Bíbẹ̀rẹ̀ – Àwọn Àmọ̀ràn ní ìpele ìpele

Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú

Tí o bá ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣé alábàápàdé ìròyìn tó jọ mọ́ dátà, àwọn ohun èlò wọ̀nyí wá lọ́fẹẹ̀ẹ́ fún lílo, tí yóò

sì jẹ́ ìwúlò fún ẹ.

Ìwé atọ́nà alájọṣe pọ̀ fún ìròyìn tó jọ mọ́ dátà Ìwé atọ́nà yìí tó jáde lọ́dún 2019 bójú wo àwọn

n kàn wọ̀nyí:

● Onírúurú ìròyìn alájọṣepọ̀ àti bí o ṣe lè bẹ̀rẹ̀ wọn.

● Bí o ṣe lè fọwọ́sowọ́pọ̀

lórí Ìròyìn tó jọ mọ́ dátà, tó bá rújú pọ̀.

● Àwọn ìbéèrè tí o ní láti béèrè kí o tó bẹ̀rẹ̀ ìfọwọ́sowọ́pọ̀

lórí Ìròyìn tó bá rújú.

● Àwọn ọ̀nà tí ó lè gbà láti fọwọ́sowọ́pọ̀

lórí Ìròyìn tó jọ mọ́ dátà.

● Bí o ṣe lè bẹ̀rẹ̀ àti ṣe Àkóso ìfọwọ́sowọ́pọ̀

lórí Ìròyìn tó jọ mọ́ dátà.

Ìròyìn tó jọ mọ́ dátà: Àwọn Ohun Èlò Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ MaryJo Webster jẹ́ àkójọpọ̀ ohun èlò fún

àwọn oníròyìn tí Wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀

iṣẹ́

lórí Ìròyìn tó jọ mọ́ dátà. Ó kún fún Àmọ̀ràn lórí dátà, àwọn

ìwé tó wúlò fún iṣẹ́ wọn, ìtọ́sọ́nà lórí R, SQL àti ìtànkálẹ̀di àti àwọn èrò lórí Ìròyìn tó jọ mọ́ dátà.

Maryjo Webster jẹ́ akọ̀ròyìn lórí Ìròyìn tó jọ mọ́ dátà pẹ̀

lú ìwé ìròyìn Star-Tribune tó kalẹ̀ sí ìlú

Minesota.

Títò àti pínpín iṣẹ́ ìwádìí tó jọ mọ́ dátà, láti ọwọ́ Marcel Pauly àti Patrick Stotz ti Der Spiegel,

fún GIJC19.

Ìlànà Àwọn Olóoòótú ìròyìn lórí Dátà láti ọwọ́ Emilia Diaz-Struck of tí tí Ìgbìmọ̀ tó ń rí sí iṣẹ́

ìwádìí lórí Ìròyìn lágbàáyé, fún àjọ GIJC19.

Bí ó ṣe lè ṣe #ddj pẹ̀lú yàrá ìkóròyìn jọ kékeré pẹ̀lú owó píníṣín àkójọpọ̀ àmọ̀ràn tí àjọ

GIJC19 ṣe àgbékalẹ̀ rẹ̀.

láti ọwọ́ Pinar Dag láti ọwọ́ àjọ datajournalismturkey.

Ìwé ìtumọ̀ ọ̀rọ̀ lórí ìlànà ìṣirò fún àwọn alákọ̀bẹ́rẹ̀

láti ìkànnì iMedD Lab.

Àyípadà ètò ìmọ̀ ẹ̀rọ ní ìpele ìpele

láti ọwọ́ Felix Ebert àti Vanessa Wormer ti àjọ Süddeutsche Zeitung, Thorsten Holz ilé ẹ̀kọ́ Fáṣítì

Ruhr tó wà ní Bochum àti Hakan Tanriverdi tí Bayerische Rundfunk. Wọ́n ṣe àgbékalẹ̀ rẹ̀ fún

àjọ GIJC19.

Àwọn ohun èlò fún ìròyìn tó jọ mọ́ dátà láti àjọ Knight tó ń rí sí iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ sáyẹ́ǹsì, tó

ṣe àgbékalẹ̀ àwọn ìwé, Ìpàdé àpérò, and àwọn ohun èlò àti ibi ìpamọ́ dátà fún àwọn akọ̀ròyìn.