Ìṣedáṣe: Ààbò àti Àìléwu

Àwọn oníròyìn Àdáṣe máa ń sábà wà láàyè ara wọn nígbà tí ó bá di ọ̀rọ̀ ààbò, lójú aye àti ìmọ̀ ẹ̀rọ ayélujára, ṣùgbọ́n ọ̀pọ̀ ohun-èèlò aṣèrànwọ́ ló wà. Ìrànlọ́wọ́ lórí ọ̀pọ̀ àkòrí wà ní àwọn ohun-èèlò tí wọn tàtẹ rẹ̀ sí sàlẹ̀, àti jù bẹ́ẹ̀ lọ ni ó wà ní ojú-ìwé ohun-èèlò GIJN:

Ààbò àti Àìléwu

Ààbò Ẹ̀rọ ayélujára

Olùgbèjà Abofinmu

Ìpè Pàjáwìrì fún àwọn Oníròyìn

Ṣíṣe Ìṣẹ́ pẹ̀lú Àwọn Oṣìṣẹ́ rẹ

Ìgbésẹ̀ àkọ́kọ́ fún àwọn aládàáṣe gbọ́dọ̀ jẹ́ láti rí ohun tí atẹ̀wéjáde rẹ máa ṣe.

Fún àwọn iṣẹ́ àyànṣe ìṣedúró tó léwu le ṣeé gbani nímọ̀ràn. Bèèrè bóyá o ní ààbò lábẹ́ ètò ti atẹ̀wéjáde. Bí wọ́n bá bò ọ́, ìyẹn dára gan, ṣùgbọ́n àwọn àlàyé kan wà tó ṣe pàtàkì láti yẹ̀wò.

Bí wọ́n bá bò ọ́, o lè fẹ́ rò ó láti ra ìlànà-adarí olúkúlùkù.

Fún àfikún Àlàyé lórí Ìfọ́nká, Ìgbéga, àti Ìṣedáṣe, wo Ìtọ́sọ́nà GIJN wa.

Àti pé nípa àwọn ìwé tó tọ́ ńkọ́, jííà àìléwu, ohun-èèlò ìbára-ẹni-sọ̀rọ̀, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ?

“ACOS Alliance” ṣátẹ ohun tí ó yẹ kí wọ́n sọ pẹ̀lú atẹ̀wéjáde. Wọ́n ṣètò Àtẹ-àyẹ̀wò Àìléwu tí ó bo gbogbo ọ̀rọ̀ àìléwu tó jẹ́ pàtó gbọ́dọ̀ bò ó ṣáájú iṣẹ́-àyànṣe. ACOS Alliance – ACOS dúró fún A Culture of Safety – jẹ́ ìfọwọ́sowọ́pọ̀ àwọn àjọ ìròyìn, àwọn ẹgbẹ́ oníròyìn aládàáṣe, àti òmìnira àwọn oníròyìn ti NgoOs.

Àwọn Ohun-èèlò lórí Ààbò àti Àìléwu

Nísàlẹ̀ ni àwọn ohun-èèlò àìléwu tí wọ́n mú láti yàrá-ìkànnì Ohun-èèlò GIJN.

Àwọn Ìgbìmọ̀ láti dá ààbò bo àwọn oníròyìn (CPJ) fúnni ni apa-mẹ́rin ohun-èèlò Àìléwu, tí wọn gbékalẹ̀ ní ọdún 2018, tí ó pèsè àwọn oníròyìn àti àwọn Yàrá-ìròyìn pẹ̀lú ìpìlẹ̀ àwọn àlàyé àìléwu èyí tí wọ́n fojú rí, ẹ̀rọ ayélujára àti àwọn ohun-èèlò ẹ̀kọ́ nípa ìhùwà àti irinṣẹ́ ní onírúurú èdè pẹ̀lúpẹ̀lú: Español, Français, ,لعربية Русский, Somali, 中文, Türkçe, မြန်မာဘာသာ.

CPJ gbé ìmúdójú-ìwọ̀n lórí abala àwọn Ìwé-àkíyèsí Àìléwu.

Tẹ̀dó sí ilẹ̀ London, “The Rory Peck Trust” pèsè olùrànlọ́wọ́ àfikọ́ra àti ìrànlọ́wọ́ sí àwọn oníròyìn àdáṣe àti àwọn ìdílé wọn káàkiri àgbáyé – mímú ìwé-àkọ́lé wọn dàgbà, mímú ìdàgbàsókè bá ire-ayé wọn àti àìléwu, àti ríran ẹ̀tọ́ wọn lọ́wọ́ láti jábọ̀ láìbẹ̀rù àti láìlọ́tìkọ̀. Àwọn ètò tó pẹ̀lú ni Ètò Olùrànlọ́wọ́ Àdáṣe, Àwọn Ohun-èèlò Àdáṣe, àti Àwọn Àmì-ẹ̀yẹ Rory Peck. Àwọn ọrọ̀ ìkànnì yìí pẹ̀lú ìgbéléwọ̀n ewu àti ìtọ́sọ́nà ìlànà ààbò.

San Francisco tó tẹ̀dó Àjọ Òmìnira Iṣẹ́-ìròyìn tí ó ṣàgbéjáde Ìtọ́sọ́nà Bí àwọn Oníròyìn Ṣe le Ṣiṣẹ́ Láti Ilé pẹ̀lú Ààbò ní ọdún 2020. Ohun tó dálé jù ni ààbò Ẹ̀rọ Ayélujára.

Àwọn Olùjábọ̀ Aláìlálà àti UNESCO fúnni ni “Ìtọ́sọ́nà Àìléwu fún àwọn Oníròyìn” tó jinlẹ̀ àti èyí tó wúlò. Ó wà ní èdè Gẹ̀ẹ́sì, Faransé, èdè Sípènì, àti èdè Pọ́túgù.

Ìwé-ìléwọ́ Àláàbò fún ìkóròyìn-jọ ìfẹ̀hónú hàn ní ilẹ̀ Brazil láti ọwọ́ Abraji (Ẹgbẹ́ ọmọ ilẹ̀ Bùràsílì ti Iṣẹ́-ìròyìn Oníwàádìí) wúlò dé àyè kan. O lè wo ìwé-ìléwọ́ kíkún ní èdè Gẹ̀ẹ́sì, èdè Pọ́túgà, àti èdè Sípènì.

Àwọn Ìlànà Àìléwu Oníròyìn Àdáṣe, tí wọ́n gbéjade láti ọwọ́ ACOS Alliance, jẹ́ ìpàtẹ ìfikọ́ra tó fẹjú tó ní èròńgbà tí ó ń ṣàgbékalẹ̀ àṣà àìléwu káàkiri yàrá-ìròyìn àti àwọn onìròyìn jákè-jádò àgbáyé.

Àwọn Ìlànà Àjọ Ìròyìn ti COVID-19: Ṣíṣe iṣẹ́ pẹ̀lú Àwọn Aládàáṣe pẹ̀sè yàrá-ìròyìn àti Àwọn Olóòtú Ìṣíde pẹ̀lú Ìtọ́nisọ́nà ìfikọ́ra lóri bí wọn yóò ṣe bo àmọ̀dájú ìtànkálẹ̀ ààrùn àti ni ọ̀nà tí ó dín ewu kùn.

Frontline Freelance Register (FFR) jẹ́ ẹgbẹ́ ìjọ́mọ-ẹgbẹ́ tó tẹ̀dó sí ilẹ̀ London “ṣí sílẹ̀ sí àwọn oníròyìn àdáṣe jádè0jádò àgbáyé tí ó hànde sí ewu ní iṣẹ́ wọn àti èyí tí ó gbọ́ràn sí “kóòdù ìwà-wíwù” wa. Ipele méjì Ìjọ́mọ-ẹgbẹ́ lówà. Ipele ọ̀fẹ́ “Ìkónimọ́ra” pèsè lẹ́tà-ìròyìn lóṣooṣù, ìfìlọ ìṣẹ̀lẹ̀, ìráàyè sí àìléwu àti àwọn ohun-èèlò alámọ̀dájú, wọ̀fún ìwé-orí lórí ìforúkọsílẹ̀, àwọn ìyáwó ohun-èèlò àìléwu, àti ìyọkúrò. Ipele “alámọ́dájú” $75 tún gba ẹ láàyè láti pàṣe “Frontline Club Charitable Trust Press Card”, àyè láti bèèrè ìwé-ìtọ́kasí alámọ̀dájú láti FFR fún èrèdí ìfàṣẹsí, àti ìyọkúrò lórí ìlànà-iṣẹ́ ìṣedúró.

FFR tún pèsè ipò ìjábọ̀ ìṣèdáṣe ọlọ́dọọdún. Ìjábọ̀ ọdún 2019 dálé èsì láti nǹkan tóju àwọn oníròyìn àdáṣe ọ̀rìn-lé-lọ́ọ̀dúnrún látí orílẹ̀-èdè Àádọ́rin. Láàárín ìwádìí jẹ́ ìṣọ́ra tó tọ́ sí àwọn aládàáṣe káàkiri àgbáyé: “Nígbà tí wọn kò sanwó fún àwọn Aládàáṣe lásìkò, wọn le fi ipá mú wọn láti gé e kúrú lórí àìléwu nítorí wọn kò ní owó tí wọ́n kó dání tí wọ́n fi pamọ́ láti gba awakọ̀ tó dára, tàbí láti dúro sí ilé-ìgbàlejò tó láàbò, tàbí láti sanwó fún ìṣedúró ẹ̀kun ogun.”