Reporting in Indigenous Communities
Ìròyìn ní èdè agbègbè jẹ́ èyí tí akọ̀ròyìn pẹ̀lú ilé iṣẹ́ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ ìlú Canada, Duncan McCue gbé jáde lọ́dún 2011. Ó ń àwọn èròjà láti kọ ìròyìn lédè abínibí jákèjádò…
Ìròyìn ní èdè agbègbè jẹ́ èyí tí akọ̀ròyìn pẹ̀lú ilé iṣẹ́ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ ìlú Canada, Duncan McCue gbé jáde lọ́dún 2011. Ó ń àwọn èròjà láti kọ ìròyìn lédè abínibí jákèjádò…
(PDF): Ilé iṣẹ́ tó ń rí sí sí iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn, àkọ́kọ́ irú rẹ̀ ní àgbáyé tí won kò fi dá oko òwò, èyí tó ń rí sí “iṣẹ́…
Ilé Ẹ̀kọ́ Fáṣítì Illinois ń ṣe Ìgbanisíṣẹ́ sí Ipò Ọ̀gá Àgbà èyí tí yóò jẹ́ Alárinà Láàárín àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ fún Ìmọ̀ Ìròyìn àti Àwọn Akọ́ṣẹ́mọsẹ́ Láti ọwọ́ Jelter Meers |…
Ìtalólobó àgbà-ọ̀jẹ̀ fún wíwú gbòǹgbò ìròyìn-èké Láti ọwọ́ Maurice Oniang’o | ọjọ́ kẹtà-lé-lógún oṣù kọkànlá, ọdún 2021 Fún àwọn oníròyìn aṣèwádìí tí wọ́n ń wú ìpòlongo tí ìròyìn tí kò…
Onírúurú ìkànnì tí ìdàgbàsókè ti débá ló wà tí ó ń ran àwọn òǹkọ̀wé lọ́wọ́la ti owó nípaṣè ìgbéjáde-ara-ẹni. Yàlá àwọn wọ̀nyí tọ̀nà fún ọ èyí yóò gbà ìwádìí. Ní…
Iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn: Ohun èlò fún àwọn oníròyìn: ìwé atọ́ni sónà olójú ewé ọgọ́rùn-ún ó lé méje èyí tí ilé iṣẹ́ Amẹ́ríkà tó ń rí sí oko òwò aládàńi…
Ilé Ẹ̀kọ́ Fáṣítì Illinois níbi tí wọ́n ti ń fi Ẹ̀dùn Ọkàn hàn Nípa Àjàkálẹ̀ Àrùn COVID-19 àti bí wọ́n ṣe ń ń polongo bí àwọn ènìyàn ṣe ń lòdì…
Àwọn òǹkà yẹn jẹ́ ohun ìkorò fún àwọn akẹgbẹ́ wa káàkiri àgbáyé. Gẹ́gẹ́ bí aṣojú àwọn oníṣẹ́-ìròyìn ìfẹ̀hónú hàn ṣe sọ, láti 1992, àwọn oníròyìn tí ó ju egbèje (1,400)…
Abraji’s Security Manual fún kíkó ìròyìn lópòópónà jọ lórí ìfẹ̀hónú hànKíkó Ìròyìn Lópòópónà Jọ Lórí Àwọn Tó Ń Fẹ̀họ́nú Hàn. Kíkó ìròyìn jọ lórí ìfẹ̀hónú hàn lóri pópó níṣe pẹ̀lú…
Láti ọ̀dọ Rowan Philip | ọjọ́ kẹtà-dín-lógún oṣù karùn-ún, Ọdún 2021 Harvey Weinstein lẹ́yìn ìgbà tí ó fara hàn ní Ilé-Ẹjọ́ ní New York. Wọ́n padà sọ ọ́ sí ẹ̀wọ̀n,…