Àwọn Ìtalólobó Ìjábọ̀ Ìròyìn àti Àwọn Èlò

Ń wá àwọn ohun èlò láti 2021 Global Investigative Journalism Conference? O ti wá sí ibi tó tọ́. Tẹ ibí yìí. O ó rí tó ojú-ewé igba, àwọn ìgbékalẹ̀, àwọn ìtọ́nisọ́nà, àwọn èlò àti àwọn líǹkì tí #GIJC21 gbé kalẹ̀.

Fún ọdún sẹ́yìn, GIJN ti ṣe àtòjọ̀ àwọn àgbàjọ̀ ti bí-wọ́n-ṣé-le ìtàn àti ojú-ewé ìtalólobó pẹ̀lú àwọn èlò àti àwọn ọgbọ́n tó wúlò fún àwọn oníròyìn aṣèwádìí lágbàáyé. Níbí yìí ni yíyan àwọn átíkù wa tó jẹ́ gbajúgbajà, ṣètò nípasẹ̀ àkòrí, láti Ìkànnì Ohun èlò GIJN.

Àwọn Ìtalólobó àti Àwọn Èlò

  • Ìtọ́nisọ́nà Afghanistan: Bí wọ́n ṣe lè ran àwọn Oníròyìn lọ́wọ́ àti Àwọn Yòókù tó wà nínú Ewu.
  • Àwọn Èlò Okòwò fún Yàrá-ìròyìn
  • Ẹ̀hun Àgbàjọ-déétà fún ìwádìí
  • Kíki Iṣẹ́-ìròyìn Aṣèwádìí
  • Ìròyìn-èké
  • Ìfọ́nká & Ìgbéga
  • Iṣẹ́-ìròyìn Dúrònù
  • Ìṣe-olóòtú àti Ìṣàkóso
  • Àwọn Ìdìbò
  • Àyẹ̀wò-kíákíá àti Ìwádìí òkodoro
  • Wíwá Àwọn Orísun Àgbà ọ̀jẹ̀
  • Aládàáni
  • Àwọn Ọgbọ́n Ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò
  • Àwọn Èlò Aṣewádìí & Ọgbọ́n
  • Àwọn Ìwé Aṣèwádìí
  • Àwọn Ìwé-ìléwọ́ Iṣẹ́-ìròyìn Aṣèwádìí
  • Àjọ Iṣẹ́-ìròyìn Aṣèwádìí
  • Ìwádìí òkodoro àwòrán
  • Journalism Security Assessment Tool (JSAT)
  • Iṣẹ́-ìròyìn Ẹ̀rọ Alágbèéká
  • Ìwádìí Lórí ìtàkùn Àtìsíwájú
  • Àwọn Èlò Ìwádìí Lórí ìtàkùn Ayélujára
  • Ìwádìí òkodoro orísun tó ṣí sílẹ̀ &àwọn èlò Ìwádìí
  • Iṣẹ́-ìròyìn-aláwòrán
  • Pódíkààsìtì
  • Jíjábọ̀ ní ìjọba-alágbárakan
  • Ìsọ́ni àti Èròjà-amí
  • Àwọn Ìtalólobó láti ṣàfihàn Àìdọ́gba
  • Ṣíṣọ́ Ìṣe WA ní orílẹ̀-èdè rẹ
  • Ṣíṣọ́ àwọn Ẹgbẹ́ Far-Right
  • Lílo ẹ̀rọ ọ̀nà-ìpadàsẹ́yìn
  • Fídíò Ìwádìí-sáyẹ̀nsì
  • Ìwádìí òkodoro Fídíò
  • Ìṣòfófó
  • Àwọn Obìnrin ní Iṣẹ́-ìròyìn
  • Àwọn Ìtàn Aṣèwádìí tó dára jù ní 2021 láti ọ̀dọ̀ Agbègbè.

Àwọn Ìtọ́nisọ́nà Ohun èlò

  • Ìtọ́nisọ́nà ti Òfin: Yíyàgò fún ẹjọ́
  • Ìṣàfihàn Dúkìá
  • Okòwò àti Ìtajà
  • Àwọn ìwádìí ọmọ-ìlú 
  • Ìṣòro ojú-ọjọ́
  • Àwọn ilé-iṣẹ́
  • Jẹdúdú-jẹrá
  • COVID-19
  • Ìrúfin
  • Déétà fún Áfíríkà
  • Déétà Iṣẹ́-ìròyìn
  • Ìpaarẹ́
  • Ẹ̀kọ́
  • Àwọn Ilé-iṣẹ́ Ìṣedíwọ̀n
  • Àyíká
  • Àyẹ̀wò-kíákíá
  •  Ìpa-abo
  • Oúnjẹ àti Ẹ̀kọ́-ọ̀gbìn
  • Ìlera àti Òògùn
  • Àjọ Ìlera
  • Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn
  • Ìfọmọṣòwò ẹrú kiri
  • Ìgbé-kiri Ayé-ẹ̀gàn Àìbófinmu
  • Ìgbé-kiri Ayé-ẹ̀gàn Àìbófinmu (Oríṣìí-ẹ̀dà kúkurú)
  • Àwọn Oníròyìn Aṣèwádìí Onílé
  • Ìṣòro LGBTQ
  • Mẹtanéè
  • Mẹtanéè (Oríṣìí-ẹ̀dà kúkurú)
  • Iṣíkiri
  • Ìṣíkiri ní ọ̀gbun
  • Olóogun àti Ìkọlura
  • Ìrúfin tí wọ́n ṣètò
  • Ìṣàkíyèsí nọ́ḿbà ìforúkọsílẹ̀ ọkọ̀-òfúrufú 
  • Ìṣẹ́
  • Dúkìá
  • Àwòrán sátẹ́láìtì
  • Ìfipábánilòpọ̀
  • Ìdárayá
  • Àwọn okùn ìpèsè
  • Ìwà Ìpániláyà
  • Fídíò fún Àwọn y6àrá-ìròyìn kékeré & Àwọn Aládàáni
  • Àwọn Ọ̀wọ́ Fídíò GIJN

Ǹjẹ́ ẹ ri wí pé ó wúlò?       Bẹ́ẹ̀ni               Bẹ́ẹ̀kọ́

   Ẹ ṣì ní àwọn ìbéèrè?

Ẹ kàn sí tábìlì ìrànwọ́ wa

Padà sí tábìlì ìrànwọ́