Ìpàdé Àpérò lórí Iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ Dátà
Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú
Àwọn ìpàdé àpérò wọ̀nyí pèsè àǹfààní lóní yanturu láti mọ àwọn ènìyàn sii, láti kọ ọgbọ́n
àtinúdá, láti jíròrò pẹ̀
lú àwọn akọ̀ròyìn yòókù lórí èrò tuntun nípa iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ dátà.
Ẹ̀ka tó ń rí sí iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn lásìkò ìpàdé tó bọ́ sí ìgbà ooru Ìdánilẹ́kọ̀ọ́
lórí iṣẹ́ ìròyìn tó jọ
mọ́ dátà sílẹ̀
láti ọwọ́ àwọn ògbọ́ǹtarìgì oníròyìn akọ́ṣẹ́mọsẹ́.
Ìkórè Dátà ń wáyé ní ìfọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀
lú àjọ tó ń rí sí iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn ti ilẹ Úróòpù. Òmíràn
yóò wáyé láàárín ọjọ́ Kọkàndínlógún sí ìkejì lè lógún, Oṣù Èbíbí ọdún 2022 ní ìlú Mechelen,
Orílẹ̀ èdè Belgium.
Ìpàdé Àpérò lórí Dátà àti iṣẹ́ ìròyìn tó jọ Ìṣirò yóò fi ààyè gba ìfikùn lukùn láàárín àwọn
akọ́ṣẹ́mọsẹ́ àti àwọn olùkọ́ni.
Àjọ̀dún Iṣẹ́ ìròyìn lágbàáyé to wáyé ní ìlú Perugia, Orílẹ̀ èdè Italy, kò yọ ilé ẹ̀kọ́ tó ń rí sí iṣẹ́
ìròyìn tó jọ mọ́ dátà sílẹ̀.
Ìpàdé Àpérò Àwọn Akọ̀ròyìn àti àwọn Olóoòótú ìròyìn tó ń ṣiṣẹ́
lórí Ìròyìn tó jọ mọ́
iṣẹ́ ìwádìí
kò yọ ìdánilẹ́kọ̀ọ́
lórí Ìròyìn tó jọ mọ́ dátà fún iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn sílẹ̀.
NICAR, jẹ́ àkànṣe iṣẹ́ àwọn akọ̀ròyìn àti àwọn olóoòótú ìròyìn, máa ń gbé ojúlówó ìpàdé
àpérò ọlọ́dọọdún kalẹ̀
lórí Ìròyìn tó jọ mọ́ dátà àti Ìdánilẹ́kọ̀ọ́
lóòrè kóòrè.
NICAR tún ní àgbékalẹ̀ àrà ọ̀tọ̀, NICAR-L láti máa gba àmọ̀ràn lọ́wọ́ àwọn oníròyìn ẹgbẹ́ wọn
yòókù. Ó tún ní ẹ̀dà tí Spanish.
for getting tips from other journalists. It also has a Spanish version.
NODA, Ìpàdé àpérò ti Nordic lórí Ìròyìn tó jọ Dátà Journalism ṣe àfihàn ìròyìn tó jọ mọ́ dátà ti
Nordic tó dára jù lọ, sí sọ ìtàn àti fífi ojú inú wo n kàn àti àmì Ẹ̀yẹ ọlọ́dọọdún. NODA tún ní
àkójọpọ̀ ẹ̀rọ ayélujára Ìbánidọ́rẹ̀ẹ́ Facebook bákannáà.
Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú
Nípa
Ìkànsíraeni