Fífí-ìdí-òdodo-múlè̩ & Àrídájú

Guide to Fact-Checking Investigative Stories  ti GIJN láti o̩wó̩ Nils Hanson (2021)

Four Quick Ways to Verify Images on a Smartphone ti GIJN láti o̩wó̩ Raymond Joseph. (2021)

Making Stories Ironclad & Bulletproof Line-by-Line, láti o̩wó̩ Nils Hanson, e̩ni tí ó ti fi ìgbà kan rí jé̩ asàtùnkó̩ ìrò̩yìn o̩ló̩fintótó fún Swedish Television. Ìwòye ojú-inú sí wíwádìí òdodo àti ìdira ní ilé-ìròyìn s̩aájú sís̩e àtè̩jáde tàbí àgbéjáde, tí a s̩e àgbékalè̩ rè̩ ní Global Investigative Journalism Conference (2019).

AFP Fact Check Training, fídíò oní è̩yà mé̩wàá tí ó sò̩rò̩ lórí ìròyìn èké, ìfìdí-òdodo-múlè̩ àti ibùgbé (2021).

Verification and Digital Investigations Resources, àko̩sílè̩ kíkún fún àwo̩n ohun èlò tí Craig Silverman s̩e àgbékalè̩ ní BuzzFeed ní IJAsia18, èyí tí ó máa ń s̩e àfikún sí, tí ó sì ń mójú tó.

The Verification Handbook dá lórí ò̩pò̩ àkórí pè̩lú ìpinnu láti jé̩ “ò̩nà gbòógì láti s̩e àgbéyè̩wò àkóónú orí ayára-bí-às̩á fún ìkásílè̩ pàjáwìrì”. Àtúnko̩ láti o̩wó̩ Silverman tí ó sì jé̩ kíko̩ láti o̩wó̩ àwo̩n onís̩é̩-ìròyìn láti BBC, Storyful, ABC, Digital First Media àti ibòmìíràn. Tún s̩e àyè̩wò The Verification Guide for Investigative Journalists and Verification Handbook: Additional Materials. Láti s̩e àgbàkalè̩ tàbí ra gbogbo wo̩n, wo àwo̩n tí a ti túmò̩, te̩ ibí.

Guide to Using Reverse Image Search for Investigations ti Bellingcat (2019).

Introduction to OSINT Video: Fídíò tí ó jáde ní o̩dún 2020 láti o̩wó̩ OSINT Curious.

Verifying Online Information Ató̩nà o̩dún 2019 láti o̩wó̩ Shaydanay Urbani, òǹkò̩wé àti oníròyìn ìwádìí ní First Draft, tí wo̩n s̩e àlàyé gé̩gé̩ bí “àtó̩nà kékeré re̩ sí àjé̩ ìfìdí-òdodo-múlè̩”. Ó tún ní àkóónú “àwo̩n ìsmò̩ pàtàkì, àgbéyè̩wò àti àwo̩n ètè àti ilànà tí a fé̩ràn”. Ó máa ń lo “ò̀pó ìfìdí-òdodo-múlè̩” márùn-ún: ìfúnni, orísun, déètì, ibùdó, àti ìwúrí.

Social News Gathering and Verification, láti o̩wó̩ Ayla Mashkoor àti  Rachel Blundy láti Storyful ní Hong Kong.

Six Fake News Techniques and Simple Tools to Vet Them, láti o̩wó̩ Olga Yurkova, olùbádásílè̩ StopFake ní Ukraine. Ó s̩e àlàyé àpe̩e̩re̩ jìbìtì mé̩fà pè̩lú àwo̩n ìlànà lé̩se̩e̩se̩ lórí fífi-ìdí-òdodo nípa òtító̩ tàbí ìró̩ wo̩n. 

What to Watch for in the Coming Wave of “Deep Fake” Videos,  láti o̩wó̩ Samantha Sunne, s̩e àgbéyè̩wò àwo̩n fídíò̩ tí wo̩n jo̩jú tí ó s̩e àfihàn líle̩ ara e̩nìkan mó̩ ti e̩lòmìíràn.

How to Spot Fake Images Anywhere on the Internet, láti o̩wó̩ Henk van Ess, tí a tè̩ jáde ní o̩dún 2019 láti o̩wó̩ Poynter. Ó tún ko̩ 100 Tools and Tricks to Verify Instagram Posts.

9 Tools for Verifying Images láti o̩wó̩ Molly Stellino ti International Journalists’ Network.

Satellite Images and Shadow Analysis: How The New York Times Verifies Eyewitness Videos

Six lessons from my deepfakes research at Stanfordláti o̩wó̩ Tom Van de Weghe ní 2019, tí ó mójú tó, “Báwo ni kí àwo̩n onís̩è̩-ìròyìn ó s̩e dojú ko̩ ìs̩òro ìròyìn aláìlé̩sè̩nílè̩ tó ń gbèrú sí. 

How The Wall Street Journal is preparing its journalists to detect deepfakes, àko̩sílè̩ Nieman Labs ní o̩dún 2018.

These New Tricks Can Outsmart Deepfake Videos—For Now, àko̩sílè̩ alátè̩ráns̩é̩ láti o̩wó̩ Sarah Scoles ní o̩dún 2018.

Deepfake-busting apps can spot even a single pixel out of place, àròko̩ lórí àwo̩n ìlànà tuntun, àròko̩ tí ó s̩e àgbéyè̩wò lórí ìmò̩-è̩ro̩ láti o̩wó̩ Karen Hoa.

Calculating time using clues within a Google Streetview scene, àròko̩ o̩dún láti o̩wó̩ oǹkò̩wé tí ó kàn ń pe ara rè̩ ní “just a shadowy nerd” tí ó sì tún ń jé̩ Sector035.

How to Fact-Check Politics in Countries with No Press Freedom, láti o̩wó̩ Daniel Funke.

How 90 Outlets Are Working Together to Fight Misinformation Ahead of Mexico’s Elections, láti o̩wó̩ Joseph Lichterman, s̩e àlàyé bí e̩gbé àwo̩n àjo̩ oníròyìn àti àwo̩n e̩gbé̩ ìlú s̩e pa ara pò̩ ní ìbè̩rè̩ o̩dún yìí láti s̩e ìfiló̩lè̩ Verificado 2018, àjo̩s̩epò̩ ìgbìyànjú fún ìfìdí-òdodo-múlè̩.

Argentina’s Chequeado Becomes Global Leader in Fact-Checking, láti o̩wó̩ Ismael Nafría, wo̩ inú ìtàn Chequeado àti bí ó s̩e ń sis̩é̩.

Fact-Checking and Verification, ojú-ewé mé̩fà tó kún láti o̩wó̩ from Raymond Joseph, onís̩é̩-ìròyìn adás̩é̩-s̩e àti olùkó̩ kláti ilè̩ South Africa tí ó s̩e àgbékalè̩ ní Global Investigative Journalism Conference (GIJC17) o̩dún 2017. Ó ti fi ìgbà kan rí jé̩ as̩àtúnko̩ fún Big Issue South Africa, tí ó bá wo̩n s̩e ìfiló̩lè̩ ní 1996.

3 Quick Ways to Verify Images On a Smartphone. E̩ má s̩àì rí àtó̩nà Joseph tí ó gbajúmò̩ gan lórí sís̩e ìfìdí-òdodo-múlè̩ fún àwo̩n ohun tí ó ń be̩ ní orí è̩ro̩ alágbèéká re̩. Èyí jé̩ ò̩kan nínú àwo̩n ohun èlò mé̩wàá GIJN tí ó wúlò jù.

How to Be a Digital Detectiveàko̩sílè̩ atanilólobó GIJC17 láti o̩wó̩ Joseph. Ó sò̩rò̩ nípa bí a s̩e lè dá ìròyìn èké mò̩ àti láti s̩e àgbékalè̩ àwo̩n ìgbésè̩ tí ó gbo̩n-n-gbó̩n láti gbé.

, àko̩sílè̩ tí ó kún fún àwo̩n ò̩nà ìwádìí gbangba àti àwo̩n ohun àlò ìwádìí pè̩lú ìlànà.

Getting Started in Online Open-Source Investigations láti o̩wó̩ Eliot Higgins ti Bellingcat, mójú tó àwo̩n èròjà ìs̩ípòpadà.

Prepublication Quality and Control,  láti o̩wó̩ Nils Hanson, àko̩sílè̩ atanilólobó GIJC17 láti o̩wó̩ olùs̩àtúnko̩ àgbà fún Mission Investigate (Uppdrag Granskning), as̩ojú ètò ò̩fintótó ní Swedish Public Television (SVT).

How to Monitor Social Media for Misinformation, láti o̩wó̩ Nic Dias, onís̩é̩-ìròyìn orí ayára-bí-às̩á àti olùwádìí àgbà fún First Draft.

Advanced Guide to Verifying Video Content, láti o̩wó̩ Aric Toler, olùwádìí àgbà àti olùkó̩ni láti ilè̩ Eastern Europe/Eurasia ní @bellingcat.

The International Fact-Checking Network wà ní the Poynter Institute. Wo̩n máa ń s̩e àtè̩jáde ìròyìn ò̩sò̩ò̩sè̩, wo̩n sì tún s̩e è̩dá Code of Principles ti fact-checkers.

How To Start Up a Fact-Checking Group, láti o̩wó̩ Santiago Sánchez, s̩e àpéjúwe ìtàkurò̩so̩ kan ní 2017 pè̩lú àwo̩n onímò̩ láti Argentina, Colombia àti Uruguay tí ó gbójú lé sís̩e àgbéjáde àwo̩n àkàns̩e is̩é̩ tí ó máa ń fi ìdí-òdodo múlè̩.

A Global Guide to Initiatives Tackling “Fake News,” àko̩sílè̩ àwo̩n ohun èlò ìfìdí-òdodo-múlè̩ tí Fergus Bell s̩e àgbékalè̩, e̩ni tí ó jé̩ onís̩é̩-ìrò̩yìn o̩ló̩pò̩-igun tí ó ń s̩e àkóso Dig Deeper Media.

A Guide to Verifying Digital Content in Emergencies (2014) láti o̩wó̩ Craig Silverman àti Rina Tsubaki.

How Not to Be Wrong, láti o̩wó̩ Winny de Jong, onís̩é̩-ìròyìn aládàás̩e àti olùkó̩ni.  “At the intersection of data and journalism,” ó bè̩rè̩, “lots can go wrong.”

Four free online plagiarism checkers, àròko̩ IJNet, sò̩rò̩ nípa GrammarlyNoPlagPlagiarism Checker àti CopyLeaks.

Get Your Facts Straight: The Basics of Fact-Checking, láti o̩wó̩ Deepak Adhikari, alátúnnkó̩ fún South Asia Check, tí ó jé̩ ara Exposing the Invisible ti Tactical Tech , ató̩nà sí ìwádìí ará-ìlú.