Iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ dátà: Àkójọpọ̀ GIJN

Àkójọpọ̀ Dátà: Àmọ̀ràn ní Ṣókí

Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú

Tí o bá ní dátà tì ẹ, ó lè wọ àwọn ìwé Àmọ̀ràn ní ṣókí lọ́fẹẹ̀ẹ́ àti àwọn ìdánilẹ́kọ̀ọ́

lórí bí ó ṣe lè

àfọ̀mọ́ rẹ̀ kí o tó bẹ̀rẹ̀ àlàyé lórí rẹ̀.

Ìtàn yìí jẹ́ àpẹẹrẹ ohun tí ó ní láti ṣe tí ààlà bá wà nínú àmúlò dátà tó bá wá láti ọ̀dọ̀ àwọn aláṣẹ

(2021).

Ìwé Ìtàn Lórí Dátà: Bí ó Ṣe lè Dá Dátà Rẹ Mọ̀ (2017) jẹ́ ìkànnì Ìbánidọ́rẹ̀ẹ́

láti ọwọ́ Heather

Krause, tí ẹ̀rọ ayélujára lórí iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ dátà ti ìlú tí ó ń ṣe ìgbélárugẹ ìtọpinpin àkóónú àti

àkójọ dátà kí wọ́n tóó di mímú lò.

Àṣàyàn Atọ́nà fún Dátà tí kò Bójú Mu (2018) jẹ́ fáìlì lórí ìkànnì GitHub tó yànàná àwọn ìṣòro

tó ń kojú dátà àti láti wá ìyànjú síi. Wọ́n tún tú u sì èdè Chinese, Japanese, Portuguese àti

Spanish.

Atọ́nà ProPublica tó Dáàbò bo Dátà Data (Àtúntò ọdún 2018) ní Jennifer LaFleur ṣe àkójọpọ̀

rẹ̀ pẹ̀

lú àfikún láti ọwọ́ àìmọ́yé àwọn òǹkọ̀we, tó jẹ́ ọ̀nà tí wọ́n ń ṣe àyẹ̀wò dátà. Maryjo iṣẹ́ ń tẹ̀

síwájú lórí rẹ̀, atọ́nà lórí sìbẹ̀, and ṣe àfikún abá tìrẹ náà.

Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ yìí láti ọwọ́ akọ̀ròyìn ọmọ Belgian kan, Stijn Debrouwere ṣàlàyé bí a ṣe lè yọ àṣìṣe

jáde dátà àti láti dẹ́kun àṣìtú àwọn Àtúpalẹ̀ dátà gbogbo. Ó wà lọ́fẹẹ̀ẹ́

lórí ìkànnì ayélujára

datajournalism.com.

Bẹ̀rẹ̀ Pẹ̀lú OpenRefine (2017) èyí jẹ́ ọ̀nà tó yá Kánkán láti kẹ́kọ̀ọ́ pẹ̀

lú àwọn àwòrán tó ní àwọn

ohun èlò tí wọ́n fi ń ṣe àfọ̀mọ́ dátà lórí ìkànnì OpenRefine. Ọ̀jọ̀gbọ́n Miriam Posner tí UCLA ló

ṣẹ̀dá rẹ̀. .

Ṣíṣe àfọ̀mọ́ ní ìkànnì OpenRefine (2018) èyí jẹ́ ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ atọ́nà lórí ẹ̀rọ ayélujára pẹ̀

lú àwọn

àpẹẹrẹ àti àwọn fọ́nrán ìdánilẹ́kọ̀ọ́ tó tún jẹ́ atọ́nà àfọ̀mọ́ fún ìwọ̀n dátà lórí ìkànnì OpenRefine.

John Little, tí ẹ̀ka ilé ìkàwé Fáṣítì Duke.

Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ yìí wá láti ọwọ́ akọ̀ròyìn kan tó jọ mọ́ dátà, láti ìlú Belgium, Maarten Lambrechts. Ó

jẹ́ atọ́nà fún Excel láti ṣe àfọ̀mọ́ àti ìpéwọ̀n to múná dóko fún dátà. Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ yìí jẹ́ ọ̀fẹ́

lórí

ìkànnì Datajournalism.com.