Verification Handbook
Ìwé Ìléwọ́ Ìṣàmúdájú jẹ́ ìwé àmúlò fún àwọn oníròyìn àti àwọn tó ń ṣe ìrànwọ́ lásìkò pájáwì láti ilé iṣẹ́ Ìròyìn ilẹ̀ Yúróòpù, ìyẹn European Journalism Centre. Wọ́n ṣe àgbékalẹ̀…
Ìwé Ìléwọ́ Ìṣàmúdájú jẹ́ ìwé àmúlò fún àwọn oníròyìn àti àwọn tó ń ṣe ìrànwọ́ lásìkò pájáwì láti ilé iṣẹ́ Ìròyìn ilẹ̀ Yúróòpù, ìyẹn European Journalism Centre. Wọ́n ṣe àgbékalẹ̀…
Guide to Fact-Checking Investigative Stories ti GIJN láti o̩wó̩ Nils Hanson (2021) Four Quick Ways to Verify Images on a Smartphone ti GIJN láti o̩wó̩ Raymond Joseph. (2021) Making Stories Ironclad…
Àwọn Aṣáájú ṣàgbéjáde sítáì “Pimp My Ride” àjọ alátùn-ún-ṣe fún ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbé-ìròyìn-jáde. Àwọn Agbóhuntuntunjáde Tíkò-lẹ́gbẹ́ A dàbí àwọn ènìyàn-àwùjọ. “AJ+” ń ṣe àtúnṣe sí yàrá-ìròyìn rẹ̀ láti bá àìní àwọn ọ̀dọ́…
Àwọn tó Lùgbàdì Àrùn Kòrónà tí kò Fara Hàn By Ilé iṣẹ́ tó ń rí sí iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn ti Howard | Ọgbọ́n Ọjọ́, Oṣù Ọ̀pẹ, Ọdún 2020 Àwọn…
Bíbẹ̀rẹ̀ – Àwọn Àmọ̀ràn ní ìpele ìpele Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú Tí o bá ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣé alábàápàdé ìròyìn tó jọ mọ́ dátà, àwọn ohun èlò wọ̀nyí wá…
Láti o̩wó̩ Kira Zalan | May 23, 2016 Ǹjé̩ e̩ ń wá àwo̩n orísun? Rírí onímò̩ ní apá ibì kan jé̩ ibi tí ó dára láti bè̩rè̩ fún ò̩pò̩ ìtàn. GIJN s̩e àyè̩wò…
Àwọn Èrò Oní-àdéhùn Ìdúnàádúràá Àdéhùn fún Átíkù Oníwàádìí gbọ́dọ̀ bo onírúurú ìṣòro tí kò fi bẹ́ẹ̀ yẹ fún, sọ pé àbùdá nípa ọmọ ọlọ́ńgbò tó rẹwà. Àwọn kókó kan tó…
Ìfúnnilówó Owó-ìrànwọ́ fún àwọn iṣẹ́-àkànṣe ìjábọ̀ wà láti onírúurú orísun. Àwọn Olùfúnnilówó kan gba gbogbo irúfẹ́ àbá wọlé, nígbà tí àwọn mìíràn wá láti ṣe ìrànwọ́ fún àwọn àkórí kan…
GIJN ti ṣe àkójọpọ̀ àti ètò àwọn ohun èròjà nípa lílo dátà fún ìròyìn tó jọ mọ́ iṣẹ́ ìwádìí. À bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ojúlówó àwọn èròjà ìdánilẹ́kọ̀ọ́ kí a tóó kán…
Láti o̩wó̩ Raymond Joseph | O̩jó̩ Ke̩rìnlélógún, Os̩ù Ògún, 2021 This photograph of a weasel clinging to the back of a flying woodpecker went viral on social media. While it had all the…