Iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ dátà: Àkójọpọ̀ GIJN

Fífá Dátà

Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú

Fífá dátà jẹ́

lílo ohun èlò tó jẹ́ kó rọrùn láti lo dátà lórí ẹ̀rọ ayélujára. Àwọn ohun tó wà ní ìsàlẹ̀ yìí

tó wà fún ẹ̀kọ́

lórí àmúlò dátà lórí ẹ̀rọ ayélujára, kò sì bí ó ṣe lè mọ̀ nípa Kóòdù.

Àkòrí nínú ìwé ìléwọ́

lórí iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ Dátà, ìpín kìíní kò yọ ìlànà lórí fífá àti àwọn àpẹẹrẹ

kóòdù .

Journocode (2019) sọ ní ṣókí lórí àwọn Ìpilẹ̀

lórí ohun èlò fún àwọn oníròyìn àti àwọn onímọ̀ ẹ̀rọ

tí wọ́n fi ìlú Germany ṣe ibùgbé.

Samantha Sunne ṣe àtúpalẹ̀ Ìpilẹ̀ṣẹ̀

lórí fífá nínú àgbékalẹ̀ yìí. Ó tún ṣe àgbékalẹ̀ àwọn ohun èlò

fún àwọn alákọ̀bẹ́rẹ̀ tó ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ nípa fífá lórí ẹ̀rọ ayélujára.

Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú