Yoruba

gijn-logo

Field Guide to Security

tí wọ́n sì tún gbé ètò ìdáni lẹ́ẹ̀kọ́ kan kalẹ̀ lórí ohun èlò alágbè ká. Pẹ̀lú ìlànà lórí bí wọ́n ṣe fàràn tó jíire kalẹ̀, and ṣíṣe àtúntọ̀ rẹ̀ lórí ẹ̀rọ ìbáni sọ̀rọ̀ alágbè ká àti láti sọ ìtàn tí … Read more

gijn-logo

Legal Defense and Emergency Aid

Aabo Ofin ati Iranlọwọ pajawiri

Tani ó ń gbèjà ẹ̀tọ́ àwọn oníṣẹ́ ìròyìn? Tani ó le pèsè àtìlẹ́yìn tí pàjáwìrì bá ṣẹlẹ̀? Èyí ní àwọn ìtọ́sọ́nà sí àwọn ẹgbẹ́ tí wọ́n ní ìdásílẹ̀ tí ó ń ṣe àmọ̀dájú ní gbígba … Read more

gijn-logo

Àwọn Ìtalólobó àti Àwọn Ète: Ìdáṣe Lásìkò Àjàkálẹ̀-ààrùn COVID-19

Ìdáṣe gẹ́gẹ́ bí oníròyìn oníwàádìí jẹ́ ìpèníjà ní àkókò tó dára jù, ó sì tún ṣàfihàn àwọn ìṣòro nígbà àjàkálẹ̀-ààrùn kòrónà. Láti ṣísàkóso ewu ajẹmára sí pípàdánù iṣẹ́ láti ara ìdínkù ọrọ̀-ajé lágbàáyé, àwọn ìṣòro wọ̀nyìí jẹ́ àrà ọ̀tọ̀ àti … Read more

gijn-logo

Ọmọ ẹgbẹ́ GIJN

GIJN jẹ ẹgbẹ ti awọn ẹgbẹ ti ko ni ere ti o ṣe atilẹyin iṣẹ akọọlẹ iwadii ni ayika agbaye. Lati ìgbà tí o ti bẹrẹ ni odun 2003, GIJN ti dagba si agbegbe agbaye pẹlu awọn ọmọ ẹgbẹ 227 … Read more

gijn-logo

GIJN Members

100Reporters, USA

Dedicated si sisọ awọn apẹrẹ tuntun ni iṣẹ iroyin lódidi,  100 Reporters darapọ mọ awọn iyebiye ti awọn onirohin alamọdaju ti o dara julọ ti aye pẹlu awọn aṣewadi ati awọn oniroyin ara ilu kaakiri agbaye, lati ṣe … Read more

gijn-logo

Teaching and Training

Okan gboogi lara ojuse GIJN ni lati se akojopo atona fun iwadii to m’una d’oko lori Iroyin. Oniruuru awon ede ni e yoo ri, pelu eto eko ati ilaniloye l’oniranran. Ofee ni gbogbo re ba de.

  • Itonisona fun iwadii ijinle
Read more
gijn-logo

AsÌpín, Ìgbéga àti Àìfíkítà

Iṣẹ́ takuntakun tó wà nìdii iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ ìwádìí lè kọ́ ìpèníjà látàrí onírúurú akùdé. Ohun èlò

yìí ṣe àgbékalẹ̀ onírúurú ìpèníjà tí àwọn àìfíkítà àti àwọn ilé iṣẹ́ ìròyìn tó dá lórí iṣẹ́ ìwádìí ń fi

ojoojúmọ́ … Read more

gijn-logo

Ìbádòwòpọ̀-ọ̀rẹ́ àti Ìfọwọ́sowọ́pọ̀

Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ lórí iṣẹ́-àkànṣe aṣèwádìí jẹ́ gbajúgbajà síi lójojúmọ́.

Ṣíṣeṣẹ́ pọ̀ pẹ̀lú alábàáṣiṣẹ́ le ṣe àfikún àti ìrànlọ́wọ́ jíjábọ̀ ohun èlò àti ìgbéga ọ̀nà oǹkàwé. Le gba àwọn Ìmọ̀ọ́ṣe tó yàtọ̀, bí i ṣiṣe àtúpalẹ̀ déétà, ṣíṣẹ̀dá àwòrán rírí, tàbí gbígbáradì … Read more