gijn-logo

Àwo̩n Ohun-Èlò àti Ìlànà

Àwo̩n O̩gbó̩n láti s̩e àgbàpamó̩ àwo̩n Àté̩jís̩é̩ orí Telegram lórí Ogun Russia àti Ukraine

Láti o̩wó̩ Bellingcat Tech Team | March 15, 2022

Pè̩lú ìtàkùn Facebook àti Twitter tí ó ti jé̩ dídínà-mó̩, Telegram jé̩ ò̩kan lára àwo̩n ìtàkùn ìbánidó̩rè̩ tí ó sì s̩e é rí lò dáadáa fún àwo̩n ará Russia. Sís̩e àgbàpamó̩ àwo̩n ìròyìn ológun tí ó wà nílè̩ ní Ukraine máa jé̩ kó s̩eés̩e fún àwo̩n olùwádìí tí e̩nìkan bá pa àtè̩jís̩é̩ náà ré̩, ytí wo̩n bá yo̩ ìtàkùn kan kúrò tàbí tí gbogbo ìtàkùn gan kò bá s̩e é lò mó̩. 

Sís̩e ìwádìí Russia káàkiri àgbáyé: àkójo̩ ohun-èlò ojú-e̩sè̩ GIJN

Ètè márùndínlógún láti s̩e ìwádìí è̩s̩è̩ ogun

Ató̩nà àwo̩n onís̩é̩-ìròyìn fún lílo AI àti àwòrán sáté̩láìtì fún ìtàn-síso̩

Ète akò̩ròyìn Katie McQue fún sís̩e kíká àwo̩n òsís̩e̩ arìnrìnàjò láwo̩n ìpínlè̩ òkun Arab

ÀWO̩N OHUN ÈLÒ ÀTI ÌLÀNÀ

Ìbéèrè àti ìdáhùn: Sís̩e ìwádìí èsì àwo̩n o̩ló̩pàá sí àwo̩n aláìnílélórí

Láti O̩wó̩ Sarah Mirk | January 31, 2022

Wo̩n s̩e ìfò̩rò̩wánilé̩nuwò fún oníròyìn aláko̩sílè̩ Melissa Lewis nípa ìgbóhùnsáfé̩fé̩ orí ayélujára kan fún Reveal, léyìí tí ó s̩e ìwádìí ohun tí ó s̩e̩lè̩ nígbà tí àwo̩n olùgbé bá pe o̩ló̩pàá sí àwo̩n aláìnílélórí ní àgbègbè wo̩n, tí ó yànàná àko̩sílè̩ ìmúni káàkiri àwo̩n ìlú mé̩fà gbòógì ní US pè̩lú ò̩gò̩ò̩rò̩ àwo̩n aláìnílélórí.

ÒMÌNIRA ÌRÒYÌN

Dídá ìje̩niníyà SLAPPs àti fífí òfin dé̩rùba àwo̩n onís̩é̩ ìròyìn dúró

Láti O̩wó̩ Snezana Green | January 26, 2022

Lára àwo̩n ò̩nà ìfi-òfin dé̩rùbà àwo̩n onís̩é̩-ìròyìn o̩ló̩fintótó ni tí ó gbajúmò̩ jù ni SLAPPs (“strategic litigation against public participation”), léyìí tí ó  fé̩ láti dé̩rù ba àwo̩n onís̩é̩-ìròyìn láti fi ìwádìí wo̩n sílè̩. Ìlòkulò irins̩é̩ òfin láti o̩wó̩ àwo̩n tó wà ní òkè láti pa àwo̩n alátakò wo̩n lé̩nu mó̩ tí kárí ayé. Aburú rè̩ ti ga púpò̩, tí ó sì s̩e pàtàkì láti dá dúró fún ìjo̩ba àwa ara wa àti àlàáfíà.

ÀKÁ OHUN-ÈLÒ GIJN

Àká Ohun-èlò GIJN: Dído̩de̩ fún owó kò̩rò̩ àti ò̩rò̩ ìsúná tí ó ní àtakò

By Rowan Philp | January 24, 2022

In this edition of GIJN Toolbox, we profile three brand new — or newly expanded — tools to dig into financial secrecy and hidden gains from corruption or crime. Our list includes a user-friendly database to search for sanctions and conflict-of-interest red flags, a site that uses an algorithm to detect hidden bank accounts, and a newly expanded database on the true owners of offshore companies.

TOOLS & TECHNIQUES

Lílo ìtàkùn Snapchat gé̩gé̩ bí ohun èlò ìs̩èwádìí 

Láti o̩wó̩ Laura Dixon | December 8, 2021

Ǹjé̩ Snapchat, ìtàkùn tí ó gbajúmò̩ fún áfátà àti fídíò tó máa ń pòórá s̩e é lò fún àwo̩n onís̩é̩-ìròyìn as̩èwádìí, tàbí gé̩gé̩ bí ìtàkùn àtè̩jáde? Báwo ni wo̩n s̩e lè lò ó? Àti pé ò̩nà wo ni ó dára jù láti gbé e gbà?

GIJC21

Àwo̩n ohun-elò gbòógì àti àko̩sílè̩ láti s̩e àwárí àko̩sílè̩ tí kò dùn-ún rí

Láti O̩wó̩ Rowan Philp | November 24, 2021

Ni abala tó kéré jo̩jo̩ ní #GIJC21, ìgbìmò̩ àwo̩n akò̩ròyìn àti as̩àtúns̩e kan nílò ìs̩é̩jú máàrùn-ún márùn-ún láti s̩e àlàkalè̩ àwo̩n ohun-èlò tuntun àti àko̩sílè̩ tí onís̩é̩-ìròyìn kankan lè fi rí àwo̩n òótó̩ tí kò dùn-ún rí. 

GIJC21

Ète fún ìwádìí sís̩e nígbà tí ìjo̩ba bá ń dáàbò bo ò̩ràn dídá àti ìwà ìbàjé̩

Láti o̩wó̩ Rowan Philp | November 22, 2021

In a session on high-level corruption at #GIJC21, a panel of reporters from Liberia, Ukraine, Sudan, Russia, and Lebanon suggested a series of strategies that can pry facts from obstinate government agencies, find whistleblowers, and deliver alternate forms of accountability for officials seemingly above the law.

GIJC21

Àwo̩n ìtàn oniwádìí tí ó s̩e tún s̩e lágbàáyé

Láti o̩wó̩ Arinze Chijioke àti Banjo Damilola | November 10, 2021

Ní GIJC21, àwo̩n onís̩é̩-ìròyìn tí ó múná dóko so̩ àwo̩n ò̩nà ìsò̩tàn tí ó dára kan tí àwo̩n akò̩ròyìn káàkiri àgbáyé lè tè̩lé láti mú àyípadà wá ní ilé-ayé.

GIJC21

Àwo̩n È̩kó̩ láti ibi àjàkálè̩ àrùn: COVID-19 àti Ìwádìí Health-Pharma 

Láti o̩wó̩ Laura Oliver | November 10, 2021

Ní àkókò àjàkálè̩ àrùn COVID-19, àwo̩n onís̩é̩-ìròyìn káàkiri àgbáyé sàdédé bó̩ sínú ílàílò ìlera aráàlú, tí wo̩n ń gbìyànjú láti fa o̩gbó̩ yo̩ ní inú àwo̩n ohun tí àwo̩n ènìyàn ń so̩, pè̩lú sáyé̩ǹsì tó dà bí pé ó ń yípadà. Ìjókòó kan ní GIJC21 fi ara àwo̩n oníròyìn mo̩lé nípa àrùn COVID-19, tí wo̩n sì ń so̩ nípa bí wo̩n s̩e lè s̩e àkásílè̩ ìgbájáde òògùn àti ìlànà ìgbàláàyè, láti s̩e àgbéyè̩wò àwo̩n è̩kó̩ sáyé̩ǹsì, sís̩e àwàrí àwo̩n ò̩rò̩ tó tako ara wo̩n, àti títú às̩írí jìbìtì àti ìwà búburú.

GIJC21

Síso̩ òku-ò̩nà di às̩eyo̩rí nípa lílo ìlànà ìs̩èwádìí aláfojúrí

Láti o̩wó̩ Rowan Philp | November 9, 2021

Ní inú ìgbìmò̩ akó̩s̩é̩mo̩s̩é̩ lórí ìwádìí ohun rírí ní #GIJC21, àwo̩n e̩ni mé̩ta láti e̩gbé̩ àwo̩n olùdásílè̩ New York Times fi hàn pé ó ti wá s̩eés̩e láti se ìròyì ta ló s̩e kín ni, nígbà wo, àti orís̩irís̩i ìs̩è̩lè̩. 

GIJC21

Ìs̩e méje tí ó dára jù fún ìkò̩ròyìn as̩èwádìí

Láti o̩wó̩ Arinze Chijioke | November 8, 2021

Ní inú ìpéjo̩pò̩ GIJC21 tí ó gbójú lé ìtàn káàkiri Asia/agbègbè pàsífíìkì, àwo̩n onís̩é̩-ìròyìn as̩èwádìí sò̩rò̩ nípa àwo̩n is̩e tí ó dára jù fún sís̩e ìròyìn àti bí síso̩ ìtàn oníwádìí tí ó dára púpò̩ s̩e nílò ìmò̩ àti ìpinnu láti wádìí òtító̩.

E̩ s̩e àwárí àwo̩n ìtàn mìíràn

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *