YÀRÁ ÌRÒYÌN ÀWỌN AKẸ́KỌ̀Ọ́
Wọ́n ti Gbóríyìn fún Ẹ̀ka Iṣẹ́ Ìwádìí lórí Ìròyìn tuntun, ti ilé ẹ̀kọ́ Fáṣítì Toronto lásìkò Àjàkálẹ̀ Àrùn Láti ọwọ́ Jelter Meers | Ọjọ́ Kẹẹ̀dógún, Oṣù Belú, Ọdún 2020 Láti…
Wọ́n ti Gbóríyìn fún Ẹ̀ka Iṣẹ́ Ìwádìí lórí Ìròyìn tuntun, ti ilé ẹ̀kọ́ Fáṣítì Toronto lásìkò Àjàkálẹ̀ Àrùn Láti ọwọ́ Jelter Meers | Ọjọ́ Kẹẹ̀dógún, Oṣù Belú, Ọdún 2020 Láti…
Àwọn Ìtalólobó fún Kíkọ́ ìròyìn-jọ-kọ̀ḿpútà fún Ìwádìí Láti ọwọ́ Miriam Forero Ariza | ọjọ́ kẹtàlá oṣù keje, ọdún 2021 Ní tòròtòrò ọdún yìí, gẹ́gẹ́ bí orílẹ̀-èdè ti Colombia tí ìwọ́de…
Ìròyìn ní èdè agbègbè jẹ́ èyí tí akọ̀ròyìn pẹ̀lú ilé iṣẹ́ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ ìlú Canada, Duncan McCue gbé jáde lọ́dún 2011. Ó ń àwọn èròjà láti kọ ìròyìn lédè abínibí jákèjádò…
(PDF): Ilé iṣẹ́ tó ń rí sí sí iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn, àkọ́kọ́ irú rẹ̀ ní àgbáyé tí won kò fi dá oko òwò, èyí tó ń rí sí “iṣẹ́…
Ilé Ẹ̀kọ́ Fáṣítì Illinois ń ṣe Ìgbanisíṣẹ́ sí Ipò Ọ̀gá Àgbà èyí tí yóò jẹ́ Alárinà Láàárín àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ fún Ìmọ̀ Ìròyìn àti Àwọn Akọ́ṣẹ́mọsẹ́ Láti ọwọ́ Jelter Meers |…
Ìtalólobó àgbà-ọ̀jẹ̀ fún wíwú gbòǹgbò ìròyìn-èké Láti ọwọ́ Maurice Oniang’o | ọjọ́ kẹtà-lé-lógún oṣù kọkànlá, ọdún 2021 Fún àwọn oníròyìn aṣèwádìí tí wọ́n ń wú ìpòlongo tí ìròyìn tí kò…
Onírúurú ìkànnì tí ìdàgbàsókè ti débá ló wà tí ó ń ran àwọn òǹkọ̀wé lọ́wọ́la ti owó nípaṣè ìgbéjáde-ara-ẹni. Yàlá àwọn wọ̀nyí tọ̀nà fún ọ èyí yóò gbà ìwádìí. Ní…
Iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn: Ohun èlò fún àwọn oníròyìn: ìwé atọ́ni sónà olójú ewé ọgọ́rùn-ún ó lé méje èyí tí ilé iṣẹ́ Amẹ́ríkà tó ń rí sí oko òwò aládàńi…
Ilé Ẹ̀kọ́ Fáṣítì Illinois níbi tí wọ́n ti ń fi Ẹ̀dùn Ọkàn hàn Nípa Àjàkálẹ̀ Àrùn COVID-19 àti bí wọ́n ṣe ń ń polongo bí àwọn ènìyàn ṣe ń lòdì…
Iṣẹ́-ìròyìn Àdáṣe: Ìṣedúró Ìgbáralé ènìyàn àti ìjọba fún ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbéròròyìn-jáde Àwọn oníròyìn Oníwàádìí Àdáṣe gbọdọ̀ ro mímú iṣedúró síta dáadáa láti dá ààbò bo ara wọn kúrò ni ewu fífi ẹ̀sùn…