tí wọ́n sì tún gbé ètò ìdáni lẹ́ẹ̀kọ́ kan kalẹ̀ lórí ohun èlò alágbè ká. Pẹ̀lú ìlànà lórí bí wọ́n ṣe fàràn tó jíire kalẹ̀, and ṣíṣe àtúntọ̀ rẹ̀ lórí ẹ̀rọ ìbáni sọ̀rọ̀ alágbè ká àti láti sọ ìtàn tí yóò mú orí yà pẹ̀lú àgbékalẹ̀ tó jíire, gbogbo rẹ̀ ni ìgbésẹ̀ yìí kò ní àkórán.
Àgbékalẹ̀ ètò ìkọ́ni lórí ààbò lórí Ìròyìn láti ọwọ́ James W Foley, ni wọ́n ṣe àgbékalẹ̀ rẹ̀ láti ṣe àfihàn ètò ẹ̀kọ́ṣẹ́ ìròyìn àti ètò ìkànsíraeni sí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ lórí ètò ààbò gẹ́gẹ́ bíi ohun tó ṣe gbòógì fún iṣẹ́ ìròyìn. Àgbékalẹ̀ ètò ìkọ́ni yìí wá láti ọwọ́ Ìgbìmọ̀ James W. Foley Legacy Foundation, pẹ̀lú ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ilé ẹ̀kọ́ Fáṣítì ìkànsíraeni Marquette Diederich. Ìlànà ètò ẹ̀kọ́ olópòó mẹ́rìndínlógún yìí bojú wo àkọlé oríṣiríṣi, èyí tí kò yọ àgbéyẹ̀wò ewu
ojúṣe àwọn alákòóso yàrá ìkóròyìn jọ, ó ààbò tó péye fún àwọn oníròyìn obìnrin àti àwọn oníròyìn kéékèèké tí wọ́n ń kojú ìfẹ̀húnú hàn, kíkó ìròyìn jọ lásìkò àjàkálẹ̀ àrùn, ìtọ́jú lórí à ì ibalẹ̀ ọkàn, ìfọ̀rọ̀werọ̀ pẹ̀lú àwọn tí ara ń kan, kíkó ìròyìn jọ lórí ọ̀rọ̀ ilẹ̀ òkèèrè, dídá ààbò bò dátà lórí ẹ̀rọ ayélujára àti kíkó ìròyìn jọ lórí ìṣẹ̀lẹ̀ bí ojú ọjọ́ ṣe rí. Nípasẹ̀ èyí, àwọn akẹ́kọ̀ọ́ yóò rí dídá ààbò bo ara wọn gẹ́gẹ́ bíi ohun tó ṣe gbòógì, tó mú ìlera lọ́wọ́ pẹ̀lú tí tẹ̀lé òfin tó rọ̀ mọ́ iṣẹ́ ìròyìn. Ìgbìmọ̀ James W Foley ní àlà kalẹ̀ lórí onírúurú ọ̀nà fún ìdáàbò bo ara ẹni.