Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ lórí iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ Dátà
Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú
Türkçe
Ǹ jẹ́ ó fẹ́ kọ́ nípa ọgbọ́n àtinúdá lórí ìwé ìtẹ̀wé? Àwọn ètò ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́
lórí ẹ̀rọ ayélujára tàbí olówó tí
kò gani lára wà pẹ̀
lú àwọn fọ́nrán tó ń kọ́ni lórí onírúurú àwọn àkọlé àtì èdè.
Wo ìkànnì YouTube GIJN fún ìfọ̀rọ̀werọ̀
lọ́fẹẹ̀ẹ́.
Ilé Ẹ̀kọ́ Code Academy pèsè àwọn ohun èlò ìbanisọ̀rọ̀ ọ̀fẹ́
lórí Python, SQL, PHP, C++, R, Java
àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀
lọ. Àwọn àṣàyàn tún wà tún rà ohun èlò ogún dọ́
là lóṣoosù èyí tí yóò kárí ọdún tí
yóò sì fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní àǹfààní sí onírúurú ìṣe.
Coursera pèsè àwọn iṣẹ́ ọ̀fẹ́ pẹ̀
lú sísan owó dọ̀
là mọ́kàndíǹláádọ́ta lóṣoosù fún sáyẹ́ǹsì tó jọ
mọ́ dátà, ìṣirò àti onírúurú àwọn ohun èlò èdè láti àwọn fáṣítì gbogbo jákèjádò àgbáyé. Wọ́n ń
kọ́ àwọn iṣẹ́
lédè Gẹ̀ẹ́sì, Spanish, Russian, Chinese, French àti onírúurú èdè.
Datawrapper ní àwọn èròjà fún ìdánilẹ́kọ̀ọ́.
edX ṣe àgbékalẹ̀ ètò ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́
lórí ẹ̀rọ ayélujára lórí àwọn ètò àti àtúpalẹ̀ dátà àti Ìṣirò lórí
onírúurú èdè tí kò sì yọ àwọn èdè wọ̀nyí sílẹ̀: Gẹ̀ẹ́sì, Spanish, Chinese, Russian, French, àti
German. Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ tún sì lè san owó dọ̀
là mọ́kàndílọ́gọ̀rún láti gba iwe ẹ̀rí tí wọ́n bá ti parí
ètò ẹ̀kọ́ wọn.
Àwọn oníròyìn àti àwọn olóoòótú ìròyìn tí iṣẹ́ Wọ́n jọ mọ́ iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn náà ní
ìdánilẹ́kọ̀ọ́ lórí ẹ̀rọ ayélujára.
Ìròyìn Ìpilẹ̀ṣẹ̀ Gọ́gù pèsè ètò ìdáni lẹ́ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́
lórí ayélujára fún àwọn oníròyìn pẹ̀
lú àfojúsùn lórí
bí wọ́n ṣe ń lọ gọ́gù gẹ́gẹ́ bíi ohun èlò fún iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ dátà.
Khan Academy pèsè ètò ìdáni lẹ́ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ fọ́nrán the àti àwọn àkànṣe ìdárayá ní èdè HTML,
CSS, JS àti SQL.
MIT OpenCourseware pèsè ètò ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́
lórí ẹ̀rọ ayélujára lórí Python, Java àti MATLAB. Ètò
ẹ̀kọ́ kọ̀ọ̀kan wá pẹ̀
lú ẹ̀kọ́
lórí fọ́nrán àti ìfikùn lukùn lórí iṣẹ́ àmúrelé.
Poynter’s News University
pese onírúurú ètò ìdánilẹ́kọ̀ọ́
lórí ẹ̀rọ ayélujára lórí àìmọ́yé àkọlé lórí iṣẹ́ ìròyìn, Àtúpalẹ̀ dátà, iṣẹ́
ìwádìí lórí Ìròyìn, ìlànà òfin àti àwọn ọ̀nà tí a lè fi sọ ìtàn. Ọ̀pọ̀
lọpọ̀ àwọn ètò ẹ̀kọ́ yìí ni wọn yóò
sanwó fún ṣùgbọ́n díẹ̀ nínú àwọn ètò ẹ̀kọ́ yìí ló wà lọ́fẹẹ̀ẹ́.