ÀÌDÁṢE: Fi Ìsedúró Wéwu
Níní ìṣedúró nígbà tí o wà lórí àwọn iṣẹ́ àyànṣe eléwu le jẹ́ ìkówólé tó mú ọpọlọ dáni àti èyí tí kò wọ́n tó bí o ṣe bẹ̀rù. Rí àwọn…
Níní ìṣedúró nígbà tí o wà lórí àwọn iṣẹ́ àyànṣe eléwu le jẹ́ ìkówólé tó mú ọpọlọ dáni àti èyí tí kò wọ́n tó bí o ṣe bẹ̀rù. Rí àwọn…
DÍDẸ́RỌ́ ÀJÀKÁLẸ̀ ÀRÙN FI ÀÀYÈ SÍLẸ̀ LÁTI WÁ ÌYÀNJÚ SÍ ÀÌṢE DÉÉDÉÉ LÓRÍ LÍLO DÁTÀ Ọjọ́ Kọkàndínlógún, Oṣù Èbíbí, Ọdún 2021 Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ṣe àǹfààní ń lá gbáà fún…
Ìkọ́ni àti ìdanilẹ́kọ̀ọ́ Ọ̀kan gbòógì lára ojúṣe GIJN ni láti se àkójọ pọ̀ atọ́nà fún ìwádìí tó múná dóko lórí ìròyìn yín. Onírúurú àwọn èdè ni ẹ yí ò rí…
Turbulent with a chance of data: Journalism’s drone-powered futures: A guide to storytelling with UAVs, láti o̩wó̩ Monica Sengul-Jones nínú datajournalism.com Tips on Drone Journalism, láti o̩wó̩ Raffy Tima tí…
Àwọn oníròyìn Àdáṣe máa ń sábà wà láàyè ara wọn nígbà tí ó bá di ọ̀rọ̀ ààbò, lójú aye àti ìmọ̀ ẹ̀rọ ayélujára, ṣùgbọ́n ọ̀pọ̀ ohun-èèlò aṣèrànwọ́ ló wà. Ìrànlọ́wọ́…
Ohun èlò fún àwọn oníròyìn: ìwé atọ́ni sónà olójú ewé ọgọ́rùn-ún ó lé méje èyí tí ilé iṣẹ́ Amẹ́ríkà tó ń rí sí oko òwò aládàńi gbé jáde lọ́dún 2009…
Ìpàdé Àpérò lórí Iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ Dátà Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú Àwọn ìpàdé àpérò wọ̀nyí pèsè àǹfààní lóní yanturu láti mọ àwọn ènìyàn sii, láti…
Crafting Investigative Reportage Into Dramatic Narratives, láti o̩wó̩ Vinod K Jose, Olùs̩àtúnko̩ àgbà fún The Caravan, Ìwé ìròyìn àkó̩kó̩ fún is̩é̩ ìròyìn aláròyé àti o̩ló̩fintótó ní ilè̩ India. Àgbékalè̩ GIJC19 …
Ìròyìn tó dára jù lọ Èyí jẹ́ Ẹ̀rọ ayélujára tó ní onírúurú ohun èlò èyí tí ilé iṣẹ́ ìtẹ̀wé ilẹ̀ Amẹ́ríkà ṣe àgbékalẹ̀ rẹ̀. Ìgbìmọ̀ amúṣẹ́yá AEJMC láti dí àlàfo…
Ìwé ìléwọ́ fún àwọn oníròyìn ilẹ̀ Lárúbáwá nípa òmìnira à ti kó ìròyìn jọ pẹ̀lú iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn: e yóò rí ìwé olójú ewé mọ́kànlélógún ọ̀hún gbà lọ́fẹẹ̀ẹ́ lórí…