Iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ dátà
GIJN ti ṣe àkójọpọ̀ àti ètò àwọn ohun èròjà nípa lílo dátà fún ìròyìn tó jọ mọ́ iṣẹ́ ìwádìí. À bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ojúlówó àwọn èròjà ìdánilẹ́kọ̀ọ́ kí a tóó kán…
GIJN ti ṣe àkójọpọ̀ àti ètò àwọn ohun èròjà nípa lílo dátà fún ìròyìn tó jọ mọ́ iṣẹ́ ìwádìí. À bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ojúlówó àwọn èròjà ìdánilẹ́kọ̀ọ́ kí a tóó kán…
Láti ọwọ́ Fabiola Torres López | Ọjọ́ Kọkànlá, Oṣù Agẹmọ 11, Ọdún 2017 Ní ọdún márùn-ún sẹ́yìn, àwọn akọ̀ròyìn tó ń bojú wo ibi ì kò èròjà sí tàbí wá…
Ìdáṣe gẹ́gẹ́ bí oníròyìn oníwàádìí jẹ́ ìpèníjà ní àkókò tó dára jù, ó sì tún ṣàfihàn àwọn ìṣòro nígbà àjàkálẹ̀-ààrùn kòrónà. Láti ṣísàkóso ewu ajẹmára sí pípàdánù iṣẹ́ láti ara…
Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú Tí o bá ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣé alábàápàdé ìròyìn tó jọ mọ́ dátà, àwọn ohun èlò wọ̀nyí wá lọ́fẹẹ̀ẹ́ fún lílo, tí yóò sì jẹ́…
Membership in GIJN Ọmọ ẹgbẹ ninu Global Investigative Journalism Network wa ni sisi si awọn ti kii ṣe ere, awọn NGO, ati awọn ajọ eto ẹkọ, tabi deede wọn, ti…
Títa àwọn àbá Iṣẹ́-ìròyìn Oníwàádìí Aládàáni dàbí títa àwọn ìtàn mìíràn gidi gan, ṣùgbọ́n ó tún le jù ú lọ. Kò kàn sí ìgbéjáde ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbé-ìròyìn-jáde tó tó tó ń wù…
Mímúlò ìtàkùn ayélujára tó níwọ̀n lò ní Yàrá-ìròyìn rẹ: Ewé-ìtalólobó lórí Ìfọ́ńká àti lílọ́wọ́sí àwọn olùwòran Láti ọwọ́ Rossalyn Warren | March 18, 2021 Bí o bá ń ka èyí,…
Iṣẹ́ takuntakun tó wà nìdii iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ ìwádìí lè kọ́ ìpèníjà látàrí onírúurú akùdé. Ohun èlò yìí ṣe àgbékalẹ̀ onírúurú ìpèníjà tí àwọn àìfíkítà àti àwọn ilé…
Is̩é̩ tí ó gbo̩ngbó̩ nípa sís̩e is̩é̩ ìròyìn o̩ló̩fintótó lè sú ènìyàn látàrí orís̩irís̩i àgbéyè̩wò ajé̩mó̩-ìs̩èlú. Ohun èlò yìí mójú tó díè̩ nínú àwo̩n àdojúko̩ tí àwo̩n adás̩é̩s̩e àti àwo̩n…
Ohun Kíkà Pàtàkì Iṣẹ́-ìwádìí “GIJN” ṣàgbékalẹ̀ àwọn ìtalólobó lórí ọ̀nà tí a lè gbà gbé ìpolongo ìkówójọ orí-ìtàkùn-ayélujára, àwọn orúkọ orílẹ̀-èdè àti ẹkùnjẹkùn tó jẹ mọ́ ìkànnì ìkówójọ orí-ìtàkùn-ayélujára, àbá…