Ohun èlò fún àfọ̀mọ́ àti àmúyẹ Dátà

Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú

Ǹ JẸ́ o ní dátà tí kò ká ojú òṣùwọ̀n? Àwọn ohun èlò wọ̀nyí yóò wúlò fún ẹ láti ṣe àmúlò dátà rẹ

dára dára.

OpenRefine jẹ́ ohun èlò ọ̀fẹ́ tó wà fún fífi dátà dárà. Ní pàtàkì jù lọ, ó wúlò fún àwọn dátà tí kò

kàjú òṣùwọ̀n. Ó wà ní èdè Gẹ̀ẹ́sì, Chinese, Spanish, French, Russian, Portuguese (Brazil),

German, Japanese, Italian, Hungarian, Hebrew, Filipino, Cebuano àti Tagalog. Ojúlówó I wá lórí

dánilẹ́kọ̀ọ́ wá ní ojú òpó OpenRefine.

Yíyọ́ dátà kúrò nínú PDF jẹ́

iṣẹ́ ń lá gbáà fún àwọn akọ̀ròyìn ní láti kojú. Àìmọye ohun èlò wọ̀nyí

ló jẹ́ kí iṣẹ́ náà rọrùn. Tabula jẹ́ ohun èlò tí wọ́n ń lo tí wọ́n ń yọ láti ara dátà inú tabular nínú pdf.

Ohun èlò míràn tó jẹ́ ọ̀fẹ́ ni XPDF, tó tún ń ṣe àtìlẹ́yìn fún àìmọye èdè yàtọ̀ sí Gẹ̀ẹ́sì.

CometDocs jẹ́ ohun èlò tó tún jẹ́ ọ̀fẹ́, tí kò sì yọ àwọn ètò míràn lórí ẹ̀rọ ayélujára tó ṣeé kó

àwọn èròjà sí àti àwọn fáìlì míràn tó wúwo.

CSVkit jẹ́ ohun èlò míràn tó jẹ́ atọ́nà láti ṣe àyípadà àti ṣiṣẹ́ pẹ̀

lú CSV, tó jẹ́

irin iṣẹ́ fáìlì.

Workbench is a set of tools for jẹ́ àkójọpọ̀ ohun èlò àfọ̀mọ́ dátà àti àtúpalẹ̀ dátà láti ilé ẹ̀kọ́ ìkọ́ni

fún iṣẹ́ ìròyìn ní ilé ẹ̀kọ́ Fáṣítì Columbia.

Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú