Iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ dátà

GIJN ti ṣe àkójọpọ̀ àti ètò àwọn ohun èròjà nípa lílo dátà fún ìròyìn tó jọ mọ́ iṣẹ́ ìwádìí

 À bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ojúlówó àwọn èròjà ìdánilẹ́kọ̀ọ́ kí a tóó kán lu èyí tó wúlò jùlọ. 

Àwọn ohun tí wọ́n tẹ̀ sí ìṣọ̀rí kọ̀ọ̀kan wà ní álífábẹ́ẹ̀tì pẹ̀lú ìtọ́kásí àti àpèjúwe ní ṣókí lórí wọn. 

Àwọn ohun èlò iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ dátà 

 • Bíbẹ̀rẹ̀ – Ìwé
 • Bíbẹ̀rẹ̀ – Àmọ̀ràn ní ṣókí 
 • Ìpàdé Àpérò lórí Iṣẹ́ ìròyìn 
 • Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ lórí iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ dátà 
 • Kíkó dátà jọọ – Bíbẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú fífá
 • Kíkó dátà jọọ – Lílọ òfin Àkọsílẹ̀ ojútáyé
 • Gbígbá dátà jọọ – Àmọ̀ràn ní ṣókí 
 • Àwọn ohun èlò fún ṣíṣe àtúntò dátà 
 • Àtúpalẹ̀ dátà olóǹkà
 • Àtúpalẹ̀ dátà – SQL
 • Àtúpalẹ̀ dátà – Òjòlá
 • Àwòrán 
 • Lílo R
 • Wíwo dátà 
 • Wíwo àwọn ohun èlò 
 • Kíkó àwọn ẹgbẹ́ tó jọ mọ́ ìròyìn lórí dátà jọọ 

Ààyè wà fún Àmọ̀ràn láti jẹ́ kí ìgbésẹ̀ yìí gbèrú síí. Jọ̀wọ́, kọ̀wé sí wa níbí. 

Ìdúpẹ́: Àwọn Ohun Èlò GIJN yìí jẹ́ àgbékalẹ̀ láti ọwọ́ àwọn òṣìṣẹ́ GIJN àti ẹ̀ka ìdánilẹ́kọ̀ọ́ lórí Ìròyìn tó kalẹ̀ sí ẹ̀ka ìkànsíraeni tí ilé ẹ̀kọ́ Fáṣítì Amẹ́ríkà pẹ̀lú ìrànwọ́ láti ọwọ́ Helena Bengsston, John Bones, Fred Vallance Jones, Madeleine Davison, Flor Coelho, Jennifer LaFleur, and Brant Houston.

Ǹ JẸ́ Ó WÚLÒ FÚN YÍN BÍ? BẸ́Ẹ̀ NI, BẸ́Ẹ̀ KỌ́

Ǹ JẸ́ o ṣì ní Ìbéèrè? 

Kàn sí ìkànnì ìranlọ́wọ́ 

Padà sí ìkànnì ìranlọ́wọ́ 

Àwọn Àròkọ tó jọra wọn 

Ìkọ́ni àti Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ 

Ìròyìn lórí Àmọ̀ràn ní ṣókí àti àwọn ohun èlò 

Àwọn ohun èlò COVID-19 

Àwọn ọmọ Ẹgbẹ́ GIJN 

Ìkànsíraeni àti ìbáṣepọ́

Fífi ènìyàn ṣòwò, iṣẹ́ kà ń pá àti fífi ènìyàn ṣòwò ẹrú 

Àmìn Ẹ̀yẹ

Ìkówójọ 

Nípa ìkànnì ìranlọ́wọ́ GIJN 

Ìpín, Ìgbé lárugẹ àìfíkítà

NÍPA ÌKÀNNÌ ÌRANILỌ́WỌ́ GIJN 

NÍPA GIJN 

GBÍGBÁRÚKÙÙ TÍ GIJN