Ìtọ́nisọ́nà yìí ni wọn ṣe ìdúpẹ́ láti ran àwọn Google News Initiative lọ́wọ́. Talya Cooper ni ó ṣe ìwádìí àti ló kọ ọ́, olùwádìí tí ó tẹ̀dó sí New York tí ó ti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olùfipamọ́ Edward Snowden ìpamọ́-ìwé-ìròyìn ní olùkọlù àti gẹ́gẹ́ bí olùṣàkóso ìpamọ́ ní StoryCorps. Ó jẹ́ òǹkọ̀wé, pẹ̀lú Alison Macrina, ti “Anonymity” ìtọ́nisọ́nà tí Nikolia Apostolou àti Reed Richardson ṣe olóòtú rẹ̀. Sentavio, nípasẹ̀ Freepik.com. Chafiq Sroor ló buwà kún un.
Atọ́kà Àkóónú/ Ìfáàrà
Orí kìn-ín-ní – Ìsàkóso àti Ìṣàbójútó
Orí Kejì – Ìbáraẹnisọ̀rọ̀ àti Ìpín Fáìlì
(Banner)
Orí Kẹta – Ìṣirò àti Ìsanwọ́
(Banner)
Orí Kẹrin – Àtúpalẹ̀ àti SEO
(Banner)
Orí Karùn-ún – Ìpinnu-láti-sọ̀rọ̀ Olùwòran
Orí Kẹfà – Àwọn Èlò Ohùn àti Rírí
Orí Keje – Ètò Ìṣàkóso Àkòónú
Orí Kẹjọ – Olùfowósílẹ̀ àti Ìsàkóso Alábàápín
(Banner)
Orí Kẹsàn-án – Ìbù-ẹwà kún àti àwọn Èlò Ìwòran Déétà
Orí Kẹwàá – Ilé-iṣẹ́ Ìròyìn Àwùjọ àti Ìtajà Ímeèlì
(Banner)
Orí Kọkànlá – Ààbò Ojúùlà àti Ìsàkóso ọ̀rọ̀-ìgbaniwọlé