- Is̩é̩ Ìròyìn ò̩te̩lè̩múyè̩
- Is̩é̩-Ìròyìn Aláko̩sílè̩
- Ìkó̩ni àti Ìdánilé̩kò̩ó̩
- Àwo̩n Ató̩nà mìíràn tí wo̩n wúlò
- Èdè Sípéènì nìkan
Ǹjé̩ e̩ ń wà ète, ohun-èlò, àti ìdánilé̩kò̩ó̩? Ató̩nà ìsàlè̩ yìí dá lé is̩é̩-ìròyìn ò̩te̩lè̩múyé̩ tí ó sì s̩e àgbékalè̩ àwo̩n àpe̩e̩re̩ àti àfihàn káàkiri àgbáyé. Ò̩pò̩ wà ní ò̩fé̩, afi tí wo̩n bá so̩ òmìíràn.
E̩ tún lè rí ìtó̩nà wa sí àwo̩n ató̩nà ní Èdè China àti Èdè Sípéénì. Ǹjé̩ e̩ ní àfikún tí e̩ fé̩ s̩e? E̩ te̩ àtè̩jísé̩ ímeèlì kí e̩ jé̩ ká mò̩.
Ìs̩é̩ Ìròyìn Ò̩te̩lè̩múyé̩
Investigate – The Manual: Àko̩sílè̩ yìí fojú sun gbígbé àwo̩n kókó tí CiFAR ti s̩e àfàyo̩ pé wo̩n s̩e pàtàkì fún ìwádìí ìwà-ìbàjé̩ ńlá, ìbàjé̩ tí ó je̩ mó̩ ìsúná, àti gbígba ohun-ìní padà, àti agbo̩n is̩é̩-ìròyìn a̩sèwádìí tí ó wúlò fún: àlàkalè̩ is̩é̩ àko̩sílè̩ àti ìwádìí, àwo̩n ohun èlò ìs̩èwádìí fún is̩é̩ ìwádìí orí ayélujára tí ó jinnú, ibùdó àko̩sílè̩ àti ààyè sí àko̩sílè̩, àti pè̩lú ààbò orí-è̩ro̩. Àpe̩e̩re̩ as̩àtìlé̩yìn mé̩ta ti jé̩ fífikún-un gé̩gé̩ bí àfihàn ìlò àwo̩n ohun-èlò àti ìlànà wò̩nyìí, tí ó dá lórí ìtàn àtibi-dé-ibi tí ò̩kan lára àwo̩n o̩mo̩ è̩kó̩s̩é̩ wa s̩e àgbéjáde. Ó tún wà ní Èdè Faransé.
Modern Investigative Journalism: Láti o̩wó̩ Mark Lee Hunter àti Luuk Sengers, pè̩lú Marcus Lindemann. Wo̩n júwe rè̩ gé̩gé̩ bí àte̩ is̩é̩ tí “ó ti wá ko̩já ohun tí ó ye̩ ní kíkó̩: ó máa ń ran àwo̩n olùkó̩ ló̩wó̩ nídìí is̩é̩ láti s̩e àfihàn bí wo̩n s̩e ń kó̩ o̩ nípa sís̩e àpéjúwe àwo̩n irúfé̩ ìbéèrè tí àwo̩n aké̩kò̩ó̩ yóò bèèrè (pè̩lú ìdáhùn rè̩), pè̩lú àwo̩n is̩é̩ sís̩e àti is̩é̩ àmúrelé tí ó tó̩ni só̩nà látàrí ìtàkurò̩so̩”. Láti o̩wó̩ àwo̩n òǹkò̩wé Story-Based Inquiry (wo ìsàlè̩ yìí). Síwájú, wo àgbékalè̩ láti àgbéjáde GIJC19.
Investigative Journalism Manual: Ató̩nà tí ó wúlò yìí bè̩rè̩ gé̩gé̩ bí ìwé ìléwó̩ fún àwo̩n onís̩é̩-ìròyìn ilè̩ Áfíríkà, pè̩lú àpe̩e̩re̩ àti is̩é̩-sís̩e, tí àjo̩ kan láti ilè̩ German, Konrad Adenauer Stiftung s̩e àtè̩jáde rè̩. Àtúns̩e tí ó gbè̩yìn kárí ayé, tí ó sì jé̩ sís̩e fún àwo̩n oníròyìn tí wo̩n ń dojú ko̩ òfin tí ó ń te̩ ìròyìn mó̩lè̩, àìsòótó̩ àti ò̩wo̩n ohun èlò. Ó tún wà ní Bahasa àti Mongolian, gé̩gé̩ bí ìtàkùn ayélujára onísò̩rò̩-ǹ-gbèsì.
Digging Deeper: A Guide for Investigative Journalists in the Balkans: Àtó̩nà yìí tí ó jé̩ títè̩jáde láti o̩wó̩ BIRN tí ó sì wà fún rírà, the Balkan Investigative Reporting Network, fojú sí ara bí a s̩e ń wú àko̩sílè̩ jáde ní agbègbè náà. Òǹkò̩wé Sheila Coronel, Olùdarí Stabile Center for Investigative Journalism ti Columbia University, tún s̩e àgbékalè̩ àwo̩n ète lórí is̩é̩-ìròyìn ò̩te̩lè̩múyé̩. S̩e àgbakàlè̩ orí kìn-ín-ní ló̩fè̩é̩. Àwo̩n Èdè: Gè̩é̩sì, Macedonian.
Investigative Journalism Handbook (2020) láti o̩wó̩ Al Jazeera Media Institute.
Drehbuch der Recherche (Àko̩sílè̩ fún ìwádìí). Láti o̩wó̩ Mark Lee Hunter àti Luuk Sengers, tí ó jé̩ títè̩jáde ní Èdè German láti o̩wó̩ Netzwerk Recherche. Àwo̩n Èdè: German
Exposing the Truth: A Guide to Investigative Reporting in Albania: Àko̩sílè̩ olójú-ewé mé̩tàléláàdó̩rin yìí lo̩ àwo̩n àpe̩e̩re̩ àti ètè àti ìlànà tí ó ti jé̩ jíjé̩rìí. Tí ó jé̩ títè̩jáde láti o̩wó̩ OSCE àti Balkan Investigative Reporting Network. Àwo̩n Èdè: Albanian, Gè̩é̩sì.
The Hidden Scenario, Ìwé o̩dún 2019 láti o̩wó̩ Luuk Sengers àti Mark Lee Hunter, “fojú sun bí ìs̩è̩lè̩ s̩e lè ran ó̩ ló̩wó̩ láti s̩e ìwádìí”. Ó wà fún rírà ní Center for Investigative Journalism.
Follow the Money: A Digital Guide to Tracking Corruption: Ìwé ìléwó̩ ò̩fé̩ yìí jé̩ títè̩jáde láti ò̩dò̩ àwo̩n International Center for Journalists. Àwo̩n Èdè: Gè̩é̩sì, Russian, Georgian
Global Investigative Journalism Casebook: Ìwé-àpe̩e̩re̩ yìí wà pè̩lú Story-Based Inquiry (Wo ìsàlè̩ yìí). Àwo̩n àròko̩ ò̩te̩lè̩múyé̩ pè̩lú orísun lórí bí àwo̩n onís̩é̩-ìròyìn s̩e s̩e ìwádìí tí wo̩n sì ko̩ ìtàn náà. Àwo̩n Èdè: Gè̩é̩sì
Global Investigative Journalism: Strategies for Support: Àgbéyè̩wò àti ìfò̩rò̩jè̩wò̩ lórí ìtànkáyé is̩é̩-ìròyìn láti o̩wó̩ David E. Kaplan ti GIJN, pè̩lú ìtanilólobó lórí ètò àwo̩n orísun oníwádìí àti wíwá owó, pè̩lú ató̩nà lórí àwo̩n e̩gbé̩ lágbàáyé. Tí ó jé̩ títe̩jáde láti o̩wó̩ Center for International Media Assistance. Àwo̩n Èdè: Gè̩é̩sì
Citizen Investigation Guide Ató̩nà o̩dún 2019 láti GIJN jé̩ gbígbéjáde láti ran àwo̩n ará-ìlú ló̩wó̩ láti s̩e ìròyìn ò̩te̩lè̩múyé̩.
Guide to Investigative Journalism: Àtè̩lé o̩dún 2007 yìí láti o̩wó̩ Public Broadcasting Service ní U.S. mú onís̩é̩-ìròyìn mo̩ bí a s̩e lè rí ìtàn, s̩e ìfò̩rò̩wánilé̩nuwò ò̩te̩lè̩múyé̩, rí kí wo̩n sì gba ìwé àko̩sílè̩, s̩e àgbékalè̩ ìtàn re̩ kí o sì gbé e jáde fún àwo̩n aráyé. Àwo̩n Èdè: Gè̩é̩sì
Hidden Scenario, látí o̩wó̩ Luuk Sengers àti Mark Lee Hunter [Ó wà fún rírà ní Centre for Investigative Journalism]. So̩ bí àwo̩n ò̩nà ìsò̩tàn s̩e lè fún is̩é̩-ìròyìn ò̩te̩lè̩múye̩ ní ètò àti àfojúsùn. Àwo̩n Èdè: Gè̩é̩sì.
Introduction to Investigative Reporting, Láti o̩wó̩ Brant Houston (Poynter News University). Ìdánilé̩kò̩ó̩ orí ayélujára yìí jé̩ US$29.95.
Investigating Religion: An Investigative Reporter’s Guide, láti o̩wó̩ Debra L. Mason àti Amy B. White [Ó wà nílè̩ fún rírà ní IRE]. Àwo̩n Èdè: English
Investigative Journalism Manual: Tí ó jé̩ títè̩jáde láti o̩wó̩ Forum for African Investigative Reporters (FAIR), ató̩nà kíkún yìí s̩e àgbékalè̩ ò̩pò̩ ète, pè̩lú àwo̩n abala pàtàkì lórí ìlera àti ìhùwàsí, pè̩lú àpe̩ere̩ láti gbogbo Áfíríkà. Àwo̩n Èdè: English, Bahasa, Español, Vietnamese, Korean, Mandarin, Japanese, Burmese, Sinhalese, Tamil, Mongolian, Nepal, Dzongkha, Bengali.
Investigative Journalist’s Guide to Company Accounts láti o̩wó̩ Raj Bairoliya. Tí ó jé̩ títè̩jáde láti o̩wó̩ Centre for Investigative Journalism tí ó sì wà nilè̩ fún rírà, ató̩nà yìí wà fún àwo̩n onís̩é̩-ìròyìn ò̩te̩lè̩múyé̩ tí wo̩n ní láti ní àgbó̩yé nípa ètò-ìsúná ilé-is̩é̩ kan (pàápàá ilé-isé̩ olókoòwò) tàbí láti rí òye okoòwò lan láti lè bèèrè ìbéèrè ‘nípa owó’.
Investigative Online Search: Ató̩nà yìí tí ó jé̩ títè̩jáde láti o̩wó̩ Centre for Investigative Journalism ní UK ní o̩dún 2011, sò̩ nipa bí a s̩e lè rí nǹkan ní orí ayélujára kí á sì wádìí òkodoro rè̩. Àwo̩n Èdè: Gè̩é̩sì
Investigative Photography: Supporting a Story with Pictures, látio̩wó̩ CJ Clarke, Damien Spleeters, àti Juliet Ferguson [Ó wà nílè̩ fún rírà ní Centre for Investigative Journalism]. Àwo̩n Èdè: Gè̩é̩sì
Investigative Reporter’s Handbook, Àtúns̩e Karùn-ún, Láti o̩wó̩ Brant Houston àti àwo̩n oníròyìn ò̩te̩lè̩múyé̩ àti àwo̩n as̩àtúns̩e. Ató̩nà yìí wà nílè̩ fún rírà ní IRE. Àwo̩n Èdè: Gè̩é̩sì
Investigative Reporting: A Toolkit for Reporters: Ató̩nà olójú-ewé o̩gó̩rùn-ún lé méje yìí jé̩ títè̩jáde ní o̩dún 2009 láti o̩wó̩ US Center for International Private Enterprise tí USAID pè̩lú Al-Masry Al-Youm for Journalism and Publication sì s̩e onígbò̩wó̩ rè̩. Àwo̩n Èdè: Gè̩é̩sì
Investigative Reporting in Emerging Democracies: Models, Challenges, and Lessons Learned: Ìròyìn láti o̩wó̩ Drew Sullivan ti Organized Crime and Corruption Reporting Project, pè̩lú ète lórí bí a s̩e ń s̩e àgbékalè̩ àwo̩n ètò, mímú ohun ró, ìlò fú àwo̩n as̩àtúnko̩, ààbò àti bé̩è̩ bé̩è̩ lo̩. Ó jé̩ títè̩jáde láti o̩wó̩ Center for International Media Assistance. Àwo̩n Èdè: Gè̩é̩sì
Manual for Arab Journalists on Freedom of Information and Investigative Reporting: Ìwé ìléwó̩ olójú ewé mó̩kànlélógún tí ó wà ní ò̩fé̩, tí ó sì s̩e é s̩e àgbàkalè̩ láti o̩wó̩ Article 19, tí the United Nations Development Programme s̩e onígbò̩wó̩ rè̩. Àwo̩n Èdè: Gè̩é̩sì, Lárábúwá
The News Initiative láti Google pèsè ìdánilé̩kò̩ó̩ alábala mé̩sàn-án lórií is̩é̩-ìròyìn aje̩mó̩wádìí, tí wo̩n fi sun ìlò àwo̩n ohun èlò Google.
The Science Writers’ Investigative Reporting Handbook Ìwé o̩dún 2018 láti o̩wó̩ Liz Gross lórí bí a s̩è lè s̩e ìwádìí ìtàn nínú ìtàn, s̩àwárí ojúsáju kí á sì rí ohun tí ó pamó̩.
Raising Hell: A Citizen’s Guide to the Fine Art of Investigation (PDF): Center for Investigative Reporting, ibùdó aláìgbójúlérè àkó̩kó̩ lágbàáyé fún ìròyìn ò̩te̩lè̩múyé̩, s̩e ìfilò̩ atónà yìí láti kó̩ gbogbo ìlú láti “s̩e iwádìí, wú ìwà ìbàjé̩ síta, kí wo̩n sì rí ibi tí agbára ti fúyé̩”. Àwo̩n Èdè: Gè̩é̩sì
Recherche in der Praxis: Informanten zum Reden bringen, Fakten hart machen, Missstände aufdecken (Research in Practice: Get Informants to Talk, Get Hard Facts, and Uncover Abuses láti o̩wó̩ Catherine Boss àti Dominique Strebel [Ó wà fún rírà]. Àwo̩n Èdè: German
Reporting in Indigenous Communities jé̩ kíko̩ láti o̩wó̩ oníròyì Canadian Broadcasting Corporation, Duncan McCue ní 2011. Ó ní ohun èlò fún kíká àwo̩n ènìyàn ìbílè̩ nílùú òkèèrè. E̩ wo, àkójo̩ àyè̩wò oníròyìn náà, ìtàkùn ayélujára rè̩ àti ìfò̩rò̩wánilé̩nuwò o̩dún 2018 pè̩lú McCue.
Story-Based Inquiry: Ató̩nà tí ó kún dénú lórí ìwádìí ò̩te̩lè̩múyé̩ tí Mark Hunter, Drew Sullivan, Pia Thosden, Rana Sabbagh àti Luuk Sengers jo̩ ko̩. Àko̩sílè̩ tí UNESCO s̩e onígbò̩wó̩ rè̩ yìí lo àwo̩n àpe̩e̩re̩ láti s̩e àfihàn ìlànà àti ìmo̩s̩é̩, léyìí tí ó pè̩lú ìwádìí, àko̩sílè̩, àyè̩wò dídára àti ìpínkárí. Àwo̩n Èdè: Gè̩é̩sì (PDF); Lárúbáwá | العربية (PDF); Chinese | 中文 (PDF); Faranse | Français (PDF); Russian | русский (PDF); Po̩tugí | Português (PDF); Spanish | Español (PDF).
The Story Tells the Facts, láti o̩wó̩ Mark Lee Hunter àti Luuk Sengers, [wà fú rírà ní Centre for Investigative Journalism]. S̩e àfihàn ò̩nà ìsò̩tàn, lára èyí tí a ti rí bí a s̩e lè hun ìtàn tí yóò tètè gbalè̩, àti láti ko̩ ìparí tí ó ní agbára. Àwo̩n Èdè: Gè̩é̩sì.
Undercover Reporting kìí se ìwé àko̩sílè̩ s̩ùgbó̩n àko̩sílè̩ àti ibùdó ohun-èlò ní orí ayélujára tí ó jáde láti ara ìwádìí fún ìwé Undercover Reporting: The Truth About Deception. Ìtàkùn náà ní ò̩pò̩ àpe̩e̩re̩ tí ó tí to o̩gó̩rùn-ún o̩dún.
The Verification Guide for Investigative Journalists ní orí mé̩wàá àti àfiwé mé̩ta. Àwo̩n àkórí jé̩ nípa àwo̩n ohun èlò ìwádìí ní orí ayélujára, dátà, àwo̩n àkóónú e̩ni tí ó ń lò, àti ìhùwàsí. Ó jé̩ alábàárì sí The Verification Handbook àti Verification Handbook: Additional Materials. Láti s̩e àgbàsílè̩ tàbí rà wo̩n, kí e̩ sì rí àwo̩n tí wo̩n ti túmò̩, te̩ ibí.
A Watchdog’s Guide to Investigative Reporting: Te̩numó̩ ìròyìn sís̩e ní Áfíríkà. Ató̩nà Èdè Gè̩é̩sì o̩dún 2005 yìí “pèsè àwo̩n àpe̩e̩re̩ ìs̩e dáradára tí ó ò wo àwo̩n àdojúko̩ ìlànà yìí fún àwo̩n tí wo̩n ń gbè̩ǹgbe̩ láti s̩e is̩é̩ ò̩te̩lè̩múyé̩”.
Is̩é̩-Ìròyìn Aláko̩sílè̩
Lessons from 30 Years Of Teaching Journalists Data Journalism, àko̩sílè̩ atanilólobo ti GIJC19 láti ówó̩ Brant Houston, e̩ni tí ó jé̩ olóyè alága nínú ìròyìn Ò̩te̩lè̩múyé̩ ní University of Illinois. Fún ìgbà tí ó lé ní o̩dún mé̩wàá, òun ni olùdarí àgbà fún Investigative Reporters and Editors.
Teach Computational Thinking, Not Just Spreadsheets or Coding, àko̩sílè̩ atanilólobó láti o̩wó̩ Paul Bradshaw, Birmingham City University/BBC Data Unit
7 countries, 9 teachers: a dossier of data journalism teaching strategies Àwo̩n ò̩nà wo ni ó wúlò jù láti fi ojú aké̩kò̩ó̩ mò̩ nípa àkójo̩pò̩ àko̩sílè̩, dátà? Láti o̩wó̩ Nouha Belaid, Anastasia Valeeva, Bahareh Heravi, Roselyn Du, Kayt Davies, Adrian Pino, Eduard Martín Borregon, Soledad Arreguez, àti Jeff Kelly Lowenstein.
Data and Computational Journalism, àròko̩ o̩dún 2020 yìí “s̩e ìfilò̩ ohun mé̩rin tí ó lè ran àwo̩n alákadá ló̩wó̩ láti tètè gba bí wo̩n s̩e ń fi àko̩sílè̩ bo̩ inú is̩é̩-ìròyìn”. Àwo̩n òǹkò̩wé rè̩ ni Norman P. Lewis, Mindy McAdams, àti Florian Stalph. Ìtó̩ka mé̩rin wo̩n:
Lákò̩ó̩kó̩, è̩kó̩ nínú òǹkà àti ìs̩irò as̩àfihàn gbo̩dò̩ jé̩ dandan, gé̩gé̩ bí ara is̩é̩ nínú è̩kó̩ tí ó ti wà té̩lè̩ tàbí àdákó̩. Lé̩è̩kejì, àwo̩n aké̩kò̩ó̩ nílò ìdánilé̩kò̩ó̩ láti sá fún àsìs̩e nínú títúmò̩ àti kíjo̩ nípa dátà nínú kíláàsì ìròyìn tàbí àkásílè̩. E̩lé̩è̩ke̩ta, ìdánilé̩kò̩ó̩ lórí ìhùwàsí gbo̩dò̩ sò̩rò̩ dátà gé̩gé̩ bí ohun èlò ìfòdodohàn tí ó ní ojú púpò̩. E̩lé̩è̩ke̩rin, ìrònú aje̩mó̩-è̩ro̩, tàbí bí wo̩n s̩e lè yànnàná tàbí wá ojúùtú sí ìs̩òro bí è̩ro̩ ayára-bí-às̩á s̩e máa ń s̩e,lè jé̩ dídàpò̩ mó̩ ìdánilé̩kò̩ó̩ tí ó ti wà té̩lè̩ láti kó̩ èrò.
More Effective Teaching of Data Journalism to Working Journalists, láti o̩wó̩ Kuang Keng Kuek Ser ti Data-N, tí wo̩n s̩e àgbékalè̩ GIJC19. Àwo̩n ète yìí wà fún àwo̩n olùkó̩ni tí wo̩ ń kó̩ is̩é̩-ìròyìn aje̩mó̩dátà sí àwo̩n onís̩é̩-ìròyìn tuntun lójú o̩pó̩n.
Hacking the curriculum: How to teach data reporting in journalism schools Ìròyìn láti American Press Institute Report láti 2018. “Àbá wa gbòógì ni fún àwo̩n ilé-è̩kó̩ is̩é̩-ìròyìn láti rí dátà àti àko̩sílè̩ gé̩gé̩ bí è̩kó̩ tí ó po̩n dandan fún gbogbo aké̩kò̩ó̩”.
Where in the world can I study data journalism? Àròko̩ o̩dún 2019 láti o̩wó̩ Bahareh Heravi s̩e ìso̩nísókí àròko̩ akadá rè̩ lórí àkòrí yìí, tí ó ní àko̩lé 3Ws of Data Journalism Education,tí ó jé̩ títè̩jáde láti o̩wó̩ Data Journalism Practice. Àko̩sílè̩ náà s̩e é rí láti UCD academic repository. Ó ní máàpù nínú.
International Journalism Education Consortium: Ìtò̩nà àti Ìjúwe sí àte̩-è̩kó̩ láti agbàrànwó̩-kò̩m̀pútà àti is̩é̩-ìròyìn aje̩mó̩-dátà (Ní títò álífábé̩è̩tì pè̩lú orúko̩ ilé-è̩kó̩ giga, àti ò̩jò̩gbò̩n)
Computer-Assisted Reporting: A Comprehensive Primer: Láti o̩wó̩ Fred Vallance-Jones and David McKie [Ó wà fún rírà]. Àwo̩n Èdè: Gè̩é̩sì
Computer-Assisted Reporting: A Practical Guide: Àtè̩jáde ke̩rin láti o̩wó̩ Brant Houston [Wà fún rìrà]. Àwo̩n Èdè: Gè̩é̩sì
Computer-Assisted Research: Information Strategies and Tools for Journalists: Láti o̩wó̩ Nora Paul àti Kathleen A. Hansen [wà fún títà láti IRE]. Àwo̩n Èdè: English
Data Journalism Handbook jé̩ akitiyan àpapà̩ àti ti ilè̩ òkèèrè tí ó je̩ mó̩ àìmò̩ye onís̩é̩-ìròyìn. Ó kún fún ìtumò̩, àpe̩e̩re̩ àti ètè láti rí, lò tàbí s̩e àgbéyè̩wò dátà. Èrò European Journalism Centre àti Open Knowledge Foundation. Àwo̩n Èdè: Ó wà ní gbígbàsílè̩ ní Lárúbáwá, Èdè Gè̩é̩sì, Faransé, Russian, àti Spanish. Ìwé iléwó̩ yìí ń jé̩ yíyípadà sí ò̩pò̩ èdè, tí ó fi mó̩ Èdè Georgia. Àtúns̩e o̩dún 2012 jé̩ títúmò̩ sí èdè tí ó lé ní méjìlá – lára èyí tí a ti tí Lárúbáwá, Èdè China, Czech, Faransé, Èdè Georgia, Greek, Èdè Ìtálì, Èdè Macedonia, Èdè Po̩tugí, Èdè Russia, Èdè Spain àti Èdè Ukraine.
Flowing Data ní onís̩irò Nathan Yau gé̩gé̩ bí olùdarí, e̩ni tí ó ko̩ Data Points: Visualization that Means Something àti Visualize This: The FlowingData Guide to Design, Visualization, and Statistics. Abala Learning to Data ní àwo̩n ìtò̩ns̀ sí ìdánilé̩kò̩ó̩, ìwé àti ató̩nà tí ó je̩ mó̩ sís̩e is̩é̩ pè̩lú dátà.
Mapping for Stories: A Computer-Assisted Reporting Guide, Láti O̩wó̩ Jennifer LaFleur àti Andy Lehren [Ó wà fún rírà láti IRE]. Àwo̩n Èdè: Gè̩é̩sì
Precision Journalism: a Reporter’s Introduction to Social Science Methods, láti o̩wó̩ Philip Meyer [Ó wà fún rírà]. Àwo̩n Èdè: Gè̩é̩sì
Datawrapper àwo̩n ohun-èlò fún ìkó̩ni
Ìkó̩ni àti Ìdánilé̩kò̩ó̩
Model Curricula for Journalism Education: Ató̩nà tí ó fojú sun agbo-ìmò̩ is̩é̩-ìròyìn ní àwo̩n ìlú tí ó s̩è̩s̩è̩ ń dìde àti àwo̩n òmìnira tí ó s̩è̩s̩è̩ ń gbérí. Tí ó jé̩ sís̩ètò láti ò̩dò̩ àjo̩UNESCO, àko̩sílè̩ yìí ̀náà pèsè àte̩ is̩é̩ fún è̩kó̩ mé̩tàdínlógún – tí ó fi mó̩ ìròyìn ò̩te̩lè̩múyé̩ – tí ó lè jé̩ títò láti bá ìwúlò orílè̩-èdè kò̩ò̩kan mu. Àwo̩n Èdè: Gè̩é̩sì (PDF); Faransé | Français (PDF); Spanish | Español (PDF); Russian | Pусский (PDF); Lárúbáwá | العربية (PDF); Chinese | 中文 (PDF); Nepali (PDF); Po̩tugí | Português (PDF); Farsi | فارسی (PDF).
International Journalism Education Consortium: Àpéjúwé è̩kó̩ is̩é̩-ìròyìn ò̩te̩lè̩múyé̩ àti àwo̩n àte̩ is̩é̩ láti ara àwo̩n è̩kó̩ is̩é̩-ìròyìn ò̩te̩lè̩múyé̩. (Ní títò orúko̩ ilé-è̩kó̩ gíga pè̩lú álífábé̩è̩tì, kí ó tó kan orúko̩ àwo̩n ò̩jò̩gbó̩n).
Algorithms for Journalists: Àte̩-is̩é̩ è̩kó̩ ti ìdánilé̩kò̩ó̩ algorithms tí onímò̩ is̩é̩-ìròyìn aje̩mó̩-àko̩sílè̩ Jonathan Stray ní The Lede Program ti Columbia Journalism School. Ó wà ní GitHub, pè̩lú ìtò̩nà sí àwo̩n àgbékalè̩, ohun kíkà àti is̩é̩-sís̩e. Mò̩ pé ìdánilé̩kò̩ó̩ náà wà fún aké̩kò̩ó̩ tí ó s̩è̩s̩è̩ bè̩rè̩ Python programming ni.
Better News Ìtàkùn ayélujára pè̩lú ò̩pò̩ ohun èlò tí American Press Institute ń s̩e àkóso rè̩.
AEJMC Task Force for Bridges to the Professions 2017 Report Ìròyìn o̩dún 2017 lórí ìfo̩wó̩sowó̩pò̩ àwo̩n akadá àti àwo̩n onís̩é̩-ìròyìn láti Association for Education in Journalism and Mass Communication (AEJMC).
Observations on how we teach drone journalism, láti o̩wó̩ Judd Slivka, olùdárí àkó̩kó̩ ní è̩ka Aerial Journalism fún Missouri School of Journalism.
Algorithms course materials at Columbia Journalism School Àte̩ is̩é̩ teaching algorithms láti o̩wó̩ Ò̩jò̩gbo̩n ilè̩ Columbia, Jonathan Stray.
The Field Guide to Security Training jé̩ àte̩-is̩é̩ tí agbáte̩rù rè̩ jé̩ OpenNews, àjo̩ tí ó ń s̩e ìrànwó̩ fún àwo̩n dìfé̩ló̩pà, àwo̩n dìsáínà, àti àwo̩n as̩àyè̩wò dátà pè to̩ tí wo̩n sì fo̩wó̩sowo̩pò̩ lórí àwo̩n àkàns̩e is̩é̩-ìròyìn gbangba, pè̩lú BuzzFeed Open Lab, ètò if̀owó̩sowó̩pò̩ lórí áàtì àti ìmò̩-è̩ro̩ ní BuzzFeed News.
Àwo̩n Ató̩nà mìíràn tí wo̩n wúlò
“The Mojo Handbook: Theory to Praxis,” láti o̩wó̩ Ivo Burum. Ató̩nà olójú-ewé ò̩ó̩dúnrún-lé-ní-àádó̩ta tí ó jé̩ kiíko̩ sílè̩ láti o̩wó̩ Ivo Burum, As̩àko̩sílè̩-abala Mojo Workin ní GIJN, tí ó sì pèsè è̩kó̩ ráńpé̩ lórí ìlò àwo̩n ohun-èlò alágbèéká láti so̩ ìtàn alábala púpò̩. Pè̩lú àfikún lórí yíya fídíò aláko̩sílè̩ àti ohun tí ó já geere, sís̩e àtúns̩e lórí è̩ro̩ ìbánisò̩rò̩ rè̩ àti ìtàn síso̩ pè̩lú è̩ro̩ ìbánisò̩rò̩ fún sís̩è̩dá àwo̩n àkóónú tí ó ń múnilára, tí ó sì ń je̩ni lógún, ó kárí gbogbo igun.
The James W. Foley Journalism Safety Modules jé̩ gbígbéjáde láti s̩àfihàn àwo̩n aké̩kò̩ó̩ is̩é̩-ìròyìn àti ìbánisò̩rò̩ sí ààbò gé̩gé̩ bí ohun pàtàkì sí is̩é̩-ìròyìn. Àwo̩n è̩kó̩ náà jé̩ gbígbékalè̩ láti o̩wó̩ James W. Foley Legacy Foundation pè̩lú àjo̩s̩epò̩ Marquette University Diederich College of Communication. Àte̩-è̩kó̩ mé̩rìndínlógún náà dá lórí ò̩pò̩ àkòrí, lára èyí tí a ti rí, s̩ùgbó̩ tí kò mo̩ ní, píparí àyè̩wò fún ewu, ojús̩e àwo̩n adarí yàrá-ìròyìn, ààbò àwo̩n onís̩é̩-ìròyì kékeré àti obìnrin, sís̩e àkásílè̩ rúkèrúdò (lára èyí tí a ti rí ìfè̩hónúhàn), ríròyìn lásìkò àjàkálè̩-àrùn yìí, ìtó̩jú ara e̩ni nínú è̩mí, ìtó̩jú orísun, sís̩e ìfò̩rò̩wánilé̩nuwò fún àwo̩n orísun oníjàgídíjàgan, ríròyìn rúkèrúdò ilè̩ òkèèrè, dídáàbò bo dátà, àti sís̩e àkásílè̩ àwo̩n ìtàn tó je̩ mó̩ ojú-o̩jó̩. Ní ò̩nà, àwo̩n aké̩kò̩ó̩ yóò ko̩ láti rí ààbò gé̩gé̩ bí ohun tí ó po̩n dandan nínú is̩é̩-ìròyìn tí ó ní agbára, àlàáfíà àti ìwà-pípé. James W. Foley Foundation pèsè àwo̩n àte̩ ajé̩mó̩-ààbò kan.
“A Taste for Trouble,” Láti O̩wó̩ Aniruddha Bahal. Ní ogún o̩dún sé̩yìn, Bahal s̩e è̩dá wàhálà tí ó mi gbogbo àgbáyé nípa sís̩e ìwádìí màgòmágó nínú eré-ìdárayá látii o̩wó̩ àwo̩n àgbà nínú eré-ìdárayá náà. E̩ ò lè mú àjo̩ tí ó ń darí ere-ìdárayá tí ó tóbi jù ní India té̩ḿbé̩lú, Bahal sì wa orúko̩ fún ara rè̩ gé̩gé̩ bí “the father of sting journalism in India”. Ìwé rè̩ tí ó tuntun jù, “A Taste for Trouble,” jé̩ kíko̩sílè̩ lásìkò̩ ìs̩émó̩lé, tí ó sì s̩e àyè̩wò gbogbo nǹkan láti kékeré rè̩ dé bí ó s̩e dá ibùdó is̩é̩-ìwádìí tiè̩ (o̩mo̩-e̩gbé̩ GIJN Cobrapost) ní ìgbà tí — gé̩gé̩ bí èrò Hindustan Times — “síso̩ òdodo sí agbára kò sí lára àlàkalè̩ àwo̩n ilé-is̩é̩ ìròyìn”.
Empowering Independent Media: U.S. Efforts to Foster a Free Press and an Open Internet Around the World: Àwòtó̩ fún ìdàgbàsókè is̩é̩-ìròyìn, tí ó wúlò lé è̩ka is̩é̩ ìròyìn, àwo̩n àjo̩ aláìgbójú-lé-èrè àti aláìgbára-lé-ìjo̩ba ni àwo̩n oriílè̩-èdè tí ó s̩è̩s̩è̩ ń dàgbà tàbí tí ó ń yí ipò padà. Ó dá lé agbo̩n méje pàtàkì lórí ìdàgbàsókè ìròyìn: ètò owó, ìròyìn ayélujára, ìgbédúró, òfin ìròyìn, ààbò, è̩kó̩, àti sís̩o̩ pè̩lú àgbéyè̩wò. Àwo̩n Èdè: Gè̩é̩sì, Èdè Sípéènì, Faransé.
Google Search Tips for Journalists: Ató̩nà kúkúrú tí ó s̩e é mú léwó̩ yìí pèsè àwo̩n ìtanilólobó tí wúlò púpò̩ fún sís̩e ìwádìí tí ó ní ìtumò̩ pè̩lú ìlò è̩ro ìwá-nǹkan Google. Tí expertisefinder.com s̩e àkójo̩pò̩ rè̩.
Journalist Survival Guide: Tí ó jé̩ gbígbé jáde láti o̩wó̩ Samir Kassir Foundation ní ilè̩ Beirut, ató̩nà aláwòrán yìí jé̩ gbígbékalè̩ láti lè ran àwo̩n onís̩é̩-ìròyìn àti àwo̩n ajìjàgbara tí wo̩n ń sis̩é̩ ní àwo̩n agbègbè ogun àti agbègbè tí ó ní rúkèrúsò, s̩ùgbó̩n ó tún ní ìtanilólobó lórí ààbò ìtàkù ayé́lujára àti bí o s̩e lè dáàbò bo ìtò̩nà re̩. Àwo̩n Èdè: Gè̩é̩sì, Larúbawá
Legal Leaks Toolkit: A Guide for Journalists on How To Access Government Information: Ìwé pélébé olójú-ewé márùndínló̩gó̩rin tí ó s̩e àko̩sílè̩ àwo̩n ohun ìbè̩rè̩ fún àwo̩n onís̩é̩-ìròyìn tí wo̩n ń gba ò̩nà tí ó tò̩ láti ní ìwé àko̩sílè̩. Tí ó jé pípèsè láti o̩wó̩ Access Info Europe àti Network for Reporting on Eastern Europe. Ó wà ní English, Italian, Russian, Italian, Macedonian, Bosnian, Croatian, Hungarian, àti Serbian.
Reporting Atrocities: A Toolbox for Journalists Covering Violent Conflict and Atrocities: Ató̩nà olójú ewé mó̩kànléló̩gó̩ta tí ó kún dénú yìí wo àbùdá rúkèrúdò, bí a s̩e lè ká a sílè̩, àti is̩é̩ àwo̩n onís̩é̩-ìròyìn ní irú àkókò bé̩è̩. Tí ó jé̩ kíko̩ láti o̩wó̩ onís̩é̩-ìròyìn láti South Africa, Peter du Toit tí ó sì jé̩ títè̩jáde láti o̩wó̩ Internews. Àwo̩n Èdè: Èdè Gè̩é̩sì
Reporting on Corruption: A Resource Tool for Governments and Journalists: Ìwé ató̩nà olójú-ewé mé̩tàdínló̩gó̩fà láti o̩wó̩ UN Office on Drugs and Crime máa ń jé̩ fífipamó̩ nínú àwo̩n ò̩rò̩ ìs̩èlú àti UN-speak, s̩ùgbó̩n àwo̩n àpe̩e̩re̩ àti ohun èlò tí ó wúlò wà. Ara àkóónú rè̩ ni dídáàbò bo orísun, è̩tó̩ sí àko̩sílè̩, àti ò̩nà ìmúra-e̩ni-dúró.
SEEMO Safety Net Manual: Guidelines for Journalists in Extraordinary or Emergency Situations: Àko̩sí́lè̩ aje̩mó̩-ààbò tí ó jé̩ gbígbéjáde láti o̩wó̩ South East Europe Media Organization– jé̩ ara àgbékalè̩ tí ó tóbi láti dáàbò bo àwo̩n onís̩é̩-ìròyìn ní agbègbè náà. Àwo̩n Èdè: English àti, Serbian, Italian, Romanian, Greek, Turkish, Bulgarian, Croatian, and Slovenian.
Tragedies & Journalists: Ató̩nà ológójì ojú-ewé pè̩lú àwo̩n ètè tí ó dájú láti s̩e ìrànwò̩ fún àwo̩n onís̩é-ìròyì, afi-àwòrán-ròyìn, àti àwo̩n as̩àtúns̩e láti ròyoìn lórí rúkèrúdò nígbà tí wo̩n ń dààbò bo e̩ni tí ìs̩è̩lè̩ s̩è̩ sí àti ara won. Tí ó jé̩ títè̩jáde láti Dart Center for Journalism & Trauma, tí ó sì jé̩ kíko̩ láti o̩wó̩ Joe Hight àti Frank Smyth. Àwo̩n Èdè: English, Spanish, 中文 (Chinese).
Verification Handbook jé̩ ohun èlò fún àwo̩n onís̩e̩ ìròyìn àti àwo̩n aranniló̩wó̩ láti European Journalism Centre. Ó pèdè àwo̩n ohun-èlò, ìlànà àti ìdári sísè̩-n-tè̩lé fún bí e̩ s̩e lè s̩e user-generated content (UGC) ní àsìkò Pàjáwìrì. Àwo̩n Èdè: English, Português, العربية , Español.
Who’s Running the Company: A Guide to Reporting on Corporate Governance: As̩àfihàn sí ìròyìn lórín ìs̩èjo̩ba olókoòwò, pè̩lú àwo̩n abala lórí àwo̩n olùdárí, ìròyìn ìsúná, àti títo̩pa ìs̩e ilé-is̩é̩. Tí ó jé̩ gbígbéjáde láti o̩wó̩ World Bank’s International Finance Corporation pè̩lú the International Center for Journalists.
Àwo̩n Èdè: Gè̩é̩sì (PDF); Faransé (PDF); Èdè Sípéènì(PDF); Bahasa Indonesia (PDF); Mongolian | МОНГОЛ ХЭЛ (PDF); Lárúbáwá | العربية (PDF); Russian | Pусский (PDF); and Portuguese | Português (PDF) .
Security and Covering Conflict: IJNet ti s̩e àkójo̩ àwo̩n àko̩sílè̩ àwo̩n ató̩nà sí ààbò àwo̩n onís̩é̩-ìròyìn àtii sís̩e àkásílè̩ àwo̩n aáwò̩ láti ilé-is̩é̩ orís̩irís̩i. Ò̩pò̩ nínú wo̩n wà ní ò̩pò̩ èdè bí Èdè Lárúbáwá, Èdè China, Èdè Russia àti Èdè sípéènì.
Èdè Sípéènì lásán
Àwo̩n ató̩nà yìí wà nílè̩ ní Èdè Sípéènì nìkan. E̩ tún s̩e àyè̩wò àwo̩n ìròyìn tí a ko̩ sí òkè yìí – ò̩pò̩ jé̩ títè̩jáde ní Èdè Sípéènì — pè̩lú ojú ewé ohun èlò rè̩ ní Èdè Sípéènì.
Cómo Investigar Temas Ambientales (Investigating Environmental Issues): Ató̩nà fún sís̩e ìwádìí àwo̩n ohun tí ó je̩ mó̩ àyíká ní apá Gúúsù ilè̩ Amé̩ríkà.
Guía Práctica sobre Periodismo de Datos (Practical Guide to Data Journalism) láti o̩wó̩ Sandra Crucianelli, tí ó jé̩ Knight International Journalism Fellow. Ató̩nà yìí so̩ àwo̩n ète fún rírí àko̩sílè̩, tí ó sì s̩e àgbéyè̩wò àwo̩n oníròyìn tó ń s̩e is̩é̩-ìròyìn alágbàsílè̩. Ó jé̩ títè̩jáde láti o̩wó̩ International Center for Journalists.
Manual de Periodismo de Datos Iberoamericano (Latin American Handbook of Data Journalism) Pèsè àwo̩n ìtanilólobó àti è̩kó̩ lórí rírí ìtalólobó, wíwá ìtàkù ayélujára dénú, àti bé̩è̩ bé̩è̩ lo̩. Ató̩nà fún àwo̩n oníròyìn tó ń so̩ Èdè Sípéènì yìí jé̩ títè̩jáde láti o̩wó̩ Poderomedia Foundation pè̩lú àjo̩s̩epò̩ School of Journalism ní University Alberto Hurtado.
Métodos de la Impertinencia (Methods of Impertinence): Press and Society Institute (IPYS) ti Venezuela s̩e àgbéjáde àkójo̩pò̩ àwo̩n ìs̩e àti è̩kó̩ tí ó dára jù fún is̩é̩-ìròyìn oníwádìí ní Latin America. Ìwé náà s̩e àkópò̩ ìjé̩rìí láti e̩nu onís̩é̩ ìròyìn ńlá mé̩wàá láti agbègbè náà.
Periodismo de Investigacion (Investigative Journalism) láti o̩wó̩ Gerardo Reyes. Ako̩kún àtó̩nà ìbè̩rè̩ sínú ìròyìn oníwádìí ní Láti America, tí ó sì ní abala lórí àwo̩n ìlànà.
Periodista de Investigacion Latinoamericano en la Era Digital (The Latin American Journalist: Research in the Digital Age) jé̩ gbígbéjáde látí o̩wó̩ Initiative for Journalism Research ní Ilè̩ Amé̩ríkà àti ICFJ pè̩lú àjo̩s̩epò̩ Connectas, tí àwo̩n alájjo̩ko̩ sì jé̩ Nathalia Salamanca, Jorge Luis Sierra, àti Carlos Eduardo Huertas.
Àwo̩n Àko̩sílè̩ Is̩é̩-Ìròyìn Ò̩te̩lè̩múyé̩