gijn-logo

Empowering Independent Media

Ríró àwọn ilé iṣẹ́ ìròyìn aládàńi ní agbára: Ìlàkàkà ilẹ̀ Amẹ́ríkà láti fún àwọn ilé iṣẹ́ ìròyìn ní ààyè láti ṣíṣe láì ní ìdíwọ́ àti ẹ̀rọ ayélujára jákèjádò orílẹ̀ èdè agbègbè gbogbo: Fífi ojú inú wo ìdàgbàsókè ilé iṣẹ́ ìròyìn, àròkọ yìí èyí tí yóò wúlò fún àjọ tí kò wá fún èrè jíjẹ àti àwọn eléyinjú àánú láti mú ìdàgbàsókè bá orílè èdè. Ìwé yìí bojú wo àwọn ọ̀nà méje tó ṣe gbòógì: ìrànwọ́ ọwọ́, ìròyìn lọ́nà ti ìgbàlódé, fífi ẹsẹ̀ dúró ṣinṣin, òfin tó rọ̀ mọ́ iṣẹ́ ìròyìn, ààbò, ètò ẹ̀kọ́, àmójútó àti ìmọ̀ràn. Èdè tí Wọ́n fi kọ́ọ́: Gẹ̀ẹ́sì, Spanish àti Faransé. 

Wíwà ohun èlò fún àwọn oníròyìn lórí gọ́gù: Ìwé pèléńbé yìí bojú wo àwọn ìlànà tí yóò jẹ́ kó rọrùn láti ṣe iṣẹ́ ìwádìí lórí gọ́gù. Èyí tí Experistisefinder.com ṣe àkójọpọ̀ rẹ̀. 

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *