Láti ọwọ́ Fabiola Torres López | Ọjọ́ Kọkànlá, Oṣù Agẹmọ 11, Ọdún 2017
Ní ọdún márùn-ún sẹ́yìn, àwọn akọ̀ròyìn tó ń bojú wo ibi ì kò èròjà sí tàbí wá ìrànwọ́
láti ọwọ́
àwọn ọlọ́ṣà lórí ẹ̀rọ ayélujára àti àwọn onímọ̀ nípa Kóòdù, àwọn ní wọ́n ń rí gẹ́gẹ́ bíi onímọ̀ ní
yàrá ìkóròyìn jọ. N kàn ti yàtọ̀
lásìkò yìí: gbogbo wa lati mọ̀ nípa onírúurú ìròyìn tó fẹsẹ̀ múlẹ̀
lórí
ìwà àjebánu, tí kò sì yọ ìlú mọ̀ọ́ká iṣẹ́ ìwádìí ìròyìn lórí Panama Papers, èyí tó ṣe àtúpalẹ̀ àjọṣe
pọ̀
láàárín àwọn akọ̀ròyìn àti ìmọ̀ ẹ̀rọ. Tó fi jẹ́ wípé àmìn ẹ̀yẹ tí Pulitzer ti ọdún 2017 bọ́ sí ọ̀dọ̀
akọ̀ròyìn tó ṣiṣẹ́
iṣẹ́ ìwádìí lórí àwọn ilé iṣẹ́ tó sún mọ́ etí omi, èyí tí ìwà àjebánu láti fi ẹ̀mí
imoore hàn fún iṣẹ́ takuntakun tí wọ́n gbé ṣe.
Ní Latin àti àárín gbùngbùn America, àlàfo ń lá wà láàrin ìmọ̀ ẹ̀rọ àti iṣẹ́ akọ̀ròyìn, sìbẹ̀, ilé iṣẹ́
ìròyìn ménigbàgbé mẹ́
jọ àti ìkànnì Ìròyìn ìgbàlódé mẹ́fà ni wọ́n ti dá ẹgbẹ́ tó ń ṣe ìgbélárugẹ iṣẹ́
ìròyìn tó jọ mọ́ dátà sílẹ̀ pẹ̀
lú ìmọ̀ àti ìrírí wọn ní ìwé ìròyìn New York Times, Guardian,
ProPublica àti ìwé ìròyìn Los Angeles Times.
Ojo Público logo
Mo jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùdásílẹ̀ àwọn ìkànnì ayélujára wọ̀nyí: Ojo Público, tó jẹ́ ìkànnì ìwé ìròyìn
ti ìgbàlódé ní àwọn akọ̀ròyìn mẹ́fà, àti àwọn onímọ̀ nípa Kóòdù méjì tó dá lórí iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́
dátà. Àpilẹ̀kọ wa, “Memoria Robada” (Stolen Memory), gba àmìn Ẹ̀yẹ Latin American Kẹta fún
ìròyìn tó jọ mọ́
iṣẹ́ ìwádìí ní ọdún 2016. Iṣẹ́ ìwádìí ẹlẹ́kùn jẹkùn tí wọ́n lọ dátà fún láti fi pèsè ẹ̀rí
tó múná dóko fún jíjí àwọn ohun ìṣẹ̀ǹbáyé kúrò ní Latin America, pẹ̀
lú àpèjúwe ibi tí wọ́n ń kó
wọn lọ gẹ́gẹ́ bíi ìwà ọ̀daràn.
Gbogbo àwọn ẹ̀ka iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ dátà tí a dárúkọ ni wọ́n ní àbùdá tí wọn, nípa ẹgbẹ́,
ìgbélárugẹ àti ìmúdàgbà. Ṣùgbọ́n lẹ́nu ọjọ́ mẹ́ta yìí, ọ̀pọ̀
lọpọ̀ ti ń ṣe àfihàn, tí wọ́n sì fi àmì ẹ̀yẹ
iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ dátà dá wọn lọ́
lá, èyí tí àjọ Global Editors Network àgbékalẹ̀ rẹ̀, tó ṣe àfihàn
ìròyìn tó jọ mọ́ dátà, tó fakọ yọ.
Àwọn ẹgbẹ́ yìí kalẹ̀ sí Argentina, Peru, Costa Rica, Colombia, Brazil, Mexico àti Chile. Mo ti ní
àǹfààní láti fikùn lukùn pẹ̀
lú àwọn lẹ́gbẹ́
lẹ́gbẹ́, tí mo sì tún kọ́ nípa ìrírí wọn, èyí tó fun ní
àfojúsùn lórí àwọn àbùdá tó ṣe kókó tí àwọn akọ̀ròyìn gbọ́dọ̀ ní, èyí tí yóò wúlò fún àwọn
akọ̀ròyìn àti àwọn ìpẹ́ẹ́ẹ̀rẹ́ tó ń tẹ̀
lé gìgísẹ̀ wọn.
1. Ìwọ̀n ṣe Pàtàkì
“Lára àwọn ọ̀nà láti rí àṣeyọrí ṣe lórí Ìròyìn tó jọ mọ́ dátà ní ọgbọ́n àtinúdá àwọn ọmọ ẹgbẹ́.”
– La Nación’s Ricardo Brom
“Lára àwọn ọ̀nà láti rí àṣeyọrí ṣe lórí Ìròyìn tó jọ mọ́ dátà ní ọgbọ́n àtinúdá àwọn ọmọ ẹgbẹ́.”
Ricardo Brom tó jẹ́ Ọ̀gá àgbà fún iṣẹ́ ọpọlọ lórí dátà fún ìwé ìròyìn Argentina kan, La Nación ló