Ìdáṣe:Àdéhùn àti Ìdúnàádúràá

Àwọn Èrò Oní-àdéhùn

Ìdúnàádúràá Àdéhùn fún Átíkù Oníwàádìí gbọ́dọ̀ bo onírúurú ìṣòro tí kò fi bẹ́ẹ̀ yẹ fún, sọ pé àbùdá nípa ọmọ ọlọ́ńgbò tó rẹwà.

Àwọn kókó kan tó kárí-ayé tí kò wọ́pọ̀ wà ní èyí tóyẹ kí á gbájú mọ́, pẹ̀lúpẹ̀lú:

  • Àlàyé ipa iṣẹ́ àti bí wọn yóò ṣe fọwọ́ mú àyípadà.
  • Ọ̀nà Ìsanwó.
  • Ẹni tí ó ni ẹ̀tọ́.

Fún iṣẹ́-ìròyìn oníwàádìí, àwọn àkòrí kan wa tí ó lẹ́tọ̀ọ́ sí ìpàkíyèsí kan pàtó:

  • Bí wọ́n ṣe le sanwó fún ọ dáadáa fún iṣẹ́-àkànṣe ńlá.
  • Mímú àwọn ẹ̀tọ́ ogún alóye.
  • Bí o ṣe le bo àwọn ìnáwó àìdájú, bí i gbígba àwọn ìwé-àkọsílẹ̀ látara FOIA.
  • Kí ló ṣẹlẹ̀ bí iṣẹ́-àkànṣe kò bá yọrí?
  • Kí ló ṣẹlẹ̀ bí atẹ̀wétà bá pa iṣẹ́-àkànṣe?
  • Àwọn ààbò abófinmu wo ni wọn yóò pèsè fún òǹkọ̀wé? (Wo abala ọ̀tọ̀ lórí media liability insurance.)
  • Bí o ṣe lè fọwọ́ mú ewu ìsedúró tara-ẹni? (Wo abala ọ̀tọ̀ lórí ìsedúró tara-ẹni.)
  • Irú ààbò aláìléwu wo ni wọ́n gbọ́dọ̀ pèsè? (Wo abala ọ̀tọ̀ lórí Aìléwu.)

O Nílò Àdéhùn

Ó ṣeé ṣe kó lọ láìsọ, ṣùgbọ́n o nílò àdéhùn.

Láìsí ìkan, “o ń fi ara rẹ sílẹ̀ sí aìsanwó, gbèsè, àti Àwọn wàhálà amòfin, “ US blogger Ryan Robinson” ṣàtẹnumọ́ ní ìsọníṣókí àwọn ìwúlò níní àdéhùn tó dára.

“O máa nílò Àdéhùn. Níbi ni tèmi. Gbà á!” Aládàáṣe US Jyssica Schwartz kọ ọ́ ní Medium ní ọdún 2018.

Ní ìbanújẹ́, sí bẹ́ẹ̀, fún ọ̀pọ̀ àwọn aládàáṣe, ọ̀rọ̀ “gbà á” wá láti ọ̀dọ̀ atẹ̀wétà, pẹ̀lú “…tábí fi sílẹ̀.”

Ṣùgbọ́n ìdúnàádúràá ṣeé ṣe, tí ó gbilẹ̀ ní ìmọ̀ ti èròjà tí ó lọ sí inú àdéhùn. (Àwọn aládàáni kan ṣedúró kíkọ́ àwọn ìmọ̀ọ́se ìṣedúnàádúràá ìpìlẹ̀.)

Kín ni ó Gbọ́dọ̀ wà nínú Àdéhùn?

Ibi kan tó dára láti bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ni “Model Freelance Publishing Agreement” tí àwọn ACOS Alliance ṣe ìdàgbàsókè rẹ̀, ẹgbẹ́ ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbé-ìròyìn-jáde jákè-jádò àgbáyé tí ó mọ̀ mámọ̀já nínú ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbé-ìròyìn-jáde ọ̀rọ̀ àìléwu, àti “The Cyprus R. Vance Center for International Justice” ní ilẹ̀ New York. Wo ìjíròrò àwọn ọ̀rọ̀ kọ́kọ́rọ́ tó fara pẹ́ ẹ tí wọ́n gbékalẹ̀ ní àjọsọ àwòṣe. (Gbogbo àwọn ìwé-fún-kíkà lókè wà ní èdè Àrábíkìì pẹ̀lú.)

Freelance Investigative Reporters and Editors (FIRE) ṣèdàgbàsókè àjọsọ ìtàn àwòṣe ọ̀fẹ́ fún àwọn oníròyìn olómìnira àti agbéròyìnjáde tó ṣiṣẹ́ pẹ̀lú wọn. Kọ́ si kí o sì bèèrè fún àjọsọ náà níbí.

“FIRE” tún fúnni ni iṣẹ́ òfin tó níṣe pẹ̀lú àdéhùn, gẹ́gẹ́ bí ara èto ìgbaninímọ̀ràn FIRE, tí ó bẹ̀rè ní ọdún 2021 láti ṣe ìrànwọ́ pẹ̀lú àwọn àdéhùn àti ìdáàbò bò olófin. Ẹgbẹ́ tí ó tẹ̀dó sí US pèsè ìráyè sí agbẹjọ́rò wákàtí kan, bí wọ́n ṣe ṣe ọ̀rínkínníwín àlàyé sí inú Legal Assistance. Láti tọ́ fún, “olùbẹ̀wẹ̀ le jábọ̀ láti tàbí gbé ní ibikíbi – ṣùgbọ́n wọ́n gbọ́dọ̀ jẹ́ olùjábọ̀ àdáṣe tí ó ń ṣíṣẹ́ lórí tàbí tí ó ń gbèrò àwọn ìtàn oníwàádìí pẹ̀lú ẹ̀dẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì àwọn agbéròyìnjáde ti U.S.”

FIRE ṣe agbátẹrù ṣẹminá kan pẹ̀lú àwọn olóòtú tó wà lókè ní ọjọ́ kejì-dín-lọ́gbọ̀n osù kẹsàn-án, ọdún 2021, nípa àwọn ọ̀rọ̀ ìṣèdéhùn. Ìgbohùnsílẹ̀ rẹ̀ wà níbí.

Fún Àfikún lóri Ìfọ́nká, Ìgbéga, àti Ìdáṣe, wo Ìtọ́sọ́nà GIJN wa

Mọ̀ wí pé àwọn òdìwọ̀n ìṣàdéhùn máa yàtọ̀ pẹ̀lú àwọn òfin agbára atẹ̀wétà.

Ọ̀pọ̀ ìkànnì ayélujára ló wà pẹ̀lú àwọn àwòṣe àdéhùn tí o le yẹ sí ipò rẹ. Gbìyànjú wíwa pẹ̀lú àwọn kọ́kọ́rọ́-ọ̀rọ̀ bíi “àwòṣe àwọn àdéhùn àdáṣe” tàbí “àjọsọ òǹkọ̀wé àdáṣe” tàbí “àdéhùn ìwé-kíkọ àdáṣe.”

Àwọn kókó kan tó kárí-ayé tí kò wọ́pọ̀ wà ní èyí tóyẹ kí á gbájú mọ́, pẹ̀lúpẹ̀lú:

  • Àlàyé ipa iṣẹ́ 
  • Bí wọn yóò ṣe fọwọ́ mú àyípadà.
  • Ọ̀nà Ìsanwó.
  • Ẹni tí ó ni ẹ̀tọ́.

Ìkàwé Síwájú si:

  • Ìjíròrò Àpapọ̀ lórí àwọn Àdéhùn láti ọwọ́ Canadian Media Guild.
  • Ẹgbẹ́ Àwọn Aládàáṣe, àjọ tí ó dúró fún ẹgbẹ́rùn-ún ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ òṣìṣẹ́ aládàáwà káàkiri ilẹ̀ US, fúnni ní ìmọ̀ràn látara Olùṣẹ̀dá Àdéhùn.
  • The National Association of Science Writers, tí ó tẹ̀dó sí Berkeley, ní California, ní ojú-ewé tó dára l´ri ìdáṣe, pẹ̀lú àlàyé lóri ìdúnàádúràá àdéhùn. Wò ó pẹ̀lú: Ìdúnàádúràá Àdéhùn: Rírí ohun tí o fẹ́ gbà, pẹ̀lú ore-ọ̀fẹ́, ìtọ́jú tó jinlẹ̀ tí wọ́n ṣe ní ọdún 2016 láti ọwọ́ Jennifer Pirtle.
  •  Ẹgbẹ́ àwọn Oníròyìn Aláyìíká, tó tẹ̀dó sí Washington, DC, sopọ̀ mọ́ ọ̀pọ̀ àwọn ohun-èèlò lórí ìdáṣe.
  • Àwọn gbólóhùn ìdánudúrò díẹ̀ tí àwọn aládàáṣe gbọ́dọ̀ mọ̀ (àti dúnàádúdàá), Gẹ́gẹ́ bí àwọn Agbẹjọ́rò ṣe sọ, átíkù ọdún 2018 láti ọwọ́ Maya Kroth ní Àtúngbéyẹ̀wò Iṣẹ́-ìròyìn Columbia.
  • Freelancevoorwaarden.nl (Dutch fún “àwọn ìgbéléwọ̀n àdáṣe”) ní àwọn ohun-èèlò pẹ̀lú àwọn àpèjúwe ti ìlànà àdáṣe ti ìtẹ̀wéjáde ìtẹ̀dó-Dutch. Wo átíkù ọdún 2019 yìí láti ọwọ́ Linda A. Thompson fún “International Journalist’s Network”.

Àmọ̀ràn láti ọ̀dọ̀ Àwọn Àgbà-ọ̀jẹ̀ ní GIJC19

Ìgbìmọ̀ àwọn Àgbà-ọ̀jẹ̀ ní 2019 Global Investigative Journalism Conference ní Hamburg, Germany, sọ̀rọ̀ lórí àkórí rírán àdéhùn ní pàtó fún àwọn oníròyìn oníwàádìí.

Kọ́kọ́rọ́ ìmúlọ kan: sísanwó fún nípa ọ̀rọ̀, nígbà tí ìlànà ìṣiṣẹ́ tó múlẹ̀, le má tọ̀ ọ́ fún pípẹ́, ṣèwádìí iṣẹ́-àkànṣe-tó-wúwo.

Dípò, olùsọ̀rọ̀ ṣèdúró ṣíṣe-ìdúnàádúràá ìdánilójú ọ̀sọ̀ọ̀sẹ̀ tàbí oṣoosù owó-ìrànwọ́ fún ìwádìí àkókò, pẹ̀lú ènì aláìní-ìdánilójú-láti-lọ-tẹ̀wéjáde, gẹ́gẹ́ bí àtúngbéyẹ̀wò abala láti ọwọ́ Rowan Philp ti GIJN.

“O le gbani ní yànjú fún ìhun yìí nípa ṣíṣàlàyé pé kò si owó-ìpani tí yóò wúlò, àti pé o lè ro òfin- àtẹ̀wétà tó ní gbèdéke àti tó rọrùn. Nínú àdéhùn kankan, rí i dájú pé o kò sí lórí ìlà gbèsè,” Philp ló kọ ọ́.

Àwọn ọ̀rínkínníwín àlàyé mìíràn le ṣe pàtàkì, bí i ìgbà tí atẹ̀wétà má a sanwó fún ọ: ìgbà tí wọ́n gba nǹkan náà, tàbí ìgbà mìíràn, lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n tẹ̀ ẹ́ síta.

Ìsanwó tí kì fi tàratara pé ńkọ́ ní wájú bí ó bá ṣeé ṣe kí ìjábọ̀ gba àkókò to gùn tí ó sì mú ìnáwó ti a kò retí dání? Ní ibí yìí, àwọn aládàáṣe kan ṣèdúró bíbèèrè fún ìsanwó “milestone” yára sí ìrígbà àwọn iṣẹ́ ní pàtó. Tí olóòtú bá ka ìtàn rẹ ńkọ́? Ǹjẹ́ o ó gba owó apá kan rárá? Ro ṣíṣe àfikún èdè bí èyí si àdéhùn rẹ:

Bí átíkù kò bá di ìtẹ́wọ́gbà fún ìtẹ̀wéjáde, wọn yóò sanwó fún àwọn olùjábọ̀ “kill fee” ti ìdá márùn-ún dín-lọ́gọ̀rún (25%) ti owó ìpìlẹ̀.

Ro àwọn ìtalólobó wọ̀nyí tó níṣe pẹ̀lú “kill fees”, tí wọ́n mú láti átíkù ọdún 2017 láti ọwọ́ Alexander Cordova:

  • Ṣètò “kill fee” ní iye tó mọ́pọlọ dání. O kò jẹ́ jó bíríjì kankan!
  • Sún owó rẹ tí ó ń níṣe pẹ̀lú iye ìtẹ̀síwájú tí o ti ní lórí iṣẹ́-àkànṣe.
  • Ro fífi àkókò ṣókí sí i lẹ́yìn ìgbà tí o bá bu ọwọ́ lu àdéhùn níbi tí olùbára ti le wọ́gi lé ti ẹ̀ (tàbí obìnrin) ìbéèrè láìsí ìjìyà kankan.

Ìdúnàádúràá Owó fún Àwọn Ìtàn Ńlá

Scott Carney, oníròyìn oníwàádìí àti onímọ̀-ẹ̀dá-ènìyàn tí ó kọ ìwé “Quick and Dirty Guide to Freelance Writing” gbàgbọ́ pé ó ṣeé ṣe láti dúnàádúràá fún èyí tó ga jù ju òsùwọ̀n àárín fún àwọn ìtàn abúramúramù.

Nínú ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nu-wò pẹ̀lú Pacific Standard, Carney sọ pé: 

“Ó jẹ́ ìṣòro ojú-àmúwayé tí àwọn òǹkọ̀wé rí iṣẹ́ wọn bí ọjà títà. Ó ti jẹ́ ìrírí mi pé tí o bá lọ síta níbẹ̀ yẹn tí o ta iṣẹ́ rẹ gẹ́gẹ́ iṣẹ́-ọnà, o ní àyè láti tà á ní owó to ju ìyẹn lọ. Òtítọ́ ibẹ̀ ni pé bí o bá lọ, tí o sì ní nǹkan tí wọ́n fẹ́, o lè tà á fún iyì ọjà. Mú “Rolling Stone Article” tí ó fojú tẹ́ḿbẹ́lú General McChrystal. Ó (oníròyìn) ti le ta ìyẹn fún ẹgbẹ̀rún lọ́nà ẹgbẹgbẹ̀rún dọ́là nítorí ìyẹn ni ó wọ̀n nìyẹn ní ọjà, ṣùgbọ́n ó ṣeé ṣe pé ó tà á fún $2 fún ọ̀rọ̀ kan.”

Àwọn ìtalólobó wo ni Carney ní nípa Ìdúnàádúràá?

“O nílò láti mú àwọn iṣẹ́ ẹ bíi nǹkan tó jẹ́ àrà ọ̀tọ̀. Mo ti ní ààyè láti dúnàádúràá Àdéhùn. Mo ti ráyè láti gba ẹ̀tọ́ mi padà. Mo ti ráyè láti gba owó tó gbúpọn fún iṣẹ́ mi nípa sísọ rárá sí ọ̀pọ̀ iṣẹ́-àmúṣe. Átíkù kan tàbí méjì ni mo máa ń kọ lọ́dún. Mo sì ní ààyè láti wà láyé pẹ̀lú ìyẹn. Ìdí ni pé mo ń tà á fún òsùwọ̀n tó ga jù. Mó ń ran ẹ̀tọ́ lọ́wọ́. Mo ń tú átíkù tà fún àwọn ọjà àlejò. Mo ń ṣe ìlọ́wọ́sí ìsọ̀rọ̀. Mo ń ta àwọn ìwé.”

Ṣíṣàmójúto Àwọn Ẹ̀tọ́: O ṣe kókó

Ṣíṣàmójútó àwọn ẹ̀tọ́ ohun-ìní fún ìtàn rẹ ni wọ́n mọ̀ ní èròngbà tó fẹjú, àti ìlàkàkà, pẹ̀lú àwọn àkíyèsí ọ̀tọ̀ fún àwọn ìtàn gangan.

Àdéhùn rẹ gbọ́dọ̀ sọ irú ẹ̀tọ́ tí atẹ̀wétà ní síta, àti ohun tí o gbà. Òfin ẹ̀tọ́-atẹ̀wétà máa ń yàtọ̀ káàkiri àgbáyé, bẹ́ẹ̀ náà ni ìwádìí rẹ.

Àwọn Atẹ̀wétà “ti bíni nínú si,” gẹ́gẹ́ bí Jack Davies, tí ó kọ átíkù Àtúnyẹ̀wò Iṣẹ́-ìròyìn Columbia ọdún 2018 nípa “rights grab.” Davies rí oríṣìíríṣìí ìtẹ̀wéjáde “demand full moral and intellectual rights to freelance reporters’ work.”

Wọ́n fẹ́ Àdéhùn “ń yọ àwọn aládàáṣe kúrò nínú ríràyè sí iṣẹ́ wọn sí ọ̀pọ̀ ítẹ́wéjáde, jíjèrè látti ara ìtúmọ̀ èdeè, tàbí láti ara ìwé tàbí ìgbàmọ́ra àtẹ-agbáwòrán-tàn ti iṣẹ́ wọn, fífi sílẹ̀ pẹ̀lú wọn ọ̀nà díẹ̀ fún dídí àwọn owó àpawọlé tí wọn ti fún mọ́wọ́,” Davies ló kọ ọ́.

Ọ̀nà kan láti rò ó nípa irú ẹ̀tọ́ tí o fẹ́ gbà padà ni láti ro bí o tún ṣe le jèrè. Níbí ni àwọn ìbéèrè kann láti rò:

  • Ṣé ki o ní ẹ̀tọ sí fíìmù àgbéléwò, pódíkáàsìtì, áti àwọn ohun àgbéjáde mìíràn tí dálé iṣẹ́ náà?
  • Ṣé kí iṣẹ́ rẹ ṣeé tà ní èdè mìíràn?
  • Ṣé o lè gbe sí orí ìkànnì ayélujára tìrẹ?
  • Ṣe àwọn oníbàárà rẹ mú òfin-atẹ̀wétà dání títí láì tàbí fún àkókò kan pàtó

Ìdẹ́kun àgbáyé ni wọ́n ṣàfihàn lórí ìkànnì “Keep Your Copyrights” láti ilé-ìwé Òfin Columbia, èyí tí ó pèsè àtúngbéyẹ̀wò kan ti òfinUS. Ìkànnì náà kìlọ̀ pé:

“Tí o bá dúró dáadáa sí, o lè látara kọ́ọ̀sì ṣe iṣẹ́ àtinúdà gbé ara iṣẹ́ tó tóbi jù, èyí tí ọ̀pọ̀ rẹ ni àwọn ènìyàn mìíràn ni tí wọ́n sì ń darí rẹ̀, èyí tí ìnífẹ̀ẹ́sí àti tìrẹ le pínyà.”