Ìròyìn tó dára jù lọ Èyí jẹ́ Ẹ̀rọ ayélujára tó ní onírúurú ohun èlò èyí tí ilé iṣẹ́ ìtẹ̀wé ilẹ̀ Amẹ́ríkà ṣe àgbékalẹ̀ rẹ̀.
Ìgbìmọ̀ amúṣẹ́yá AEJMC láti dí àlàfo tó wà nínú ìwé àbọ̀ àwọn akọ́ṣẹ́mọsẹ́ ti ọdún 2017 Ìwé àbọ̀ ọdún 2017 yìí tó dá lórí ìfọwọ́sowọ́pọ̀ láàárín àwọn ọ̀mọ̀wé àti àwọn oníròyìn tó nínú ẹgbẹ́ tó ń rí sí ètò ẹ̀kọ́ fún àwọn oníròyìn àti àwọn akọ́ṣẹ́mọsẹ́ nípa ìkànsíraeni tí a mọ̀ sí Association for Education in Journalism and Mass Communication (AEJMC).
Àkíyèsí nípa bí wọ́n ṣe ń kọ́ iṣẹ́ ìròyìn lọ́nà kíkà láti ọwọ́ Judd Slivka, and tó jẹ́ Ọ̀gá àgbà nílé ẹ̀kọ́ tí wọn tí ń kọ́ni ní ìmọ̀ nípa iṣẹ́ akọ̀ròyìn tó wà ní Missouri.
Àwọn ohun èlò ètò ẹ̀kọ́ nípa Aligọ́rídìmù ti ilé ẹ̀kọ́ tí wọn tí ń kọ́ni ní ìmọ̀ nípa iṣẹ́ akọ̀ròyìn tó wà ní Columbia
Kíkọọ́ ìlànà ètò ẹ̀kọ́ aligọ́rídìmù láti ọwọ́ Ọ̀jọ̀gbọ́n Jonathan Stray ti ilé ẹ̀kọ́ Columbia.