Iṣẹ́-ìròyìn Àdáṣe: Ìṣedúró Ìgbáralé ènìyàn àti ìjọba fún ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròròyìn-jáde

Iṣẹ́-ìròyìn Àdáṣe: Ìṣedúró Ìgbáralé ènìyàn àti ìjọba fún ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròròyìn-jáde

Àwọn oníròyìn Oníwàádìí Àdáṣe gbọdọ̀ ro mímú iṣedúró síta dáadáa láti dá ààbò bo ara wọn kúrò ni ewu fífi ẹ̀sùn kanni.

Àwọn Ìlànà “Ìgbáralé Ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròyìn-jáde” jẹ́ ìsádi tó lòdì sí ìnáwó ọrọ̀-ajé ìfẹ̀sùnkanni fún ọ̀rọ̀ àkọsílẹ̀, ọ̀rọ̀ òdì, ìbanilórúkọjẹ́, ìjáwọlé ìdánikanwà-ẹni, ìjíwèékọ, ìrúfin ẹ̀tọ́-ìkọ̀wé, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Ìṣedúró le bo ìnáwó tó ga tó ṣeé ṣe àti àwọn ohun tó bàjẹ́ tó níṣe pèlú owó nípa àwọn gbólóhùn tó takò ó tàbí àwọn ìwọ̀fún tí-kìí-ṣe-ti-ilé-ẹjọ́.

Ìròyìn ayọ̀ ni pé àwọn aládàáṣe tí ó ṣiṣẹ́ fún ìgbéjáde-ìròyìn tí wọ́n dá sílẹ̀ máa ń sábà jẹ́ kíkójọ láti ọwọ́ ìlànà ìgbéròyìnjáde. Tí ó bá lérí pé o wà lẹ́yìn òun, ó dára jù; ṣùgbọ́n pẹ̀lú ìgboyà yẹn, àwọn ewu iṣẹ́ kan wà. A ó sọ̀rọ̀ nípa wọ́n níwájú.

Síbẹ̀ síbẹ̀, tí ọ̀ǹbúrẹ́là tó wà láárín kò bá bò ọ́, o lé lò ó (kì í ṣe láti sọ kókó) láti mú ìlànà tìrẹ jáde.

Àwọn ìlànà Oníròyìn Oníwàádìí tí wọ́n dínkù wà látara onírúurú  àwọn àjọ tuntun (ṣàpèjúwe nísàlẹ̀) pẹ̀lú ìkóròyìnjọ tó lódìwọ̀n.

Ohun-èèlò GIJN yìí pín sí ojú-àmúwayé méjì: Ìkóròyìnjọ ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròyìn-jáde, àti ìṣedúró ara-ẹni.

Nígbà tí o bá ń mú ìṣedúró ìgbáralé ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròyìn-jáde tí ara rẹ, àwọn wọ̀fún pọ̀ tó máa ń dani lọ́kàn rú. Ìdáhún tó tọ́ máa ń yàtò pẹ̀lú àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ kan ní pàtó àti ohun tí o lè lágbára.

Ìwàláàyè ìṣedúró ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròyìnjáde, àti pàtàkì rẹ̀, ó yàtọ̀ káàkiri àgbáyé. Àwọn àlàyé àkáùǹtì kúkurú dábàá pé àwọn aládàáṣe méjèèjì àti àwọn ẹgbẹ́ ilé-iṣẹ́-ìròyìn ní ọ̀pọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè ṣiṣẹ́ láìsí ìṣedúró ìgbáralé.

Fún àfikún àlàyé lórí ìfọ́nká, ìgbéga àti iṣẹ́ àdáṣe, yẹ Ìtọ́sọ́nà GIJN wa wò.

Síbẹ̀ síbẹ̀, nígbà mìíràn, oríṣìíríṣìí irúfẹ́ ìdáàbòbò máa ń wá. Àjọ Ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròyìn-jáde tí ó ṣe àtẹ̀jáde pẹ̀lú àsopọ̀ pẹ̀lú àwọnnn àjọ tó tóbi jù le jẹ́ bíbò nípa àwọn ìlànà wọn. Àwọn Agbẹjọ́rò tó ń gba àwọn oníròyìn nímọ̀ràn le ràn ọ́ lọ́wọ́ nípa ṣíṣe ìlérí ìdábòbò ọ̀fẹ́ tí ìwé-òfin bá wà.

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pe ọ̀pọ̀ àwọn ìròyìn nísàlẹ̀ jẹ́ ti ìnífẹ̀ẹ́sí àwọn ilẹ Amẹ́ríkà ti Àríwá, àwọn kókó àgbáyé wà ní ìrònú oníṣèdúró.

Bẹ́ẹ̀ ìṣedúró tó dára jù, àti pé èyí níṣe jákè-jádò àgbáyé, ni láti ní òye irúfẹ́ nǹkan tí ó lè kó ọ sí wàhálà.

Ìdáàbòbò fún àwọn Àjọ Ilé-iṣẹ́ Ìròyìn

Àwọn Àgbéjáde Ìròyìn Oníwàádìi Àdáwà náà nílò ìṣedúró ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròyìn-jáde àìgbáralé.

Àwọn èyí ni àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tó jọra tí àwọn aládàáṣe àti àwọn àjọ nílò láti mọ̀ nígbà tí wọ́n bá ń ra ìṣwdúró àìgbàralé.

Gẹ́gẹ́ bí Olùṣedúró ṣe máa ń yàtọ̀ fún ti iṣẹ́-ìròyìn oníwàádìí, àjọ ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròyìn-jáde nílò láti ṣètò ọ̀gbọ́n àkọ́rọ́yí láti sọ̀rọ̀ sí àwọn ìkanni wọ̀nyí.

Àwọn wọ̀fún fún àwọn àjọ wà ní ọ̀pọ̀ ọ̀nà tó jọra fún àwọn olúkúlùkù, fún ìdí èyí a ti gbé ọ̀rọ̀ náà yẹ̀wò síra níbí. 

Ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròyìn-jáde le pèsè ìkóroyìnjọ

Fún àwọn aládàáṣe, ìròyìn ayọ̀ ni pé ọ̀pọ̀ ìlànà ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròyìn-jáde máa ń bẹ̀bẹ̀ fún iṣẹ́.

Ó jọ pé bíbo olùṣiṣẹ́-aládèhún pẹ̀lú pẹ̀lú àwọn aládàáṣe, kò fi bẹ́ẹ̀ wọ́n fún ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròyìn-jáde, gẹ́gẹ́ bí olùbádúnáà oluṣedúró àti aṣojú ìṣedúró tí GIJN fi ọ̀rọ̀ wá lẹ́nu wò.

Bẹ́ẹ̀, dídábò bò àwọn aládàáṣe kì í ṣe aláìmọtara-ẹni-nìkan tán. Ṣíṣe bẹ́ẹ̀ máa ń dín àwọn óṣeéṣe tí kò bójú mu kù ti ìnáwó tí ó hànde sí àwọn aládàáṣe tí wọ́n ń dòwòpọ̀ pẹ̀lú àwọn ẹgbẹ́ yòókù ní ilé-ẹjọ́.

Ìkóròyìn-jọ le jẹ́ ọ̀kan pẹ̀lú olúkúlùkù. Àwọn ìlànà kan bèèrè fún ìgbéjáde ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròyìn-jáde láti pinnu láti gba òṣìṣẹ́ olómìnira; àwọn mìíràn gbà láti ṣe ìpinnu nígbà  tí ìlérí bá bẹ̀rẹ̀. Àwọn kan tilẹ̀ tún bèèrè lọ́wọ́ àwọn aládàáṣe láti gba ipele ojúṣe kan láti ri dájú pé wọ́n gba àwọn ífẹ̀míwéwu kan.

Tí atẹ̀wétà kan bá ṣèlérí ìdáàbòbò amòfin, ó gbọ́dọ̀ tún bèèrè ìbèérè. Ohun tó tọ́ ni láti bèèrè nípa àkókò àti ọ̀nà fún ìkóròyìn-jọ àti bí o bá lajú ní ọ̀nàkọnà. Bèèrè fún àtẹ̀jáde ìlànà, tàbí ó kéré tán ẹ̀hun tí ó ṣe pàtàkì sí ọ.

Tí ìgbéjáde ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròyìn-jáde bá sọ pé o ní ààbò, ó dára jù kí o ní ìlérí náà sí orí ímèèlì rẹ gẹ́gẹ́ bí ẹ̀rí, tàbí ẹ̀hun kan nínu àdéhùn.

Àwọn ohun tó nílò gbéra, kì í ṣe kókó ní ọ̀nà tó dára, nígbà ìdúnáàdúràá àdéhùn. Àwọn ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròyìn-jáde kan wá àwọn ẹ̀hun láti yọ ara wọn kúrò nínú ohun tí wọ́n nílò. Ó ṣeé ṣe láti dúnáàdúràá.

Ìyọkúrò Ìdúnàádúràá àti àwọn ẹ̀hun ojúṣe.

Àwọn ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròyìn-jáde kan máa ń yí àwọn ewu sórí àwọn aládàáṣe. Ìrugasókè si, ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròyìn-jáde fẹ́ “yọkúrò” ẹ̀hun láti dín iṣẹ́ kù lọ́rùn ara wọn bí ọ̀rọ̀ ilé-ẹjọ́ bá lọ yọjú nínú átíkù àti ẹ̀hun “Ojúṣe” láti mú àwọn òǹkọ̀wé sọ àjàgà tí wọn fipá mú lé wọn lórí. Àwọn ẹ̀hun yìí le léwu. Àwọn oníròyìn kọ̀ láti bu ọwọ́ lù wọ́n àti àwọn ìdúnàádúràá mìíràn.

Ìdí fún ìmúlọ́kàn yìí han kedere dáyè kan. Àwọn aládàáṣe díẹ̀ le san owó ìfẹ̀sùn-kan tó wọ́n, ká tó wá sọ àmì-ẹ̀yẹ ìfìyàjẹ ohun-tó-bàjẹ́.

Àwọn aládàáṣe jiyàn pé ìgbéròyìnjáde tó gbà wọ́n fún átíkù yìí àti tí ó bu ọwọ́ lù ú ni kí ó gbé ewu náà.

Fún àwọn oníròyìn tó kọ àwọn átíkù aláìlánìríìyànjiyàn, bíbu ọwọ́ lu àwọn àdéhùn pẹ̀ lú ìfisílẹ̀ àti ẹ̀hun ojúṣe le má ni ewu tó pọ̀, ṣùgbọ́n fún àwọn oníròyìn oníwàádìí, ewu ìnáwó tó jù le máa halẹ̀ mọ́ GIJN tó wá pẹ̀lú àwọn oníròyìn, àwọn agbẹjọ́rò àti àwọn àgbà-ọ̀jẹ̀ ìṣedúró láti jẹ́ kí ìmọ̀ràn wọn tó wa ní sàlẹ̀ múlẹ̀.

Ìlòdìsí le ṣiṣẹ́

Àwọn òǹkọ̀wé kan ti kọ̀ láti bu ọwọ́ lu àwọn àdéhùn pẹ̀lú irúfẹ́ àwọn ẹ̀hun adínilọ́wọ́ tí wọ́n sì borí.

“Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wí pé o le rí bákan láti sọ fún atẹ̀wéjáde láti yí ẹ̀hun kan padà, kò sí ewu bí o bá ṣe bẹ́ẹ̀, níwọ̀n ìgbà tí ó bá mú ọgbọ́n dání àti ìrònú,” Sara Tatelman kọ̀wé ní ọdún 2018 lórí Ìgbìmọ̀ Ìtàn ti ọmọ Kánádà, Ìtẹ̀wéjáde tí Ìtọ́sọ́nà Ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròyìn-jáde tí ọmọ Kánádà ṣẹ̀dá rẹ̀ àti Ẹgbẹ́ Àwọn Òǹkọ̀wé ti ọmọ Kánádà láti dá agbègbè prí-ìtàkùn ayélujára fún àwọn oníròyìn olómìnira àti àwọn aládàáṣe káàkiri Kánádá. Ó ti wá jẹ́ ìtẹ̀jáde ti Ìtọ́sọ́nà Àdáṣe ọmọ ilẹ̀ Kánádà.

Wọ́n le mú ìrẹ̀wẹ̀sì bá àwọn òǹkọ̀wé láti máa bá àwọn olóòtú tó lágbára àti pé wọ́n wá àwọn tí wọ́n tún dára wọn lójú. Ọ̀kan lára àwọn òǹkọ̀wé náà ni Lesley Evans Ogden, tí ó sọ ìrírí rẹ̀ ní Átíkù Ìgbìmọ̀ ìtàn tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ “Indemnity Clauses – The Wobbly Bridge of Freelancing.”

Dúnàádúràá sí Òdìwọ̀n ohun tó bàjẹ́

Wọ́n le dúnàádúràá Ìṣèyípadà láti pèsè ààbò sí ì.

“Má ṣe bẹ̀rù láti bèèrè àwọn òdìwọ̀n tí ó yẹ kó yípadà láàánú rẹ (àti pé wọn kò gbọdọ̀ fi ipá mú ọ láti gba àwọn òdìwọ̀n ìgbáralé tí o kò fara mọ́,)’ Michelle Guillemard kọ ọ́ nínú “Post for Health Writer Hub”.

Lẹ́ẹ̀kan si, eléyìí le níṣe pẹ̀lú ìlànà ìṣedúró ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròyìn-jáde, nítorí bẹ́ẹ̀ bèèrè nípa rẹ̀.

GIJN fọ̀rọ̀ wá àwọn agbẹjọ́rò, àwọn oníròyìn, àgbà-ọ̀jẹ̀ ìṣedúró lẹ́nu wò lórí kókó tí wọn yóò dúnàádúràá lé lórí. Èyí ni àtẹ atọ́ka tí wọ́n kó pọ̀ ti àwọn ìtalólobó GIJN:

 • Ṣe àfidípò-àbá tí ó ṣòdìwọ̀n ìgbáralé tó níṣe pẹ̀lú ìjọba àti ara-ẹni rẹ. (wọ́n máa ṣée ṣe kí wọ́n má jẹ́ àgbà ọ̀jẹ̀ láti rí ohun tó pọ̀ lára rẹ, ṣùgbọ́n ohun tó jẹ́ orí le ṣe ìrànwọ́.)
 • Ó máa ń jẹ́ kí òdìwọ̀n ìkóròyìn-jọ ti àgbéjáde sí ìṣòfin tó kẹ́yìn, pẹ̀lú ìkìlọ pé o kàn máa pa ẹ́ lára nìkan bí ìgbáralé rẹ̀ bá wà ní ìdásílẹ̀ àti tí gbogbo ẹ̀bẹ̀ ti tán.
 • Tí, bí i nígbà mìíràn ìṣẹ̀lẹ̀, èdè àdéhùn fẹ́ kí àwọn òǹkọ̀wé fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé átíkù náà kò ní àkọ́sílẹ̀ tí kò dára tàbí ìborúkọ-ẹlòmìíràn jẹ́, ó bèèrè pé àwọn olùyípada bí i “sí ìmọ̀ mi tó dára jù” gbọ́dọ̀ fi kún un.
 • Ó ṣe òdìwọ̀n ìgbáralé rẹ sí ohun tí o kọ, kì í ṣe ohun tí olóòtú kọ, tí ó ń yọ ọ́ kúrò nínú àwọn àṣìṣe rẹ gédégbé. Wọ́n mọ èyí sí “Ojúṣe ìfidípò tàbí káàkiri”.

Nísàlẹ̀ ni o ti le rí àwọn ìtalólobó tó dára fún ìdúnàádúràá, àti àwọn àlàyé sí i lórí ojúṣe ẹ̀hun:

 • “How to Deal with Warranty and Indemnity Clauses” láti ọwọ́ Pat McNees, lórí búlọ̀ọ̀gì àwọn òǹkọ̀wé àti àwọn olóòtú, ìmúdójú-ìwọ̀n ní ọdún 2015.
 • Ojúṣe-ẹni: “How to Reduce the reach of Yours” láti ọwọ́ Kendall Powell, Ẹgbẹ́ ti Orílẹ̀-èdè àwọn Òǹkọ̀wé Sáyẹ̀nsì ní ọdún 2009.
 • Àwọn Ẹ̀hun mẹ́ta tí àwọn Aládàáṣe gbọ́dọ̀ mọ̀ nípa (àti dúnàádúràá), Gẹ́gẹ́ bí àwọn Agbẹjọ́rò ní Maya Kroth, Àgbéyẹ̀wò Iṣẹ́-ìròyìn ilẹ̀ Kòlúḿbíà, ní ọdún 2018.
 • Kí gan ni Ojúṣe àti báwo ni ó ṣe bá aládàáṣe? Láti ọwọ́ Art Neill, Forbes, ọdún 2018.
 • Ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròyìn-jáde tó ń lọ bá àwọn agbẹjọ́rò ṣèdúró àwọn Aládàáṣe tó wò kánkán fún àwọn ẹ̀hun ojúṣe ní igbìmọ̀ ìtàn, ọdún 2018.
 • “Indemnity Clauses Leave Freelancers Open to Lawsuits” láti ọwọ́ Dawn Fallik àti Jonathan Peters, Poynter, ọdún 2015.
 • Ìrugasókè ní àwọn ẹ̀hun ojúṣe nínú Àdéhùn Àdáṣe ti Sara Tatelman, Ìgbìmọ̀ Ìtàn, ọdún 2018.

Gba Ìṣedúró Ìgbáralé Ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròyìn-jáde

Fún àtẹ̀jáde átíkù ara-ẹni, Àwọn aládàáṣe le fẹ́ ra ìṣedúró ìgbáralé ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròyìn-jáde ti wọn.

Ìfẹ̀lójú ìṣòro jẹ́ kí ó ṣeé gbani nímọ̀ràn, pàápàá jù lọ fún àwọn àjọ oníròyìn, láti gba ìrànlọ́wọ́ ti iṣẹ́.

Ìṣedúró “àwọn alárinnà” máa ń sábá níṣe láti ṣe ìrànwọ́ láti rí ìlànà tó tọ́. Wọ́n máa ń sábà gba owó láti ọwọ́ Olùṣedúró.

Wọ́n ṣèrànwọ́ láti fún àwọn ohun tó nílò ní oríkì. Wọ́n dúró gẹ́gẹ́ bí alárinnà, tó ń gba ọ̀rọ̀ àkọsílẹ̀ lọ́wọ́ olùpèsè ìṣedúró àti tó ń pèsè ìlànà ìtọ́sọ́nà láti rí wọ̀fún tó dára jù.

Ilé-ẹ̀kọ́ fún Ìròyìn Aláìfitèrè-ṣe ṣe sẹminá pẹ̀lú àgbà-ọ̀jẹ̀ ìṣedúró ọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà méjì tí ó pèsè àgbéyẹ̀wò tó dára jù lọ. Yẹ fídíò ọdún 2020 yìí wò láti ọwọ́ Chad Milton àti Michelle Worrall Tilton ti Olùṣàbẹ̀wò-sí Ewu Ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròyìn-jáde.

Átíkù ti ọdún 2017 ti àtúngbéyẹ̀wò iṣẹ́-ìròyìn Columbia. 

Àtúngbéyẹ̀wò Iṣẹ́-ìròyìn Átíkù “I’m a Freelance Journalist, Do I Need Liability Insurance? Láti ọwọ́ Annalyn Kurtz, òǹkọ̀wé ti ẹ̀kọ́-ọrọ̀-ajé tí ó tẹ̀dó sí ilẹ̀ New York àti Olóòtú.

Gbójú lé ọ láti dí áláfo ìwé-ìbẹ̀wẹ̀ fún iṣẹ́

Láti gba ìlànà kan, wọn yóò ni kí o dí àlàfo ìwé-ìbẹ̀wẹ̀.

Olùṣedúró máa fẹ́ mọ ohun tó pọ̀ nípa rẹ. Ó ṣeé ṣe kí wọ́n bi ọ́ nípa iṣẹ́ rẹ, bóya wọ́n ti gbé ọ rí, kí ni ohun tí ó ṣe láti ri àrídájú àwòmọ́ ìṣelóòtú, ọ̀rọ̀ nípa ìsúná rẹ, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

Jọra ṣùgbọ́n àwọn ọ̀rínkinniwín ìbéèrè ni wọ́n bi àwọn àjọ tí wọ́n fẹ́ gba ìṣedúró. (A o ṣe ìdàgbàsókè fún èyí lẹ̀yín wá.)

Àwọn ìdáhùn rẹ yóò jẹ́ kí ìṣirò ti olùṣedúró mọ àwọn ewu tí o laju sí. Ìpinnu yìí ṣèpalára ìlànà tí wọ́n fúnni, pàápàá jù lọ “premium” (èyí tí ó túmọ̀ sí, ohun tí o san).

Ríra ìṣedúró ìgbáralé le dúró fún àwọn ìpinnu onífunra tó ju ohun tí o san. Ipele “Owo Ìgbani” tún wà (Ohun tí olùṣedúró kò san lorí àlàyé), sí bẹ́ẹ̀ pe ìdínkù. Èyí ni kọ́kọ́rọ́ pàtó tí ó iye rẹ faragbá.

Ìlànà-ìrònú tó ṣe pàtàkì mìíràn ni òdìwọ̀n pátá ti ìgbáralé (èyí tó jù tí olùṣedúró yóò san). Ó máa ń sábá jẹ́ mílíọ̀nù dọ́là kan, ṣùgbọ́n ní ọ̀pọ̀ ìgbà ó ga si. Àwọn ipele tó ga jù máa ń ran owó tí o san.

Àwọn nǹkan pọ̀ láti rò, bí i:

 • Àwọn ewu tán bò? Àwọn àtẹ atọ́ka le rí bí i pé ó gùn, àṣìṣe, àkọsílẹ̀-irọ́, àlàyé-èké, ìfetíkọ́, ìkọjá-ààyè, ìgbéni, Ìjawọ́-ìdáwá-ẹni, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Ṣùgbọ́n ṣé ó pé?
 • Ohun tí wọn ò bò? Gédégbé “Ìyọkúró” ni àwọn nǹkan bí Iṣẹ ọ̀daràn àti ìfigagbága ìlùfin, ṣùgbọ́n ó tó ìṣàtúngbéyẹ̀wò àtẹ dáadáa.
 • Ṣé ó bo gbogbo irúfẹ́ ìṣètẹ̀wéjáde, bí ètò pódíkáásìtì?
 • Ṣé o ó di bíbò bí wọ́n bá fẹ̀sùn kàn ọ́ ní òkè-òkun?
 • Ta ló pinnu pé ìyanjú tí kì í ṣe ilé-ẹjọ́ di gbígbà? (Ẹ̀hun kan le jẹ́ kí olùṣedúró kan fipá mú ọ láti gba ìyanjú.)
 • Ṣe ìlànà-adárí náà bo àwọn ohun tó bàjé tó ní ìjìyà?
 • Ṣé o bò fún àwọn àlàyé òótọ́ tó lòdì sí ọ, kì í ṣe nígbà àkókò ìlànà-ìdarí nìkan ṣùgbọ́n fún owó tó lòdì sí ọ pẹ̀lú fún ohun tí ó ṣẹlẹ̀ kó tó di àkókò ìlànà-ìdarí (ìṣedúró oníṣẹ̀lẹ̀)?
 • Ṣé wọn yóò yọ àwọn ìnáwó ààbò òfin kúro nínú ìlànà-ìdarí gbèdéke?
 • Ṣé o le mú Agbàmọ̀ràn òfin rẹ?
 • Ṣé gbèdéke sí owó òfin ní wákàti wákàtí wà?
 • Ṣé ìlànà-ìdarí olùṣedúró ní ààbò ètò-ìsúná?
 • Ṣé ìlànà-ìdarí bo ìbẹ̀wò-òfin àgbéjáde tó ṣáájú, bí i ìdíje fún àṣẹ-àkọọ́lẹ̀ láti múni tàbí ìpamọ́ kúró lọ́wọ́ ìgbìyànjú láti dí ìgbéjáde lọ́wọ́?
 • Àwọn olùṣedúró kan bèrè kí ó gba agbẹjọ́rò láti ráyè sí ìṣeéṣe láti fẹ̀sùn kàn ọ́ àti kí agbẹjọ́rò náà kọ ìjábọ̀ sí olùṣedúró kí ó tó má a ṣe ìlànà-ìdarí. Ìnáwó èyí le jọnilójú gidi.
 • Ìgbà wo ni wọ́n le wọ́gi lé ìlànà-ìdarí.

Mú ìṣedúró síta gẹ́gẹ́ bí àjọ iṣẹ́-ìròyìn oníwàádìí

Iṣẹ̀-ìròyìn oníwàádìí “le máa bani lẹ́rú” fún àwọn olùṣedúró, àgbà-ọ̀jẹ́ tí GIJN ṣàbẹ̀wò sí ló sọ èyí. “Kò pọ̀ bí o bá má a gba ìgbénilọlé-ẹjọ́, ṣùgbọ́n ìgbà wo lo ó gbà á,” Olùdarí àgbà ilé-iṣẹ́ ìṣedúró kan ló sọ bẹ́ẹ̀.

Nítorí àdánú tòótọ́ sí olùṣedúró, àwọn àjọ iṣẹ́-ìròyìn oníwàádìí le retí ìwádìí ìjìnlẹ̀ láti ọwọ́ àwọn alárinnà ìṣedúró tàbí olùṣedúró tòótọ́.

Ní ìdáhùn sí ìbéèrè yìí, ilé-iṣẹ́ ìṣedúró kan kọ:

“ohun tí a ó nílò láti sún síwájú pẹ̀lú ìgbéléwọ̀n nì wọ̀nyí:

 • Àpèjúwé kúkurú ti ètò àjọ rẹ, ìrànwọ́, àti àfojúsùn iṣẹ́-ìròyìn rẹ.
 • Ìdàkọ kan àwọn àlàyé ètò-ìsúnà rẹ tí ẹ jábọ̀ jù láìpẹ̀ yìí.
 • Ìdàkọ ìlà iṣolóòtú rẹ kan
 • Ìdàkọ Ìṣàbójútó ìbẹ̀wò-òfin/ àwọn ìlànà ìtọ́sọ́nà ìsáyelé òfin.”

Àwọn Alárinnà Ìṣedúró, Àwọn Olùdarí Àgbà Ìṣedúró, àti àwọn mìíràn ṣè dààmú tí olùbẹ̀wẹ̀ ìṣedúró gbọ́dọ̀ sọ̀rọ̀ sí fínnífínní ohun tó kan àwọn olùṣedúró. Àwọn Àbá wọn kan ni:

 • Dájọ́ dáadáa nígbà tí o bá ń ṣàpèjúwe iṣẹ́ rẹ àti àwọn àfojúsun rẹ. Yẹra fún ìgbéraga.
 • Ó sọ sí ìkọ́ni oníròyìn àti ìrírí rẹ̀.
 • Ṣàjọsọ bóyá o ó lo àwọn ìlànà ìwádìí tó ní ewu ó ga, bi iṣẹ́ abẹ́lẹ̀, ó sì dúrò lórí ohun tó darí.
 • Ṣàpèjúwé ìlànà ìṣàtúngbéyẹ̀wò iṣolóòtú, pàápàá jù lọ ìlànà-adarí fún àyẹ̀wò kíákíá.
 • ṣàlàyé àwọn ọ̀nà fún ìbẹ̀wò òfin ti ìta tàbí abẹ́nú.
 • Ní àwọn agbẹjọ́rò ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròyìn-jáde ìgbáralé tó dára láti gbà ọ́ nímọ̀ràn, fífẹ́ ẹ pẹ̀lú ìrírí ìbẹ̀wò-òfin.
 • Ó sọ ìtàn kíkún àti ìdápàárá ìtàn nípa ìbẹ̀wò-òfin ti tẹ́lẹ̀.

Ẹ̀hun kan tí ó le fa ìkónilọ́kàn kan pàtó sí àjọ ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròyìn-jáde oníwàádìí kan ẹni tí ó gbà sí ìyànjú. Èyí ní ibi tó múlẹ̀ tí àwọn olùṣèdúró fẹ́ràn láti gé àwọn gbèsè àti àwọn oníròyìn láti dábòbo àra wọn lọ́wọ́ olùfẹ̀sùn-kanni. Àwọn ẹ̀hun tó fipa láti gba àdéhùn fún àwọn àwọn olùṣèdúró láǹfààní ní àwọn ìpinnu wọ̀nyẹn, ṣùgbọ́n ní ọ̀pọ̀ ìgbà wọ́n le yẹra fún wọn, gẹ́gẹ́ bí àwọn àgbà-ọ̀jẹ̀ ṣe sọ, tàbí wọ́n le dúnáàdúràá ìlànà wọn. Àwọn Ẹ̀dá, fún àpẹẹrẹ, wọn le sọ pé àwọn tí wọn ti ṣèdúró fún máa san owó kan tó ju ipele kan lọ.


Àwọn ẹgbẹ́ tí ó ń fúnni ni ìṣedúró Ìgbáralé Olúkùlùkù

Àwọn àjọ iṣẹ́-ìròyìn tó mọ iṣẹ́ nígbà mìíràn wá láti ran àwọn ọmọ ẹgbẹ́ wọn lọ́wọ́ nípa dídá ìdàpọ̀-ọ̀rẹ́ sílẹ̀ pẹ̀lú olùpèsè ìṣedúró. Fún àwọn àjọ ìròyìn olómìnira ní Gúúsù Amẹ́ríkà, Ilé-ẹ̀kọ́ fún Ìròyìn Aláìfitèrè-owó-ṣe wá láti ran àwọn ọmọ ẹgbẹ́ lọ́wọ́ pẹ̀lú ìgbáralé ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròyìn-jáde. Àwọn INN ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú onírúurú àwọn olùpèsè ìṣedúró, fúnni ní ìṣàbẹ̀wò ọ̀fẹ́ wákàtí kan pẹ̀lú olùgbaninímọ̀ràn ìṣedúró kan, ó sì fúnni ni ìmọ̀ràn àti ẹ̀kọ́ lórí kókó ọ̀rọ̀. Níbí o lè ka ọ̀rínkinniwín àlàyé si.

Fún àwọn aládàáṣe àwọn ìfúnni tó jọra wà, ṣùgbọ́n kì í ṣe dandan kó mú ìmọ̀lára ohun tó nílò dání ti iṣẹ́-ìròyìn oníwàádìí.

Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ti “The Authors Guild” tí ó jẹ́ àwọn ìwé òǹkọ̀wé ti ilẹ̀ Amẹ́ríkà tọ́ fún ètò ẹgbẹ́ ìdúnàádúràá pàtó àti kí wọ́n gba ìṣedúró ìgbáralé ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròyìn-jáde “Ìyọkúrò oníkókó” látara AXIS PRO, ilé-iṣẹ́ ìṣedúró Kansas City Missouri. “The Authors Guild”owó tí wọn yóò san ní ọdún 2020 ni $135 lọ́dọọdún (tàbí $100 fún àwọn òǹkọ̀wé tó ń ga.) AXIS PRO le pèsè àwọn ìlànà-adarí tí ó bo ìlérí fún àkọsílẹ̀-ìbanilórúkọ-jẹ́, ìjálú-ìdáwà-ẹni, ẹ̀tọ́-ìdàkọ tàbí ìrúfin ìbọwọ́lù, ìjíwèékọ, àṣìṣe àti ìfisílẹ̀, àti àwọn ewu tó níṣe mìíràn.

“The National Federation of Press Women” ní “United States” fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ rẹ̀ ní ìlànà-ìdarí ìdínkù látara “Walterry Insurance Brokers” àti “Chubb Specialty Insurance”. Igun ìkóròyìn-jọ ìgbáralé ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròyìn-jáde” wọn jẹ́ $495 lọ́dún.

Ní Kánádà, ìjọ́mọ-ẹgbẹ́ ní Àdaṣe CMG pẹ̀lú ìrááyè sí ìṣedúró àwọn àṣiṣe àti ìfisílẹ̀, ṣùgbọ́n ìlànà ìpìlẹ̀ kò bo “àwọn òǹkọ̀wé tó kọ tàbí ṣàtẹ̀jáde oníwàádìí tàbí àkóónú ìlànà gangan…”

Òlúgbé tó ń darí ìṣedúró ìgbáralé ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròyìn-jáde ní United States ni AXIS PRO, AIG, CapSpecialty, Chubb, CNN, Hiscox, Mutual Insurance Company Ltd. (Bermuda), OneBeacon, Philadelphia, àti QBE.

Owó ìkẹ́kọ̀ọ́ pèsè àtúngbẹ̀wò

Pípèsè owó tún le ṣini lọ́nà; àwọn àgbà-ọ̀jẹ̀ tẹnumọ́ ìyípadà owó fún ọ̀pọ̀ ìyẹ̀dà, bí i iṣẹ̀ tó ti dúró àti àwọn ìlànà kan pàtó ti ìlànà-ìdarí. Fún àwọn àjọ ìròyìn ìnáwó wọn máa ń yàtọ̀ dáadáa, ó dálé àkóónú gangan àti irúfẹ́ iṣẹ́-ìròyìn. Fún ẹgbẹ́ ìròyìn kékeré ní United States, owó tí wọ́n san lọ́dún tó kéré ju ni $2,500 ní tòròtòrò ọdún 2020, gẹ́gẹ́ bí alárinà ìṣedúró àti àwọn àgbà-ọ̀jẹ̀ ilé-iṣẹ́.

Àwọn Ìnáwó Aládàáṣe máa ń farahàn láti abẹ́ $1,000, gẹ́gẹ́ bí àwọn tí wọ́n fi ọ̀rọ̀ wá lẹ́nu wò láti United States, Kánádà, àti Australia, Annalyn Kurtz ṣàlàyé ní átíkù CJR lórí ẹ ní ọdún 2017 tí ó ri pé ìnáwó yàtọ̀:

Méjì nínú olùpèsè ìṣedúró agbáralé ni Axis Pro àti Hiscox, àwọn méjèèjì ni wọ́n fẹ́ kọ ìlànà-ìdarí fún àwọn oníròyìn àdáṣe ní àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ kan ní pàtó. Nígbà tí mo dí àlàfo inú ìwé-ìbẹ̀wẹ̀, Axis Pro sọ pé owó sísan bẹ̀rẹ̀ láti 4718 fún $250,000 ti ìkóròyìn-jọ, sí $1,049 fún $1,000,000 ìkóròyìn-jọ.

Matt Knight, òǹkọ̀wé àdáṣe àti agbẹjọ́rò tólọ́gbọ́n ohun-ìní, jabọ̀ ní ọdún 2018 pé owó tán san le bẹ̀rẹ̀ láti $1,000 sí 42,500 lọ́dọọdún pẹ̀lú ìdínkù ti $3,000 sí $5,000. 

Ìlànà-ìdarí ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròyìn-jáde Guild ti ọmọ ilẹ̀ Kánádà fikún àtẹ wọn pẹ̀lú owó tán san lọ́dọọdún ti CAD300 fún CAD100,000 àwọn àṣiṣe àti ìfisílẹ̀ ìdáàbòbò, àti ó tó CAD850 fún CAD mílíọ̀nù kan ní ìkóròyìn-jọ, ṣùgbọ́n ìlànà-ìdarí kò bo ìwádìí iṣẹ́-ìròyìn ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́. Ohun-ẹgbẹ́ fún olùpèsè, ẹgbẹ́ Beazley, sọ pé owó sísan yàtọ̀ èyí tí ó dálé ìṣẹ̀lẹ̀ olúkúlùkù.

Michelle Guillemard, ní Ìgbésórí-ìkànnì ayélujára fún òǹkọ̀wé ìlera ti ìmúdójú-ìwọ̀n níọdún 2020, sọ pé ìlànà ìdarí ìṣedúró ojúṣe ní Australia bẹ̀rẹ̀ láti A$1,000 (èyí tí yóò jẹ́ US$700) lọ́dọọdún.