tí atẹ̀wétà ń pa wọlé kì í sáábà dá dọ́là tó ti sọnà padà

Ọ̀pọ̀ ènìyàn ti wá-ń-sanwó fún àkóónú báyìí. Báyìí ní àwọn atẹ̀wétà ṣe ń fowó dókòwò.

Àbá tí kò mọgbọ́n wá fún ìṣèrànwọ́-owó fún ìròyìn abẹlé: Díyelé àwọn ènìyàn fún un.

Gẹ́gẹ́ bí àwọn àjọ ìròyìn ṣe ń gbìyànjú láti polówó-ọjà lágbàáyé, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ń tẹpẹlẹ mẹ́ olùkà kọ̀ọ̀kan.

Àwọn àjọ ilé-iṣẹ́-ìròyìn tí a dá sílẹ̀ àti orí-pápá-iṣẹ́-ìwádìí iṣẹ́-ìròyìn

Àwọn àǹfààní fún ìdásílẹ̀ oríṣìíríṣìí nínú àwọn àjọ tuntun.

Ìbáṣepọ̀ ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbé-ìròyìn-jáde pẹ̀lú aṣèrànwọ́-owó VC

Ìdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbé-ìròyìn-jáde:  Àwọn oníròyìn di aṣòwò láti ṣàwárí iṣẹ́-ìròyìn tó peregedé.

Bí “Buzzfeed “ ṣe ń ṣàgbéró àwòṣe ìpawwówọlé olóríṣìíríṣìí ọ̀nà èyí tí kò farati ìkànnì-ìbánidọ́rẹ̀ẹ́-ojú-ìwé-àgbáyé.

“Jeff Bezos” ní ìmọ̀ràn fún okòwò ìròyìn: “Ẹ sọ fún àwọn ènìyàn kí wọ́n sanwó. Wọn yóò san án”

Taa ni ó ní afọ kàntàn tó sì ń sanwó fún ìròyìn.

Martin Baron: “Ìṣẹ̀lẹ̀ okòwò kán wà fún àfikún ìṣẹ̀lẹ̀ ẹ̀kọ́ fún iṣẹ́-ìròyìn oníwàádìí.