Iṣẹ́-Ìròyìn Oníwàádìí Aládàáni: Bí Wọ́n Ṣe Máa Ń Ró-Ohùn

Títa àwọn àbá Iṣẹ́-ìròyìn Oníwàádìí Aládàáni dàbí títa àwọn ìtàn mìíràn gidi gan, ṣùgbọ́n ó tún le jù ú lọ. Kò kàn sí ìgbéjáde ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbé-ìròyìn-jáde tó tó tó ń wù láti lọ́wọ́sí nínú jíjábọ̀ aṣọ́nilọ́wọ́-ṣọ́nilẹ́sẹ̀ (ajáfitafita).

 Fún àfikún lórí Ìfọ́nká, Ìgbéga, àti Ìjẹ́-aládàáni, ṣàyẹ̀wò sí Ìtọ́sọ́nà GIJN wa.

Àti pé rírohùn iṣẹ́-ìwádìí èyí tí ó le má dàájú àti àbájáde tó tako ara máa ń sábà dojúkọ wọ́n, tó ń bèrè fún ìdásílẹ̀ ìgbẹ́kẹ̀lé tó wọ́pọ̀.

Kín ló tún kù, ìnáwó ṣíṣe iṣẹ́-ìwádìí agbani-lákòkókò le ga, nígbà tí ìsan-wó-padà kò tó. Ó ṣòro láti kan sọ pé iye àkókò àti akitiyan tí yóò níṣe pẹ̀lú, ṣíṣe àtúpalẹ̀ àǹfààní-ìnàwó tí kò dán mọ́ọ́rán kàn jẹ́ àsọtẹ́lẹ̀ tó fẹjú.

Nígbà náà, ní ìkẹyìn, ó ní ewu tara-ẹni. Àwọn Aládàáni le dojúkọ àwọn ìpèníjà tó dá yàtọ̀ ń ṣiṣẹ́ lórí àwọn ìtàn tó tako ara wọn, pẹ̀lú amòfin àti àwọn àwọn ewu aláìléwu tí àwọn àbájáde ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbé-ìròyìn-jáde kò le rò.

Ó ṣòro láti sọ pé iye àkókò àti akitiyan tí yóò níṣe pẹ̀lú, ṣíṣe àtúpalẹ̀ àǹfààní-ìnàwó tí kò dán mọ́ọ́rán kàn jẹ́ àsọtẹ́lẹ̀ tó fẹjú

Lẹ́yìn gbogbo èyí, ipò àwọn olùjábọ̀ oníwàádìí aládàáni ṣì í lágbára. Tí wọ́n yọ jáde láti ìdáwà-dáńfó àti òmìnira láti mú ìtàn ẹni àti àtẹ̀jáde, àwọn aládàáni rí ọ̀pọ̀ ìpínlérè. Àwọn kan dá ìbáṣepọ̀ ọlọ́jọ́-pípẹ́ sílẹ̀ pẹ̀lú àwọn olóòtú àti àtẹ̀jáde, àwọn mìíràn mú iṣẹ́ ìlọ́wọ́sí lẹ́gbẹ̀ẹ́ kan láti ṣe ìrànwọ́ fún sísan owó, àti fẹ ìkànsí wọn lójú àti owó-tó-wọlé gẹ́gẹ́ bí àwọn òǹkọ̀wé, àwọn olùkọ̀ọ́ àti àwọn alámọ̀ràn.

“GIJN” ti ṣe wo àwọn ìpèníjà tó jẹ́ àrà ọ̀tọ̀ ti títa iṣẹ́-ìròyìn oníwàádìí àti níbí pèsè ìmọ̀ràn àfikọ́ra láti ọ̀dọ̀ àwọn oṣìṣẹ́ onírìírí ọlọ́jọ́-pípẹ́.

A dojúkọ:

  • Rírí àwọn àbájáde tó nípa
  • Ṣíṣe àwọn ìró-ohùn tó múnádóko
  • Dídá ààbò bo èrò rẹ
  • Rírèrò ìsúnà rẹ.

Ní àfikún sí àyẹ̀wò tó gbòòrò yìí, “GIJN” ti ṣe àtójọ àtẹ ìtalólobó àti àwọn ète pàtó sí ìjẹ́-aládàáni nígbà àjákálẹ̀ ààrùn-tó-kárí-ayé COVID-19.

Rírí àwọn Àbàjáde tó Nípa

Wọ́n nílò Ipele ìfọkàntán tó jẹ́ àrà ọ̀tọ̀ kí àtẹ̀jàde ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbé-ìròyìn-jáde ta tẹ́tẹ́ lórí oníròyìn oníwàádìí, ohun-tó-bójú-ayé-mu tó mú ìgbéga bá ìnílò láti ṣe àsopọ̀ ara-ẹni.

Kíkọ́ ìbáṣepọ̀-ọ̀rẹ́ nípa kọ́kọ́ ta àwọn ìtàn tí kì í ṣe ti oníwààdìí le jẹ́ ọ̀nà tó dára láti kọ́ ìsopọ̀ tó tọ́. Ṣíṣe “cold calls” lórí àwọn ìtàn ajẹmọ́-ìmọ̀lára le ṣòro gidi.

Àbá tó wọ́pọ̀ ni láti pàdé àwọn olóòtú ajẹmọ́-ìbáṣepọ̀-ọ̀rẹ́ nípa lílọ àwọn sẹminá àti àwọn ìpàgọ́.

Lásìkò Ìwádìí

Ó tún ṣe é gba nímọ̀ràn ń ṣe ìwádìí lórí àtẹ̀jáde tó nípa, kì í lórí àwọn ibi tí wọ́n ń ṣe átíkù oníwàádìí nìkan, ṣùgbọ́n pẹ̀lú àwọn ẹni tí wọ́n nífẹ̀ẹ́ sí àkòrí rẹ.

Pẹ̀lú ìran yìí lọ́wọ́, wá a síwájú:

  • Ka ohun tí wọ́n ti tẹ̀ jáde tàbí gbé sáfẹ́fẹ́ tẹ́lẹ̀, lórí kókó ọ̀rọ̀ rẹ tàbí kókó ọ̀rọ̀ àwọn mìíràn.
  • Kọ́ nípa ọ̀nà-àmúṣe wọn àti sítàì.
  • Ṣàyẹ̀wò àlàyé iṣẹ́ wọn.
  • Ṣàbẹ̀wò àwọn olóòtú wọn tó wà lóókè.
  • Bèrè bóyá ìwọ tàbí ẹni tí o mọ̀ ní àsopọ̀ ara-ẹni tí ó le ṣílẹ̀kùn.

Ro ọ̀pọ̀ ọjà fún àwọn ohun-èèlò rẹ “láti rún ìwúlò jáde láti gbogbo akitiyan àgbàjọ-ìròyìn” gẹ́gẹ́ Rowan Philp ti “GIJN” ṣe sàpèjúwe lé lórí nínú átíkù kan ti ọdún 2019 GIJN lórí íjẹ́-aládàáni.

“Àwọn Oníròyìn Oníwàádìí Aládàáni nílò láti wọ ìwà à ń wá ọ̀pọ̀ àǹfààní ìtajà fún gbogbo ìrètí ìjábọ̀, bí wọ́n bá nílò láti tiraka tàbí yè,” Rowan ló kọ ọ́, òun fúnra rẹ̀ jẹ́ aládàáni onírìírí.

Àwọn Ikọ̀-ìrújú ní ìgbà náà ṣàpèjúwe onírúurú ìwọ̀fún, pẹ̀lú ìtẹ̀jáde, ìfojú-wò, àti ààtò alárìígbọ́ fún mímúlò ajẹmọ́-owó-tó-wọlé.

Ṣíṣe Ìró-Ohùn

Níwọ̀n ìgbà tí o bá ti ní ìtẹ̀wéjáde kan pàtó lọ́kàn, o máa nílò láti ní àwọn ìró-ohùn lọ́kàn.

 Ọ̀pọ̀ àmọ̀ràn aládàáni tó gbéwọ̀n nípa títa ìtàn ṣì ì níṣe pẹ̀lú iṣẹ́-ìròyìn oníwàádìí. Àwọn ìró-ohùn gbọ́dọ̀ jẹ́ ṣókí, ní ìtumọ̀, àti ìdásí kíákíá.

“O nílò láti yí olóòtú lọ́kàn padà pé ìwọ ni ẹni tó tọ́, pé ìwọ nìkan ni o lè ṣe ìtàn yẹn.” – Oníròyìn Catalina Lobo-Guerrero

“O nílò láti yí ọkàn olóòtú padà tàbí ẹnikẹ́ni tí ó bá ń rò ó wò bóyá ìwọ ni ẹni tó tọ́, bẹ́ẹ̀ sì ni ìwọ nìkan ni ẹni tó le ṣe ìtàn náà, nítorí o ní ìpìlẹ̀ rẹ̀, àwọn orísun, ìrírí tó ṣe kókó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ tàbí o ráàyè sí àwọn ìwé-àkọsílẹ̀, èyí tó lù síta tí ẹnikẹ́ni kò ní,” Catalina Lobo-Guerrero ló sọ bẹ́ẹ̀, oníròyìn aládàáni tí “Colombi” àti ẹni tó ti fi ìgbà kan rí jẹ́ olóòtú “GIJN” pẹ̀lú ìrírí tí ó ju ọdún mẹ́wàá lọ.

Àwọn Ìtalólobó Láti ọ̀dọ̀ Àwọn Olóòtú

Olóòtú Orílẹ̀-èdè jákè-jádò òkun àgbáye Scott Stossel fún wọn ní ìtalólobó rẹ̀ níbi ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò lọ́dún 2017:

  • Ṣe àwọn ìjábọ̀-ìsáájú. Rí i dájú pé ìró-ohùn rẹ jáde dáadáa.
  • Kọ gbogbo ọ̀rínkínníwín àlàyé. Ṣàwárí àwọn ìwà, àwọn ewu àti ìdí tó fi ṣe pàtàkì sí àwọn òǹkàwé.
  • Ṣàfihàn ìmọ̀ọ́ṣe ìwé-kíkọ. Ìró-ohùn fúnra gbọ́dọ sọ ìtàn, kí ó sì ṣàgbékalẹ̀ igun ìtàn.
  • Ní eré-oníṣe díẹ̀. Dé ọkàn eré-oníṣe nínú ìró-ohùn fúnra rẹ̀.
  • Jẹ́ kí òye ìwúlò ìròyìn yé ọ. Bí àsomọ́ pẹ̀lú ìròyìn tó ń lọ lọ́wọ́ bá ṣe hàn kedere, ni ó dára.
  • Ṣe é lákòókò tó tọ́.

Gẹ́gẹ́ bí Ìwé-ìléwọ́ Iṣẹ́-ìròyìn Oníwàádìí, Iṣẹ́-àkànṣe ti àwọn ètò Ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbé-ìròyìn-jáde Káàkiri Àgbáyé ti Àjọ Konrad Adenauer Stiftung, ìró-ohùn gbọ́dọ̀ pẹ̀lú: 

  • Ìlàpa-èrò Ìtàn
  • Ìdí tí ìtàn yẹn fi tọ́ fún pépà yìí ní pàtó tàbí ọ̀nà-òǹkàwé.
  • Ìsọníṣókí àkáùntì ti ìdojúkọ tàbí ọgbọ́n-ìkọ́ni.
  • Àtẹ-àkókò
  • Ìsúná

Sarah Blustain, Olóòtú Àgbà ti “Type Investigations” (fìgbà kan rí jẹ́ Olùrànwọ́ Oníwàádìí), ṣàgbékalẹ̀ ewé-ìtalólobó lórí kíkọ àbá ìtàn tí ó tẹnumọ́ “jẹ́ kó kúrú,” “sàn-án ni kí o rìn,” kí o sì “fún àwọn olóòtú ní ohun tí wọ́n fẹ́ mú jáde láti inú ìró-ohùn rẹ ní àkàsọ̀ ìṣolóòtú.” Ó sọ wí pé ohun tí òun máa ń sábà gbà níyànjú “ìró-ohùn ìpínrọ̀ mẹ́rin,” pẹ̀lú àwọn wúnrẹ̀n tó ṣe pàtàkì mẹ́rin:

  • Ohun tí ìtàn jẹ́.
  • Ìdí tí ó fi ṣe kókó – àti ìdí tó fi ṣe kókó báyìí.
  • Kín ni àwọn ìwádìí rẹ.
  • Ìdí tí o fi gbọ́dọ̀ jẹ́ ẹni tó máa kọ ọ́.

Mother Jones, ìwé-ìròyìn US tí ó mú ìtàn oníwàádìí kún un, tẹnúmọ̀ àwọn kókó yìí nínú Ìlànà Ìtọ́sọ́na Òǹkọ̀wé Aládàáni rẹ̀: 

“Sọ fún wa ohun tí gbèrò láti kó jọ láìkọjá ìpínrọ̀ díẹ̀ lọ, ìdí tí ó fi ṣe pàtàkì àti tó fi wuni, àti bí o ó ṣe jábọ̀ rẹ̀. Ìbéèrè náà gbọ́dọ̀ fi ìdojúkọ, ohùn, àti sítàì ránṣẹ́ ó sì gbọdọ̀ dáhùn àwọn wọ̀nyí: Kín ni àwọn ìṣe-yàn rẹ pàtó fún ìkọ̀wé lórí àkòrí yìí? Àwọn ohun tinú wo lo ní pẹ̀lú àwọn orísun rẹ? Tí àwọn ìtàn tó ṣe kókó miìíràn bá ti di ṣíṣe lórí àkòrí yìí, báwo tìrẹ yóò ṣe yàtọ̀ – àti dára jù?”

“Jọ̀wọ́ ṣe àfikún ìlà kan tàbí méjì nípa ìpìlẹ̀ rẹ àti méjì tàbí mẹ́ta kílìpù tó yẹ jù (àwọn àsopọ̀ dára).”

“Sọ fún wa ohun tí gbèrò láti kó jọ láìkọjá ìpínrọ̀ díẹ̀ lọ, ìdí tí ó fi ṣe pàtàkì àti tó fi wuni, àti bí o ó ṣe jábọ̀ rẹ̀.” – Mother Jones

Átíkù Nieman Storyboard tọdún 2018 – The Pitch: At the Guardian’s Long Read, No Rigid Formula or Geographic Limits – kì í ṣe nípa iṣẹ́-ìròyìn oníwàádìí nìkan, àti ó lejú lórí ohun tí ó gbà. “Àmọ̀ràn olóòtú: kọ́ ohun tí wọ́n ti tẹ̀ jáde tẹ́lẹ̀. Jẹ́ ẹni-tó-láṣẹ, máa dán, àti “gígbéni.” Gbìyànjú láti fi ìró-ohùn tó tutù (tó dára).”

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n kọ ọ́ pẹ̀lú owó-ìrànwọ́ lọ́kàn, ìlà-òòró ti ọdún 2016 láti ọwọ́ Eric Karstens pẹ̀lú àkòrí How Not to Win a Journalism Grant, tí wọ́n tún gbéjáde ní ọdún 2018 láti ọwọ́ GIJN, ní ọ̀pọ̀ èrò tó dára lóri ìgbékalẹ̀.

Ohun tí Àwọn Olóòtú Ń Wà nínú Àtúnṣe àwọn Ìró-Ohùn, apá kejì ti ọ̀wọ́ apá-kẹta lórí ríró-ohùn fún Nẹ́tíwọ̀kì Iṣẹ́-ìròyìn Àtúnṣe ní ọdún 2018, Julia Hotz fẹ àwọn kókó mẹ́jọ yìí lójú:

  1. Ìdáhùn tó hàn kedere, ọ̀rínkínníwín àlàyé, ìmọ̀lára-àkókò sí “Kín ni ìdí tí àwọn òǹkàwé ṣètọ́jú?”
  2. Ìmọ̀lára wí pé asọ̀tàn gidi, àti pé ìtàn wà láti sọ.
  3. Ẹ̀rí – aláwòmọ́ tàbí alásọye – ipa ìdáhùnsí.
  4. Ìdúpẹ́ olódìwọ̀n ìdáhùnsí, àti ojú lára ìṣèlọ́pò rẹ̀.
  5. Òye lórí bí átíkù ṣe bẹ̀rẹ̀, àti bí àwọn mìíràn yóò ṣe tẹ̀lé e.
  6. Ìsọníṣókí àlàyé lórí bí o ó ṣe jábọ̀ ìtàn, àti ìdí tí wọ́n fi yàn ọ́ láti jábọ̀ rẹ̀.
  7. Àkòrí láti ta ìwúlò ìtàn àti ṣàfihàn àtẹ-àkókò rẹ̀.
  8. Òye ohun tí àtẹ̀jáde ìròyìn bò (àti èyí tí kò bò).

Apá kìn-ín-ní ọ̀wọ́ jẹ́ ẹyọ ìbánidámọ̀ràn lórí ìpele àkọ́kọ́ fún ìdàgbàsókè ìró-ohùn, àti apá tó parí fúnni ní àwọn àpẹẹrẹ láti inú ìró-ohùn aláṣeyọrí.

Bí O ṣe lè Ró-ohùn “New York Times” pẹ̀lú àṣeyọrí (tàbí, bẹ́ẹ̀, ẹlòmìíràn) láti ọwọ́ Tim Herrera, pẹ̀lú “àwọn àṣìṣe mẹ́fà tó wọ́pọ̀,” tó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú “O kò mọ ohun tí ìtàn rẹ ẹ́ jẹ́.”

Ìdí tí wọ́n fi já Ìró-ohùn rẹ kulẹ̀ – Láti ọ̀dọ̀ àwọn Olóòtú Fúnra Wọn, ìmọ̀ràn láti ọ̀dọ̀ àwọn olóòtú tí ìwé-ìròyìn tó ń sáájú ní ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò láti ọwọ́ Ben Sledge fún Ẹgbẹ́ Alájẹ-sẹ́kù Ìwé-kíkọ.

Àtẹ kan tó dára ti ọ̀pọ̀ ìlànà ìtọ́sọ́nà àtẹ̀jáde ríró-ohùn ni àwọn Oníròyìn Alámọ̀dájú ti Àwùjọ gbé sí orí-ìtàkùn ní US.

Àtẹ̀jáde-ìròyìn Oníwàádìí béèrè fún ohun tó pọ̀ 

Àwọn orí-ìtàkùn ayélujára ti ìtẹ̀wé-jáde oníwàádìí máa ń sàbà pèsè  ìlànà ìtọ́sọ́nà lórí ohun tí wọ́n ń wá. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wí pé àwọn ìmọ̀ràn kan jẹ́ ìtẹ̀wésíta-pàtó, àwọn kan sì wà tí wọ́n jẹ́ àtẹ̀ránṣẹ́ tó wọ́pọ̀.

“Reveal”, rédíò oníwàádìí ti US ṣàfihàn láti Ìkànnì fún Ìjábọ̀ Oníwàádìí, bèèrè fúnn ọ̀pọ̀ àlàyé, kí o sì fún wọn ní àwọn ìbéérè tó le.

Ààtò Àgbàwọlé bẹ̀rẹ̀ bó ti yẹ tó, ń fún àwọn oníròyìn ní ọ̀rọ̀ ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta láti “sọ fún wa ohun tí ìtàn rẹ dálé lórí àti irú ìbéèrè tí ìtàn rẹ ń gbìyànjú láti dáhùn.”

Àwọn irúfẹ́ ìbéèrè mìíràn wà, pẹ̀lúpẹ̀lú:

  • Ta ni ó ta bá?
  • Kín ni ó jẹ́ kó jẹ́ ìtàn tí orílẹ̀-èdè?
  • Kín ni ó jẹ́ kó jẹ́ “àtòjọ ìtàn fún rédíò”?

Nígbà náà ni àwọn olóòtú Reveal ronú jinlẹ̀, pẹ̀lú àwọn ìbéèrè mẹ́sàn-án tó níṣe pẹ̀lú:

  • Ṣàtòjọ àwọn àlàyé máàrún tó dá yàtọ̀ tí o kò tí ì kójọ àti èyí tó ń ṣiṣẹ́ láti má kò ó jọ.
  • Sọ fún wa nípa àwọn ẹ̀dá gangan àti ìran tí o retí láti gbà sílẹ́ pẹ̀lú wọn.
  • Ta tún ni ó ti kó irú ìṣẹ̀lẹ̀ yíì jọ (pèsè àsopọ̀), àti bí ìtàn rẹ yóò ṣe yàtọ̀?

Ṣíṣe pẹ̀lú Àìlánìídájú

Ọ̀pọ̀ àìlánìídájú lówà ní bí ìròyìn yóò ṣe jáde síta, ṣùgbọ́n ìyẹn kò nílò láti jẹ́ àìwúlò.

Lobo-Guerrero sọ pé: “bẹ́ẹ̀ ọ̀nà kan láti ró-ohùn ìtàn oníwàádìí ni láti sọ pé: Ohun tí mo retí láti gbà nìyí, bí mo bá ṣàfihàn àbá ìpìlẹ̀ mi, ṣùgbọ́n bí n kò bá rí i gbà, èyí yóò ṣáà jẹ́ ìtàn lọ́nàkọnà nítorí… bí àwọn àbá a,b,c, tàbi ohun tí àwọn olóòtú kan pè ní ìtàn tó pọ̀ jù tàbí tó kéré jù.”

Ìtọ́sọ́nà ọdún 2015 láti inú “Balkan Investigative Reporting Network” (BIRN) ní àwọn ìpín-sí-ìsọ̀rí tó wúlò lórí ríráàyè sí ipò-ohun-tó-ṣeé-ṣe, àti kíki àbá ìpìlẹ̀, àti dídásílẹ̀ ìtàn tó kéré jù/pọ̀ jù. Èdè Gẹ̀ẹ́sì ni wọ́n kọ ọ́.

Kín ni Wọ́n Yọ Sílẹ̀?

Èwo-ni-kín-n-ṣe máa ń wà nígbà tí o bá ti ní òye ńlá láti tà. Bá wo ni ó ó ṣe ṣàfihàn ìtàn rẹ nígbà tí o tún dá ààbò bò ó, pẹ̀lú? Iró-ohùn náà ní láti jẹ́ pàtó, ṣùgbọ́n kí ó má fi bẹ́ẹ̀ ní ọ̀rínkínníwín àlàyé pé òye rẹ yóò tọ súná.

Èwo-ni-kín-n-ṣe máa ń wà nígbà tí o bá ti ní òye ńlá láti tà. Bá wo ni ó ó ṣe ṣàfihàn ìtàn rẹ nígbà tí o tún dá ààbò bò ó, pẹ̀lú?

Iṣẹ́-ìwádìí “Type” ti Blustian dábàá: “O kò fẹ́ ṣe wàhálà púpọ̀ jù tí wọn yóò wà fún agbéròyìnjáde ní ìwádìí rẹ tí wọ́n le fún olùjábọ̀ mìíràn.” Ó dá wọn lẹ́kùn fífún ènìyàn ní orísun rẹ.

O lè pinnu láti gbẹ́kẹ̀lé olùgbéròyìnjáde awòsàkùn kan. Tàbí, àwọn olùbánidámọ̀ràn alámọ̀dájú kan, bèèrè fún àdéhùn aláìhànde-síta “nondisclosure agreement” (NDA). Èdè náà le rọrùn.

Ohun tó ṣeé ṣe kan bẹ́ẹ̀:

“Atẹ̀wétà X gbà láti má tẹ àwọn ìwádìí tó kún fún ìro-ohùn láti ọwọ́ Òǹkọ̀wé X láìgbàṣẹ kíkọ sílẹ̀ òǹkọ̀wé  X jáde.”

Samantha Sunne ló lo ìmọ̀ rẹ̀ láti gbé èdè náà kalẹ̀, olùjáàbọ̀ aládàáni ní ilẹ̀ New Orleans, Louisiana, ẹni tí ó tẹ lẹ́tà-ìròyìn tí wọ́n pè ní Ohun-èèlò fún Àwọn Olùjáábọ̀.

“NDA le pa jù èyí dá lórí iṣẹ́-àkànṣe,” ó fèsì ní ìgbésórí-ìtàkùn ti ọdún 2018. “N kò ní ní dandan fún gbogbo ìtàn, nítori mo gbìyànjú rẹ̀ lẹ́ẹ̀kan sí i pẹ̀lú olóòtú kan tí n kò tíì bá ṣiṣẹ́ pẹ̀lú rí, ó sì já mi kulẹ̀.” Níbáyìí, Sunne sọ fún àjọ “GIJN”, òun ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn ènìyàn tí òun mọ̀ pé òun sí rí ìmọ̀lára pé kò sí ìnílò fún irú ìdánilójú bẹ́ẹ̀.

Àwọn Aládàáni Oníwàádìí gba ni mọ́ràn pé àwọn ohun tó burú jù láti jẹ́ kó hànde sí àwọn olùgbéròyìnjáde ni àwọn orísun àti àwọn ìwé àkọsílẹ̀. Ṣùgbọ́n tí ìyẹn bá ṣe kókó, nóòtì NDA le ṣàtinúdá láti dáàbò bo ohun tí ó ti hànde síta.

Sunne dá àbá pé ọ̀nà tó dán mọ́ọ́rán jù láti gba ìdánilójú ohun-àṣírí ni láti bèèrè fún ímeèlì.

Fún ọ̀pọ̀ aládàáni, ìṣòro náà wá sí ìgbẹ́kẹ̀lé. Àwọn tí wọ́n ní ìbáṣepọ̀ iṣẹ́ pẹ̀lú olùgbéròyìnjáde ní pé àwọn kì í ronú nípa rẹ̀. Àti pé àwọn olùgbéròyìnjáde kan hànde pẹ̀lú ìmọ̀lára sí ìdáàbò ti aláṣẹ.

Iṣẹ́-ìwádìí Type, fún àpẹẹrẹ, gba ìfojúwò yìí sí ìṣohun-àṣírí:

“A gba ìṣe kàn-ń-pá láti ṣọ́ àwọn òye ìtàn rẹ dáadáa; a kò ní pín in ká kọjá àárín àwọn ọmọ-ẹgbẹ́ aṣe-olóòtú. A tún ṣàkíyèsí àwọn àkóónú àbá rẹ le ní àwọn àlàyé ṣe kókó. Jọ̀ ọ́ jẹ́ kí á mọ̀ bí o bá ní ìfẹ́sí fífi àwọn ọ̀rínkínníwín àlàyé sílẹ̀ láti ímeèli, a ó ṣi gbé ọ̀nà ààbò ti ìbáraẹnisọ̀rọ̀ sílẹ̀.”

Ṣíṣè-ṣirò Iye-owó Rẹ

Ṣíṣẹ̀dá ìṣúná jẹ́ lámèyíìtọ́ fún jíjẹ́ kí ìjẹ́-aládàáni lérè.

Ìfojúsọ́nà Iye-owó máa ràn ọ́ lọ́wọ́ láti pinnu iye tí o ó dá lé wọn àti ìgbà tí o ó gbójú kúrò nígbà tí wọ́n bá fowó kékeré lọ̀ ọ́.

“Lẹ́yìn ọdún díẹ̀ tí o ti ń gbìyànjú láti fojú ya àwọn ìtàn oníwàádìí kó lòdì sí ìdáṣe abójú-ayé-mu, mo wá pẹ̀lú ìlànà abójú-ayé-mu ti mo pè ní “tiers,” tí Aládàání Sunne ti US kọ.

Àwọn Aládàáni mìíràn gbà: Gbáradì láti kọ àwọn iṣẹ́-àkànṣe tí ó kéré sí kókó tí o fọ́-kalẹ̀.

Fún ipele kọ̀ọ̀kan, ó ṣàpèjúwe iye akitiyan tí òun yóò fi sí ṣíṣàwárí àwọn òye: “Ìdí fún èyí hàn kedere: N kò fẹ́ wádìí sí – ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò, àkọsílẹ̀ àwùjọ, àti iye-owó ìrìn-àjò – bi mo bá ma gbẹ̀yìn àìní nǹkan kan. Bí n kò bá rí àdéhùn tí wọ́n bu ọwọ́ lù, tàbí ó kéré tán ìnífẹ̀ẹ́sí láti ọ̀dọ̀ olóòtú, mà á fi ìtàn náà sílẹ̀.”

Àwọn Aládàáni mìíràn gbà: Gbáradì láti kọ àwọn iṣẹ́-àkànṣe tí ó kéré sí kókó tí o fọ́-kalẹ̀.

Ìdí mìíràn láti hun ìfiyèsí ìnáwò pọ̀ ni láti dúnàá-dúràá iye-owó tí akòlesọ-àsọtẹ́lẹ̀ sí, bíi ìrìn-àjò, tàbí àwọn èyí àìlesọtẹ́lẹ̀, bí i owó ìjọba fún gbigba ìwé àkọsílẹ̀.

Ọ̀pọ̀ àwòṣe ló le ranni lọ́wọ́ pẹ̀lú ṣíṣe-ṣúná tí Rory Peck Trust ti pèsè.

Oníròyìn Oníwàádìí Emmanuel Freudenthal pín ìtalólobó rẹ̀ mẹ́fà lórí bí o ṣe le máa gbé gẹ́gẹ́ bí Aládàáni níbi Ìpàgọ́ Kọkànlá Iṣẹ́-ìròyìn Oníwàádìí Lágbàáyé. Fún ìṣirò àti ìṣọ́ ti ìnáwó, ó dábàá lílo ápùù bíi “SmartReceipts” àti “Waveapps” tàbí Excel.

Toby McIntosh jẹ́ olùbánidámọ̀ràn àgbà fún Ìkànnì Ohun-èèlò ti GIJN. Ó tún wà pẹ̀lú Bloomberg BNA ní Washington fún ọdún mọ́kàndínlógójì. Ó jẹ́ olóòtú tẹ́lẹ̀ ní FreedomInfo.org (2010-2017), níbi tí o ti kọ lórí àwọn ìlànà FOI káàkiri àgbáyé. Búlọ̀ọ̀gì rẹ̀ jẹ́ eyeonglobaltransparency.net.