Iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ Dátà: Àkójọpọ̀ GIJN
Ìpàdé Àpérò lórí Iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ Dátà Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú Àwọn ìpàdé àpérò wọ̀nyí pèsè àǹfààní lóní yanturu láti mọ àwọn ènìyàn sii, láti…
Ìpàdé Àpérò lórí Iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ Dátà Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú Àwọn ìpàdé àpérò wọ̀nyí pèsè àǹfààní lóní yanturu láti mọ àwọn ènìyàn sii, láti…
Crafting Investigative Reportage Into Dramatic Narratives, láti o̩wó̩ Vinod K Jose, Olùs̩àtúnko̩ àgbà fún The Caravan, Ìwé ìròyìn àkó̩kó̩ fún is̩é̩ ìròyìn aláròyé àti o̩ló̩fintótó ní ilè̩ India. Àgbékalè̩ GIJC19 …
Ìròyìn tó dára jù lọ Èyí jẹ́ Ẹ̀rọ ayélujára tó ní onírúurú ohun èlò èyí tí ilé iṣẹ́ ìtẹ̀wé ilẹ̀ Amẹ́ríkà ṣe àgbékalẹ̀ rẹ̀. Ìgbìmọ̀ amúṣẹ́yá AEJMC láti dí àlàfo…
Ìwé ìléwọ́ fún àwọn oníròyìn ilẹ̀ Lárúbáwá nípa òmìnira à ti kó ìròyìn jọ pẹ̀lú iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn: e yóò rí ìwé olójú ewé mọ́kànlélógún ọ̀hún gbà lọ́fẹẹ̀ẹ́ lórí…
Àpèjúwe àti àwọn ètò ẹ̀kọ́ lórí iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn [Ní sísẹ n tẹ̀lé álífábẹ́ẹ̀tì orúkọ àwọn Fáṣítì gbogbo àti àwọn Ọ̀jọ̀gbọ́n]. Aligọ́rídìmù fún àwọn Oníròyìn Àkànṣe iṣẹ́ sílábọ́ọ̀sì tí…
Kò buŕkú jù láti so̩ pé orílè̩-èdè Amé̩ríkà kò tí rí irú ìbò bí èyí rí. Ní o̩jó̩ ke̩ta, os̩ù Bélú, àwo̩n o̩mo̩ orílè̩-èdè Amé̩ríkà yóò dìbò yan ààre̩, àwo̩n…
Àwọn oníròyìn náà ń kíyèsí ìpolówó ìmọ̀-ẹ̀rọ. Àwọn náà sinmi lé e. “CJR” Kín ni ohun tuntun nínú títẹ àádọ́ta àbájáde fún owó iṣẹ́-ìròyìn: àlàyé tó lọ sàn-án (apá kejì).…
Ǹ jẹ́ ẹ́ ń wá àmọ̀ràn ní ṣókí, àwọn ohun èlò tàbí ìtọ́ni sónà? Yẹ ìsàlẹ̀ wò fún àwọn ìtọ́sọ́nà tó ní í se pẹ̀lú ìwádìí ìjìnlẹ̀ lórí Ìròyìn pẹ̀lú…
Ìwé Ìléwọ́ Ìṣàmúdájú jẹ́ ìwé àmúlò fún àwọn oníròyìn àti àwọn tó ń ṣe ìrànwọ́ lásìkò pájáwì láti ilé iṣẹ́ Ìròyìn ilẹ̀ Yúróòpù, ìyẹn European Journalism Centre. Wọ́n ṣe àgbékalẹ̀…
Guide to Fact-Checking Investigative Stories ti GIJN láti o̩wó̩ Nils Hanson (2021) Four Quick Ways to Verify Images on a Smartphone ti GIJN láti o̩wó̩ Raymond Joseph. (2021) Making Stories Ironclad…