IṢẸ́ ÌWÁDÌÍ 

Ìwé Àkọsílẹ̀ Iṣẹ́ Ìwádìí ń pèpè fún iṣẹ́ ìwádìí tó dá lé àkójọpọ̀ dátà fún COVID-19 

Ìwé Àkọsílẹ̀ lórí iṣẹ́ ìwádìí fún àkójọpọ̀ dátà lórí COVID-19 kan  tí kéde àwọn ń wá àwọn tó lè ṣe iṣẹ́ ìwádìí lórí àkòrí yìí. Tí wọ́n yóò sì fi orí rẹ̀ sọ gbogbo ohun tó jọ mọ́ COVID-19. 

Gbèdéke ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n, Oṣù Ògún ti wón fún àwọn tó bá nífẹ̀ẹ́ láti kópa. 

pe