ÀWỌN ÀRÒKỌ

DÍDẸ́RỌ́ ÀJÀKÁLẸ̀ ÀRÙN FI ÀÀYÈ SÍLẸ̀ LÁTI WÁ ÌYÀNJÚ SÍ ÀÌṢE DÉÉDÉÉ LÓRÍ LÍLO DÁTÀ

Ọjọ́ Kọkàndínlógún, Oṣù Èbíbí, Ọdún 2021 

Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ṣe àǹfààní ń lá gbáà fún fún àkójọpọ̀ dátà láàrín àwọn olùṣe ìwádìí láti ṣe àtúnṣe kù dìẹ̀ ku diẹ tí wọ́n ti ń fojú fò, and gẹ́gẹ́ bíi àròkọ tí Shannon Mattern gbé kalẹ̀, èyí tó dá lórí “Bí Wọ́n Ṣe ń Yà Òfo” èyí tí wọ́n tẹ̀ jáde nínú ìwé ìròyìn tó jáde ní Oṣù Èrẹ́nà. 

Ọ̀jọ̀gbọ́n kan tó ń rí sí ọ̀rọ̀ ìṣẹ̀dá ọmọ ènìyàn ní ilé ẹ̀kọ́ iṣẹ́ ìwádìí fún ìbálòpọ̀ ẹ̀dá, Mattern ṣe àpèjúwe onírúurú àwọn ohun èlò àti ẹ̀rọ ìgbàlódé “gbà pé ààlà ń lá ló wà”  nínú kíkó àwọn ohun ìṣẹ̀ǹbáyé jọ.